Jump to content

Fountain University

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Fountain University, Osogbo
Fáìlì:Fuo-pt-list-of-courses.jpg
Senate Building, Fountain University, Osogbo
MottoKnowledge, Faith and Leadership
Established2007
TypePrivate
Religious affiliationNasrul-Lahi-L-Fatih Society (NASFAT)
ChancellorAlh. Umaru Mutallab CON
Vice-ChancellorProfessor Olayinka Ramota Karim
Academic staff178
Students2147
LocationOsogbo, Osun, Nigeria
ColoursGreen and Mint
         
WebsiteOfficial website

Fountain University (FUO) jẹ́ fásitì aládàání ní Osogbo, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣụn, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí á ṣe ìdásílè rẹ̀ láti pèsè ẹ̀kọ́ ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà ẹ̀sìn Islam.[1][2] Univesity of Nasrul-lahi-li Fatih ni orúkọ iléẹ̀kọ́ gíga yìí ń jẹ́ tẹ́lè, láti ọwọ́ ìjọ Nasrul-lahi-li Fatih (NASFAT) ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù Karùn-ún, ọdún 2007.[3] Ilé-èkọ́ gíga náà ní àwọn ẹ̀ká ẹ̀kọ́ márùn-ún sínú, tí ń ṣe: College of Basic Medical and Health Sciences, College of Natural and Applied Sciences, College of Management and Social Sciences, College of Law, àti College of Arts.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Fountain University". www.4icu.org. Retrieved 9 August 2015. 
  2. "Nigeria's 59 private universities …locations, Vice Chancellors names, websites, dates of establishment". Kukogho Iruesiri Samson. pulse.ng. 22 April 2015. Retrieved 10 August 2015. 
  3. Anaekwe, Ikechukwu (August 27, 2023). "Fountain University, Osogbo, Osun State". six33four. https://six33four.ng/blog/article/fountain-university-osogbo-osun-state. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]