Edgar Adrian

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Edgar Adrian, 1st Baron Adrian
Ìbí Edgar Douglas Adrian
30 Oṣù Kọkànlá, 1889(1889-11-30)
Hampstead, London, England
Aláìsí 4 Oṣù Kẹjọ, 1977 (ọmọ ọdún 87)
Cambridge, Cambridgeshire
Ọmọ orílẹ̀-èdè United Kingdom
Pápá Electrophysiology
Ilé-ẹ̀kọ́ Cambridge University
Ibi ẹ̀kọ́ Cambridge University

Edgar Douglas Adrian niogbónjo osu kokànlá Odún 1889 (11-30-1889). A bi I ni ilú Hampstead, London, England. O kú ní ojó kerin osú kejo odún 1977 (ní ìgbà naa o jé omo dun méta-di-ni-aadorun-un).

O jé ará ìlu British tí o jé onímo ifero mo-ise-ohun-elémi ati ólùgbà ebùn íyibíye olólá ni odún 1932 fún ìmo ìse ohun elemi ti oun àti Sir Charles Sherrigbon jùmò jé fún ìmúlò oun kan nínú ara tí o má gbé ìròyin làtí ibi opolo de ibi-ti-o kú lárá.

Omo Alfred Douglas Adrian, onimoran ofin fún igbimo ijoba ibíle tí BriitisI (British) ni ojogbon Edgar je. Òjògbón Edger Adrian lo si ile-ìwe West Minister, o si ká sáyénsì adándá ni ilé-ìwé gíga ti Kémíbiriijì. O si wa ni ibè fún opolopo odun. O parí kí kó ìmò egbógi ni odun 1915. Isé aseparí fun eko won ti ile-wosan ni o se ni ile-Iwosan ti St. Bartholemew’s ni London nigba ogun agbaye kiini, O se ìtójú àwon ológun. Òjogbón Edger pada si Kémíbirììji ní odun 1919, ni igba ti o di odun 1925. Òjògbón Adrian Baron fé Arabirin HESTER AGNES PINSENT ni ojó kerin-la osu keta odun 1923 (14-6-1923). Won bi omo méta (omo obinrin kan àti awon Ibejí miiran). Òjògbón Adrian se awárì elétirìiki nínú èyá ara níbí isan.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]