Gérard Kango Ouedraogo
Ìrísí
Gérard Kango Ouédraogo (ojoibi 1925) je Alakoso Agba orile-ede Upper Volta (loni bi Burkina Faso) lati 13 February 1971 de 8 February 1974. O tun di Aare Ile-Igbimo Asofin ile Burkina Faso lati 1978 de November 25, 1980.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |