Jump to content

Idibo fun ipo Gomina ipinle Eko ni odun 2015

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Idibo fun ipo Gomina ipinle Eko waye ni ojo kokanla osu kerin odun 2015. Oludije ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) Akinwunmi Ambode, ti o jẹ oniṣiro agba fun ipinlẹ Eko tẹlẹ, bori oludije ẹgbẹ oṣelu People’s Democratic Party (PDP) Jimi Agbaje ati oludije Alliance for Democracy (AD) Bolaji Ogunseye. Gomina ati igbakeji gomina ni a yan lori tikẹti kanna.

Idibo fun asoju egbe APC

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oludije egbe APC Akinwunmi Ambode bori awon oludije mejila miran lati gba tikeeti egbe naa. O bori pelu ibo 3,735 lati bori oludije to sunmo re, Obafemi Hamzat (ti o gba ibo 1,201), ati olori ile igbimo asofin ipinle Eko Adeyemi Ikuforiji, eni to wa ni ipo keta to jinde pelu ibo mejilelogosan.

  • Akinwunmi Ambode
  • Obafemi Hamzat
  • Adeyemi Ikuforiji
  • Supo Shasore
  • Ganiyu Olanrewaju Solomon
  • Lekan Pitan
  • Tola Kasali
  • Tokunbo Agbesanwa
  • Abayomi Sutton
  • Adekunle Disu
  • Tokunbo Wahab
  • Lanre Ope

Ogbeni Akinwunmi Ambode ni o jawe olubori ti o de fi si ipo lati se asoju egbe APC ninu idibo gomina ipinle eko.

Idibo fun asoju egbe PDP

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ogbeni Jimi Agbaje ni o jawe olubori ti o de fi si ipo lati se asoju egbe PDP ninu idibo gomina ipinle eko.

Ogbeni Akinwunmi Ambode ni o jawe olubori ninu idibo gomina ipinle Eko ni odun 2015[1][2]


  • Idibo Apejọ Orilẹ-ede Naijiria, 2015 (Lagos State)
  1. https://dailypost.ng/2015/04/12/ambode-wins-lagos-gubernatorial-election/
  2. https://www.premiumtimesng.com/news/172484-breaking-akinwunmi-ambode-wins-lagos-apc-governorship-primaries.html