Kiruki
Kiriku (ti a bí ní oṣù Kejìlá ojo kẹtàdínlógún ọdún 2014), tí orúkọ àbísọ rẹ sì jẹ Enorense Victory, jẹ́ ọmọ Nàìjíríà, aláwàdà, òǹkọ̀wẹ́ alátìnúdá àti ọmọdé Òṣeré .[1][2]
Ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kiriku jẹ́ ọmọ Benin láti Edo State.[3] Ó jẹ́ ará Urhobo.[4][5] Ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ni ó wà.[6] Òun ni àbúrò Umbrella Boy, tó tún jẹ́ alákòóso rẹ̀.[7][6] Òun ni ọmọ àbígbẹ̀yìn nínú àwọn ọmọ mẹ́rin tí òbí rè bí.[8]
Iṣẹ́ ọnà rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kiriku bẹ̀rẹ̀ ìṣe alawada rẹ ni ọmọ ọdún merin.[8] ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ tàn nígbà tí àwọn Fídíò rẹ tán sì ayélujára pẹ̀lú iranlọwọ Instablog9ja àti Tunde Ednut. Ó kókó bẹ̀rẹ̀ ìṣe rẹ ni ìlú re, Benin City, kí ó tó kó lọ sí ìlú Èkó Lagos - Tí ó jé orísun ìdániláráyá tí orílè èdè Nàìjíríà - láti tẹ́lẹ̀ ìṣe àwàdà rẹ. Ọtí ṣíṣe papọ̀ Broda Shaggi, Mr Funny ati Iyanya. Ó sì ti ní àpapò ìṣe pelu Officer Woos ati Cute Abiola.[9] Ìwé-ìròyìn The SUn pè é ní aláwàdà ọmọdé tí àwọn èèyàn fẹ̀ràn jù lọ ní Naijiria.[10][11]
Àmì-ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kiriku jáwé olúborí fún ìdíje "the Breakout Social Content Creator fún ọdún 2022, ní Net.ng awards.[12][13]
Ìgbésé ayé tí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Òun, àti ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ra ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ méjì fún àwọn òbí wọn méjèèjì ní ọdún 2022, gẹ́gé bí àmì ìdúpẹ́.[14][15] Ó ní ìdí tí òun fi ra ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ náà fún àwọn òbí rẹ̀ ni pé èyí tí wọ́n ń lò ti gbó, wọ́n sì ti ń lò ó fún àìmọye ọdún. Àti pé ó ti pinnu láti ra ọkọ̀ náà nígbà tí ó bá ti lówó.[16]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Kiriku, Child Content Creator Making A Difference". The Sun (Nigeria) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 24 May 2022.
- ↑ "Young Comedian And Skit Maker Kiriku On The Ruse For Comedy Excellence". This Day (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 10 April 2022.
- ↑ Ojo, James (November 17, 2022). "Skit Making Not Affecting My Education, says 7 Year Old Kiriku". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ "Nípa Kiriku : Àwọn òtítọ́ nípa Ọmọ tí òjò orírẹ koju ikeje ọmọ Nàìjíríà comedian". Eje's Gist (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Mar 19, 2022.
- ↑ Odebunmi, Samuel (August 22, 2022). "Mọ̀ nípa Kiriku: Ìtàn rẹ , iyẹ tí ó ní , Àwọn àmì í kàwé rẹ , Àti Ìṣe rẹ". Koko.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on September 24, 2023. Retrieved January 27, 2023.
- ↑ 6.0 6.1 Alake, Olumide (November 14, 2022). "“Many Think I Picked Kiriku From the Street”: Skitmaker Umbrella Boy Clears The Air, Shares Other". Legit.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ Akindele, Tolu (March 23, 2022). "Popular Young Instagram Skit Makers Working With Family Members". The Nation (Nigeria) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ 8.0 8.1 Nosa, Oke-Hortons (December 25, 2022). "7 Things You Need to Know About the Most Popular and Youngest Skit Maker in Nigeria". Legit.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ "Kiriku Worth Paying Attention, An Asset To The Industry – Mayowa Adenekan". Vanguard (Nigeria) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). November 16, 2022.
- ↑ "Kiriku: Nigeria’s Most Sought After Child Comedian". The Sun (Nigeria) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 24 May 2022.
- ↑ Azubuike, Emmanuel (August 6, 2022). "Kiriku: The Seven-Year-Old Nigerian Kid Comedian Who Is Bringing Laughter To Millions". The Netng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ Abiosun, Anjolaoluwa (July 5, 2022). "NET Honours 2022: Kiriku Wins Breakout Social Content Creator Of The Year". The Netng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ Azubuike, Emmanuel (July 5, 2022). "NET Honours 2022: “I Can’t Really Express How I Feel Right Now” Kiriku Reacts As He Bags His First-Ever Award". The Netng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ Bassey, Ekaete (13 June 2022). "Kiriku Acquires Two Mercedes Benz Cars". The Nation (Nigeria) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ Stephen, Kolade (13 June 2022). "Comedian Kiriku Buys Two Mercedes Benz Worth Millions Of Naira". NaijaLoaded (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ Ajose, Kehinde (4 December 2022). "Why I bought Car For My Father –Eight-year-old Skitmaker". The Punch (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).