Joseph Conombo
Ìrísí
Joseph Issoufou Conombo (9 February 1917 – 20 December 2008) je Alakoso Agba orile-ede Upper Volta (loni bi Burkina Faso) lati 7 July 1978 de 25 November 1980. A bi ni ipinpa Kombissiri, o lo si ile-eko oniwosan ni Dakar, Senegal, leyin re o kopa ninu Ogun Agbaye Keji gege bi omo-ogun ile Fransi.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |