Kola Muslim Animasaun
Ìrísí
Kola Muslim Animasaun | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 5 July 1939 |
Aláìsí | 30 May 2019 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Journalism |
Ìgbà iṣẹ́ | 1961 – present |
Gbajúmọ̀ fún | Vanguard |
Olóyè Kola Muslim Animasaun (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù keje, ọdún 1939) jẹ́ akọ̀ròyìn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àti alága ẹgbẹ́ olótùú fún ìwé-ìròyìn The Vanguard, tó ń ṣáájú àwọn ìwé-ìròyìn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ìwé rè From 1939 to the Vanguard of Moodern Journalism, ní wọ́n gbé jáde ní Nigerian Institute of International Affairs, ní ìpínlẹ̀ Èkó, ní oṣù keje, ọdún 2012. Àwọn ènìyàn pàtaàkì tó wà níbi ayẹyẹ nahà ni aṣíwájú Bola Tinubu, olórí ẹgbẹ́ òṣèlú ti Gbogbo Progressives Congress, àti Abiola Ajimobi, Gómìnà ipinle Oyo, tó wà ní apá Gúùsù mọ́ Ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Naijiria.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Blessed reunion in Vanguard". The Nation. 2 February 2007. Retrieved 13 June 2015.
- ↑ "Ajimobi, Tinubu urge journalists to be fearless". The Punch. Archived from the original on 2015-06-15. Retrieved 2015-06-13. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)