Jump to content

Joe el

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Joe El
Orúkọ àbísọJoel Amadi Didam
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiJoe EL, Joe-El, Joe Everlasting
Ọjọ́ìbíSokoto, Sokoto State, Nigeria
Irú orin
Occupation(s)
  • Singer
  • Songwriter
  • Musical performer
InstrumentsVocals
Years active2006–present
LabelsKennis Music
Associated acts

Joel Amadi, tí a mọ̀ sí Joe El, (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹta ) jẹ́ olórin, òǹkọrin àti eléré ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ilé-iṣẹ́ Kennis Music fọwọ́ síí.

Ní ọdún 2006, ó kópa nínú ìdíje orin-kíkọ tí Star Quest ní ìlú Jos,lẹ́yìn náà ni ó tún kópa nínú ìdíje ayẹyẹ àjíǹde ọlọ́dọọdún ti i Kennis Music.

Ẹbí àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìdílé Amadi Didam ní ìpínlẹ̀ Sokoto ni a bí Joel Amadi sí. Àmọ́ Ipinle Kano ni ó dàgbà sí.[1] Bàbá rẹ̀ wá láti Zikpak, ìlú Kafanchan, apá Gúúsù Ipinle Kaduna,[2] àti ìyá rẹ̀ láti ìlú Otukpa ní Ipinle Benue. Lẹ́yìn ètò ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀ẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní ilé-ìwé Ramat, ó lọ ilé-ìwé girama Army Day Secondary School, ní Bukavo Barracks, Ipinle Kano, lẹ́yìn tí ó ṣe tán, ó wá lọ Kaduna State College of Education, ní ìlú Kafanchan (èyí tó ní ìbáṣepọ̀ pèlú University of Jos), ó ṣe tán ní ọdún 2005, pẹ̀lú ìgboyè nínú Accounting àti Auditing.[1]

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-iṣẹ́ ìròyìn ni ó gbé ìròyìn ikú bàbá rẹ̀ láti ọwọ́ àwọn darandaran ìlú rẹ̀, wọ́n sì ba kẹ́dùn.[3][2][4]

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi olórin

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Joe El bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ rẹ̀ ní ọdún 2006 níbi tí ó ti kópa nínú ìdíje orin kan[5] èyí tó jẹ́ ìgbà àkọ́kọ́ rẹ̀ lórí ẹ̀rọ-amóhùn-máwòrán. Ní ọdún 2009, ó kó lọ sí ipinle Eko. Ó pàdé Kenny Ogungbe, olùdarí KEnnis Music, tí ó fún ni iṣẹ́ ní ọdún 2010. Oein àkọ́kọ́ kọ rẹ̀ ni "I No Mind" ni wọ́n padà yàn bíi orin R'n'b tó dára jù lọ ni NMVA 2011 awards.

Ó túnbọ̀ jẹ́ gbajúgbajà si nígbà tí ó gbé orin "Bakololo" jáde, èyí tí ó padà di orin tí ilé-iṣẹ́ rédíò máa ń kọ látigbà dégbà ní ọdún 2011 àti 2012. [5] Ó tún gbé orin bíi "Love song" and "Happy" jáde. Pẹ́lú àwọn orin yìí, ó lọ sí bíi ìpínlẹ̀ mẹ́rin ní orílẹ̀-èdè NAijiria,ó sí kọrin ní Glo Rock n Roll show, the Star Quest Grand Finale, the annual Kennis Music Easter Fiesta àti àwọn orí-ìtàgé ńlá mìíràn.[5]

Wọ́n máa ń fi wé 2face Idibia, tí ó jé gbajúgbajà olórin ilé Nàìjíríà nítori wọ́n jọra bákan.[6] Ní ọdún 2014, ó fi ìfé tó ní sí 2face Idibia hàn àti èrò ọkàn rẹ̀ hàn láti bá a kọrin.[7] Ní ọdún 2014, Joe El gbé orin kan jáde tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Hold On" níbi tí ó ti ṣàfihàn 2face Idibia.

  • "Gbemisoke", 2016
  • "Nwanyi Oma"
  • "Keep Loving"
  • "Yamarita" (featuring Olamide)
  • "Chukwudi" (featuring Iyanya)
  • "Celebrate" (featuring Yemi Alade)
  • "Oya Now" (featuring Oritsefemi)
  • "Rawa (dance)", 2019
  • "Epo" (featuring Davido, Zlatan)
  • Songs
  • Hold On
  • Timeless (2015)[8]
  • Do Good (2016)[9]
  • She Like Me
  • Onye (Eji Kolo)
  • You Are In Love
  • I No Mind
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • "Bridal" (featuring Sound Sultan and Honorebel)
  • Kennis Music All Starz Compilation (2011)[10]

Àwọ́n àmì-ẹyẹ̀ rè

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Year Event Prize Recipient Result Ref
2015 The Headies Award for Best Collaboration "Hold On" (featuring 2Baba)|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [11]
2014 The Headies Award for Best Collaboration style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [12]
Nigerian Music Video Award (NMVA) Best Video Award By A New Act "Oya Now" (featuring Oritsefemi) Gbàá [13]
Best Afro Beat Video style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [13]
Best RnB Video style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [13]
2013 The Most Finest Girl in Nigeria Beauty Pageant Best New Act Himself Gbàá
The Most Endorsed Artiste Himself Gbàá [1]
2012 Kennis Music The Most Laspotech celebrated Artiste of the year Award Himself Gbàá
2011 Nigerian Music Video Award (NMVA) Best RnB Video Award style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 1.2 "Joe El". notjustok. Archived from the original on 22 September 2020. Retrieved 8 August 2020. 
  2. 2.0 2.1 "Herdsmen Murder Singer Joeel's Father in Kaduna". THEWILL. 25 July 2020. Retrieved 8 August 2020. 
  3. Bamidele, Michael (July 25, 2020). "Joel Amadi Loses Father to Herdsmen Attack". The Guardian. https://m.guardian.ng/life/joel-amadi-loses-father-to-herdsmen-attack/. 
  4. "Singer Joel Amadi's Father Killed By Herdsmen". Retrieved 8 August 2020. 
  5. 5.0 5.1 5.2 "Joe El". notjustok. Archived from the original on 22 September 2020. Retrieved 8 August 2020. 
  6. Olatunbosun, Yinka (24 August 2014). "Nigeria: Joe-El's Journey to Stardom". All Africa. This Day. Retrieved 8 August 2020. 
  7. "I can't fight with Tuface Idibia; he's my brother, a legend. – JoEl Amadi (WATCH)". Idoma Voice. July 25, 2014. Retrieved 9 August 2020. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  8. "Nigerian Artist, Joe El Debuts 'Timeless' Album: Features International Music Prodigy B. Howard on 'Blown Away' Track". CISION PR Newswire. King Empire Entertainment. August 19, 2015. Retrieved August 17, 2020. 
  9. Yhusuff, al (16 September 2016). "Do Good". Tooxclusive. Archived from the original on 7 March 2021. Retrieved 8 August 2020. 
  10. "Kennis Music All Starz Compilation 2011". Retrieved August 17, 2020. 
  11. Adeleke, Shayo (30 September 2015). "The Headies Awards 2015 – Full Nominees List". 36NG. http://www.36ng.com.ng/2015/09/30/the-headies-awards-2015-full-nominees-list/. 
  12. "The Headies Awards 2014 – Full Nominees List (Year in Review: July 2013 - June 2014)". The Headies. May 25, 2014. Retrieved August 17, 2020. 
  13. 13.0 13.1 13.2 "Niyola's 'Toh Bad' Takes Away Best RnB Video At NMVA". Channels Television. November 27, 2014. Retrieved August 17, 2020.