Lagos–Ibadan Expressway
Òpópónà Èkó – Ìbàdàn je opopona ti o gùn tó 127.6 kilometres (79.3 mi)* ti o so Ibadan, olu ilu ipinle Oyo pèlú Eko, ilu totobijulo orile-ede Naijiria. [1] O tun jẹ ọna pataki si ariwa, gusu ati awọn ẹya ila-oorun ni Nigeria. Ọna opopona jẹ èyí ti a kókó se ni Naijiria, ti a ṣe ni Oṣu Kẹjọ ọdun 1978 lakoko akoko ologun, labẹ iṣakoso Lieutenant-General Olusegun Obasanjo . [2]
Opopona náà jẹ ọkan ninu àwon opopona laarin ipinlẹ sí ìpínlè ti àwon ènìyàn n run julọ ní Nàìjíríà, awon oko ti o un gba ibè lojumo ma un le ni 250,000, o si je
si opopona ti o tobi julọ ni Afirika. [3] [4] O ara àwon isé tí ṣe AFederal Road Maintenance Agencyral (FER ma ún tun se laarin ìpínlè si
àjo ti óún ma un t
tun ojú ònà se ti óún ma Ma ún se larin à larinnipinle si
Titunṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni July 2013, Ááre Goodluck Ebele Jonathan aarẹ orílè-èdè Naijiria nígbà naa kéde àtúnse ònà náà, Aare Goodluck so pe yo din àkókò ti àwon ènìyàn n lo loju ònà ku. Ilé-isé Julius Berger Nigeria ati Reynolds Construction Company Limited ni wón gba isé náà owo àtúnse rè ni bilionu 167 Naira, owo ti o jé 838,986,290 dólà nígbà náà. [5] Awọn apa meji ti opopona náà ni wón yoo tun ṣe, apa kini (Lagos si Interchange Sagamu) ati apa kejì (Iparọpo Sagamu si Ibadan). [6]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Day of Horror on Lagos–Ibadan Expressway". http://www.vanguardngr.com/2014/11/day-horror-lagos-ibadan-expressway/.
- ↑ "Revealed: How OBJ Stopped Lagos–Ibadan Expressway Project". Archived on 21 May 2015. Error: If you specify
|archivedate=
, you must also specify|archiveurl=
. http://tribune.com.ng/news/top-stories/item/30170-revealed-how-obj-stopped-lagos-ibadan-expressway-project/30170-revealed-how-obj-stopped-lagos-ibadan-expressway-project. - ↑ "Auto Crash Claims Seven, Injures 20 Others Along Lagos–Ibadan Expressway". DailyPost Nigeria. http://dailypost.ng/2015/03/23/auto-crash-claims-seven-injures-20-others-along-lagos-ibadan-expressway/.
- ↑ "Pains of Motorists on Lagos–Ibadan Expressway". This Day Live. Archived from the original on 21 May 2015. https://web.archive.org/web/20150521043325/http://www.thisdaylive.com/articles/pains-of-motorists-on-lagos-ibadan-expressway/195037/.
- ↑ "Jonathan Flags-Off Reconstruction of Lagos–Ibadan Expressway". http://www.premiumtimesng.com/news/140305-jonathan-flags-off-reconstruction-of-lagos-ibadan-expressway.html. Retrieved 17 May 2015.
- ↑ "Nigeria: Reconstruction of Lagos–Ibadan Expressway Progressing Well". Archived from the original on 20 May 2015. https://web.archive.org/web/20150520103827/http://constructionreviewonline.com/2015/02/reconstruction-lagos-ibadan-road-nigeria-well-reconstruction/. Retrieved 17 May 2015.