Ajíbọ́lá Bàṣírù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Surajudeen Ajíbọ́lá Bàṣírù (Ph.D) tí a bí ní ọjọ́ Kínní oṣù Keje, ọdún 1972 ( 1-07-1972) jẹ́ ọmọ ilé Aṣojú-ṣòfin Àgbà tí ó ń ṣojú fún [1] Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó tún fígbà kan tẹ́lẹ̀ jẹ́ Kọmíṣánà ní abẹ́ Ministry of Regional Integration & Special Duties ní oṣù Kẹjọ ọdún 2010 sí oṣù Kọkànlá ọdún 2014. [2] Ó ti fìgbà kan ṣiṣẹ́ Olùkọ́ ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní oṣù Kọkànlá, ọdún 2014 sí oṣù Kárùún 2017.

Inẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ajíbọ́lá Bàṣíru lè sile-ákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Salvation Army tí ó wà ní Oke-Fíà ìlú Òṣogbo, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun , ní ọdún 1983. Lẹ́yìn èyí ni ó lè sí ilé-ẹ̀kọ́ Girama Láro ní Òke-Fíà yí kan náà, níbi tí ó ti gba ìwé-ẹ̀rí WASC / GCE O'Level ní ọdún 1988.

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Amòfin[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ajíbọ́lá Bàṣírù wọlé sí Ilé- Ẹ̀kọ́ ti Ìlọrin láti ọ́ nípa èdè Lárúbáwá àti ìwádí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nínú ẹ̀sìn Islam, Ṣùgbọ́n ó kúnà ní ìpele ẹ̀kọ́ ọdún kẹta rẹ̀, Ó wọ ilé-ẹ̀kọ́ University of Lagos, ní Àkọkà, Yábàá, láti kẹ́kọ́ inọ̀ ofin tí ó sì gba oyè ìmọ̀-ẹ̀ ẹ̀kọ́ LLB (Hons) Bachelor of Law ní ọdún 1994-2000. [3]

Ó lè sí ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ofin ti ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó wà ní Bwari, Abuja, FCT. (2001-2002) tí ó sì gba ìwé ẹ̀rí Second Class, Upper Division láti ọdún 2005 sí 2006. Ó tún lè sí ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Ìlú Èkó láti gba LLM (Masters of Law) tí ó jẹ́ ẹ̀kọ́ nípa Secured Credit Transactions; Planning & Compulsory Acquistion ; Law of gbè Sea and Comparative Company Law. Ní ọdún 2016, Ó gba oye ìmọ̀ Ọ̀mọ̀wé (PHD) nínú ìmọ̀ Property Law, ní ẹ̀ka ikẹ́kọ̀ọ́ inọ̀ Òfin ní Fásitì Ìlú Èkó Awọn iṣowo Awọn Gbese Ipamọ; Gbigba A. [4]

Ṣíṣe òṣèlú rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Dokita Surajudeen Ajíbọ́lá Bàṣírù tí ń ṣojú fún ẹkùn Àárín gbùngbùn Ọ̀ṣun ni ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú [5] [6] All Progressives Congress (APC). Ó ti wà nínú ẹgbẹ́ yí lásìkò tí orúkọ ẹgbẹ́ náà wà ní Alliance for Democracy (AD), ṣáájú kí wọ́n tó ṣàyípadà orúkọ sí Action Congress of Nigeria (ACN) kí ó tó wá di All Progressive Congress (APC). Ó ti fìgbà kan jẹ́ Kọmíṣánà [1] lábẹ́ ìjọba Ọ̀gbẹ́ni Rauf Arẹ́gbẹ́ṣọlá .

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "The Cabinet - The Official Website Of The State Of Osun" (in en-US). The Official Website Of The State Of Osun. Archived from the original on 2018-11-28. https://web.archive.org/web/20181128151013/http://osun.gov.ng/governor/cabinet/. 
  2. "Ministry of Regional Integration and Special Duties - The Official Website Of The State Of Osun" (in en-US). The Official Website Of The State Of Osun. Archived from the original on 2018-09-08. https://web.archive.org/web/20180908184223/http://osun.gov.ng/government/executive/ministries/regional-integration-and-special-duties/. 
  3. "How my expulsion from UNILORIN changed my career -Osun Attorney-General Ajibola". http://thenationonlineng.net/how-my-expulsion-from-unilorin-changed-my-career-osun-attorney-general-ajibola/. 
  4. "Aregbesola, Prominent Nigerians to Honour Ajibola Basiru For His Doctorate Degree - CityMirrorNews". CityMirrorNews. 2016-04-14. http://citymirrornews.com/top-news/2016/14/aregbesola-prominent-nigerians-to-honour-ajibola-basiru-for-his-doctorate-degree/. 
  5. "He was declared winner of Osun Central Senatorial election by the Independent National Electoral Commission (INEC)". February 25, 2019. https://www.legit.ng/1224020-apcs-basiru-defeats-pdp-wins-osun-central-senatorial-seat.html. 
  6. "Exclusive List Of New Commissioners And Special Advisers Governor Aregbesola Sent To Osun State House Of Assembly | Sahara Reporters". 2017-04-16. http://saharareporters.com/2017/04/16/exclusive-list-new-commissioners-and-special-advisers-governor-aregbesola-sent-osun-state.