Gabriel Okara

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gabriel Okara
Ọjọ́ìbíGabriel Imomotimi Gbaingbain Okara
24 Oṣù Kẹrin 1921 (1921-04-24) (ọmọ ọdún 102)
Bomoundi, Niger Delta, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Novelist, poet
Notable workThe Voice

 Wọ́n bi Gabriel Imomotimi Okara ni ojo Kerinlelogbon osu Kerin odun 1921 (born 24 April 1921). eni ti won bi ni Bumoundi  Yenagoa, Bayelsa State. O je akewi ati olukotan omo orile ede Naijria[1]  O je okan lara awon akewi igbalode (Modernist poet of Anglophone Africa) ile alawo dudu ti o n so Geesi. Won mo Gabriel latari awon iwe itan , The Voice (1964), ati iwe ewi ti o ko ti o fi gba ami eye, iyen: The Fisherman's Invocation (1978), The Dreamer ati His Vision (2005). Ninu awon iwe itan aroso ati ewi re ni Okara ti ma n fi eko, esin, alo-onitan ati awon ami oniruuru ile alawo dudu han. fun idi eyi, ni won se n pee ni "the Nigerian Negritudist".[2] Gege bi alatunse awon ise re Brenda Marie Osbey, se so, o ni " A le so wipe awon ise olokan-o-jokan paapaa julo ewi akoko ti Gabriel Okara koko ko ni ise litireso orile-ede Naijiiria ati ewi igbalode ile Adulawo ti bere"[3]

Igbesi aye re[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gabriel Imomotimi Gbaingbain Okara, je omo oloye ile Ijọ kan,[4]  won bi ni  Bomoundi ni ilu Niger Delta ni odun 1921. O keko nile eko ijoba ti  Government College Umuahia, ti o si tun lo si ile eko agba ti later Yaba Higher College. Lasiko ogun agbaye elekeji (World War II), o gbiyanju lati dara po mo omo ogun oke ti ile Britiko iyen British Royal Air Force sugbon ko pari eko wiwa oko ofurufu, amo o ba ile ise papako ofurufu ti  British Overseas Airway Corporation  ti won pada yi si (British Airways).[5]

Ni odun 1945, Okara ri ise gege bi atewe fun ile ise itewe ijoba amunisin ile Naijiria. O sise ni ile ise yii titi di igba ti oun naa fi bere si ni kowe jade. O koko sogbufo ewi kan lati ede Ijaw si ede Geesi, ti o si ko iwe fun ile ise iroyin asoro-magbesi ijoba . O keko nipa imo igbohun-safefe ni ile eko agba ti  Northwestern University ni odun 1949 saaju ija ogun abele Nigerian Civil War to be sile ni odun(1967–70).  O si tun sise gege bi Information Officer fun apa Ariwa ijoba Naijiria (Eastern Nigerian Government Service), ati onkowe Chinua Achebe, Okara tun je asoju fun Biafra laarin odun1969.[6] Lati 1972 si 1980, O je adari fun ile ise atewe ipinle Rivers State to wa ni Port Harcourt.[7]

Awon iwe re[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

leyin ti Okara kuro nile iwe, o ko iwe ere onise pelu aroko fun ile ise igbohun-safefe, ewi re ti o ko ni odun 1953 iyen: " "The Call of the River Nun" ni o fi gba ami eye ni odun idije fun ise atinuda (Nigerian Festival of Arts). Lara awon ewi re ni won te jade ninu iwe iroyin olose-ose ti Black Orpheus, ni 1960 o ti di ilu mooka lori agbekale ise re. Opo awon ewi re ni won ti se ogbufo re si orisirisi ede. Okara kopa ninu akojopo African Writers Conference ti o waye ni 1June,196 ni Makerere University College ni Kampala, Uganda, pelu awon onkowe bi: Chinua Achebe, Rajat Neogy, Bloke Modisane, Okot   p'Bitek, Bernard Fonlon, Ngugi Wa Thiong'o, Segun Olusola, Grace Ogot, Jonathan Kariara, Rebecca Njau, Wole Soyinka, John Pepper Clark, Saunders Redding, Christopher Okigbo, Francis Ademola, Ezekiel Mphahlele, Arthur Maimane, ati awon miiran bee. 

Eyi ti o gbajumo julo ninu awon ewi Okara ni "Piano and Drums".  Ewi miran to tun ;gbajumo ni "You Laughed and Laughed and Laughed", ni o fara han julo ninu awon iwe ajokopo ewi. Ohun ti o je  Okara lokan ju ni ipenija ti asa ati ise ile Adulawo n koju latari olaju awon Oyinbo Western culture, ni eyi ti ewi re "Once Upon a Time" so nipa re.[8]

O safihan akori yii ninu itan aroso re ti, The Voice (1964).  Ti olu eda itan  Okolo, feran asa igbalode awon  Geesi ju  asa ibile abinibi re lo."

Lafik awon ewi re ati itan aroso re Okara tun ti ko ere onise ti won ti ka seti igbo awon ara ile ninu ero asoro magbesi .

Opo awon aroko re ti ko tii di tite jade lo ba ogun abele Biafara lo.

Ni April 2017, won se  odun litireso ti won pe ni (Gabriel Okara Literary Festival) ni ogba ile eko University of Port Harcourt lati fi seye fun.[9][10] Ojogbon Chidi T. Maduka gbe iwe kan jade ti o pe ni "Gabriel Okra"  May 2017.  ti o fi salaye pe"Gabriel Okara ni won ko fi si ipo ti o ye ki o wa laarin awon onkowe litireso ile Adulawo" . Bakan naa ni   Lindsay Barrett, so wipe " Okara funra re ko ba ile eko Yunfasiti kan se" nigba ti Odia Ofeimun lu  Okara logo enu wipe "kii se wipe Okara je eni ti o  tipe ninu ise apileko nikan bi n ko se wipe oun ni bi ko se wipe oun ni o bere ise tite iwe litireso ni apa ile Adulawo".[11]

Awon ami eye re[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • 1953: Best All-Round Entry In Poetry at the Nigerian Festival of Arts, for "The Call of the River Nun"
  • 1979: Commonwealth Poetry Prize, for The Fisherman's Invocation
  • 2005: NLNG Prize, for The Dreamer, His Vision
  • 2009: Pan African Writers' Association Honorary Membership Award[12][13]
  • 2017: Gabriel Okara Literary Festival

Awon ise akanse re[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • 1964: The Voice (novel), London: Deutsch, first edition; Heinemann African Writers Series (No. 68), 1970. Africana Publishing, ISBN 0-8419-0015-90-8419-0015-9.
  • 1978: The Fisherman's Invocation (poems)
  • 1981: Little Snake and Little Frog (for children)
  • 1992: An Adventure to Juju Island (for children)
  • 2005: The Dreamer, His Vision (poems)
  • 2006: As I See It (poems)
  • 2016: Collected Poems (edited and with an introduction by Brenda Marie Osbey), University of Nebraska Press, African Poetry Book Series, ISBN 978-0-8032-8687-0978-0-8032-8687-0.

Awon itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Laurence, Margaret; Stovel, Nora Foster (2001). Long Drums & Cannons: Nigerian Dramatists and Novelists, 1952-1966. University of Alberta. pp. 171–. ISBN 978-0-88864-332-2. https://books.google.com/books?id=QxYr-RW-yF8C&pg=PA171. Retrieved 8 May 2011. 
  2. Sumaila Umaisha, "Gabriel Imomotimi Gbaingbain Okara: The Poet of the Nun River — interview", African Writing, No. 6.
  3. Brenda Marie Osbey, Introduction, Gabriel Okara: Collected Poems, University of Nebraska Press, 2016.
  4. "Gabriel Okara," in Hans M. Zell, Carol Bundy, Virginia Coulon, A New Reader's Guide to African Literature, Heinemann Educational Books, 1983; pp. 445–447.
  5. James M. Manheim, "Okara, Gabriel 1921–", Contemporary Black Biography . Encyclopedia.com.
  6. "Gabriel Okara (Gabriel Inomotimi Gbaingbain Okara) Biography", Jrank.org.
  7. "Gabriel Okara", Encyclopædia Britannica.
  8. Gabriel Okara, "Once Upon a Time", in Collected Poems, University of Nebraska Press, 2016.
  9. Ozolua Uhakheme,"A bouquet for poet Okara", The Nation, 8 March 2017.
  10. Anote Ajeluorou, "‘Gabriel Okara has written in all genres, yet not much attention has been given to his work’" Archived 2018-06-11 at the Wayback Machine., The Guardian (Nigeria), 19 March 2017.
  11. Anote Ajeluorou, "Gabriel Okara… Restoring the genius of Africa’s oldest living poet", The Guardian (Nigeria), 5 May 2017.
  12. "Chronology", Gabriel Okara: Collected Poems (2016).
  13. Evelyn Osagie, "Echoes of Achebe’s works at writers’ show", The Nation (Nigeria), 25 November 2015.

Fun ika siwaju si[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Echeruo, Michael J.C. "Gabriel Okara: a Poet and His Seasons." World Literature Today, 1992: 454–456
  • Mark Willhardt, Who's Who in 20th Century World Poetry, Routledge (2001, ISBN 0-415-16355-20-415-16355-2), p. 237.
  • Eldred Ibibiem Green, Gabriel Okara: The Man and His Art. Port Harcourt, Nigeria: Onyoma Research Publications, 2007.

Awon ija sode[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]