Youssouf Ouédraogo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Youssouf Ouédraogo

Youssouf Ouédraogo (25 oṣù ọ̀pẹ, Ọdún 1952 – 18 oṣù Bélú, Ọdún 2017) jẹ́ Olóṣèlú ni Burkinabé. Ní ọdún 1992, Ó di Alakoso Agba orile-ede ìyẹn Puraimu Minisita Burkina Faso láti ọdún 1983. Ó sin ìlú láàárín 16 oṣù Ogúdù, Ọdún 1992 sì 22 oṣù ẹrẹ́nà, Ọdún 1994. Ouédraogo jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Alákòóso Congress for Democracy and Progress (OCP), O tún sin ìlú gẹ́gẹ́ bí Minisita Ìpínlẹ̀ fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀-òkèèrè, ìyẹn Minister of State for Foreign Affairs ní oṣù ṣẹ́ẹ́rẹ́, ọdún 1999 sì Ogúdù, ọdún 2007.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]