M. K. O. Abíọ́lá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Moshood Abiola
Abiola.jpg
Ọjọ́ìbí (1937-08-24)24 Oṣù Kẹjọ 1937
Abeokuta
Aláìsí

7 Oṣù Keje, 1998 (ọmọ ọdún 60)


7 Oṣù Keje 1998(1998-07-07) (ọmọ ọdún 60)
Abuja
Orílẹ̀-èdè Nijiiria
Orúkọ míràn M.K.O Abiola
Iṣẹ́ Okowo, Oloselu, Oluranilowo.
Known for Being arrested following a Presidential election in Nigeria which he won/Philanthropy
Spouse(s) Simbiat Atinuke Shoaga[1][2]
Kudirat Olayinka Adeyemi[2]
Adebisi Olawunmi Oshin[2][1]
Doyinsola Abiola Aboaba[3][2]
Modupe Onitiri-Abiola[4][1]
Remi Abiola
(+other women)
Children Abdulateef Kola Abiola[1]
Dupsy Abiola
Hafsat Abiola
Rinsola Abiola
Khafila Abiola
(+other children)

Moshood Kashimawo Olawale Abiola (August 24, 1937 - July 7, 1998) ti a tun mo si M.K.O Abiola jẹ́ omo orile ede Naijiria. A bi ni ilu Abeokuta ni Ipinle Ogun. O je onisowo,ontewe, oloselu ati oloye ile Yoruba Egba patapta. O dije sipo Aare orile-ede Nijiiria ni odun 1993, oun naa si ni gbogbo eniyan gbagbo ati fenuko si jake-jado orile-ede Nijiiria wipe o jawe olubori nigba ti olori ijoba ologun igba naa Ibrahim Babangida ko kede re gege bi olubori eto idibo naa ti o si fi esun aisotito ati aisododo eto idibo yan naa. M.K.O ku ni odun 1998.

Igbesi Aye re[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Moshood Abiola ni akobi  baba ati iya re leyin ikunle omo ketalelogun, idi eyi ni o faa ti won fi duro titi di eyin odun meedogun (15 years) ki awon obi re to fun loruko re “Kasimawo”[5] . Moshood fakoyo ninu imo idagbale (entrepreneur) lati igba ewe re, o bere ise igi-sise –ta lati omo odun mesan. O ma n ji ni idaji lo soko igi lati wagi ti yoo ta saaju ki o to lo si ile-iwe ki oun ati baba re to ti rugbo pelu awon aburo re o le rowo na. Nigba ti o to omo odun meedogun (15 years), o da egbe ere kan kale ti won ma n korin kiri lati le ri ounje je nibi inawo eyikeyi ti won ba lo. Laipe, o di gbaju-gbaja nibi orin re to n ko kiri, o si di eni ti o n bere fun owo ise ki won to korin lode inawo kan-kan. Awon owo ti o n ri nibi ere re yii ni o fin n ran ebi re lowo ti o si n san owo ile-eko giga ti Ijo Onitebomi ti o wa ni Abeokuta . Abiola je Olootu iwe iroyin osoose ile-iwe won ti o n je The Trumpeter ti Olusegun Obasanjo si je igbakeji re. O dara po mo egbe National Council of Nigeria and the Cameroons ni igba ti o di omo odun mokandinlogun nitori ife ti o ni si eto oselu awa arawa labe asia Obafemi Awolowo oludasile egbe oselu Action Gruop.[6]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named wives
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named international
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named encyclopedia
  4. "REMEMBERING ABIOLA, 15 YEARS AFTER". National Mirror. July 6, 2013. http://nationalmirroronline.net/new/remembering-abiola-15-years-after/. Retrieved March 26, 2017. 
  5. Meaning of Kashimawo in Nigerian.name
  6. "Legend of our Time: The Thoughts of M.K.O. Abiola" Ogunbiyi and Amuta(eds), Tanus Press, p. 5