Nigeria Ministry of Education
Ilé-iṣẹ́ àpapọ̀ ẹ̀kọ́ tí wọ́n máa ń pè ní (Federal Ministry of Education) jẹ́ apá kan ti àwọn ilé-iṣẹ́ àpapọ̀ Naijiria (Federal Ministries of Nigeria) tí ó ń ṣe ìtọ́sọ́nà ètó-ẹ̀kọ́ ní Nàìjíríà. Ó wà ní Block 5A (8th Floor), Federal Secretariat Complex, Shehu Shagari Way, Central Area, P.M.B. 146, Garki, Abuja.
Ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ààrẹ Muhammadu Buhari yan Adamu Adamu, gbajúgbajà oníròyìn gẹ́gẹ́ bí mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ ní oṣù kọkànlá ọdún 2015.[1]
Iṣẹ́ Wa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]" Ìpinnu wa ni láti lo ètò-ẹ̀kọ́ gẹ́gẹ́ bí ohun èlò fún ìtèsíwájú ìdàgbàsókè gbogbo àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sí agbára wọn ní kíkún, fún ìgbéga ti orílẹ̀-èdè tí ó lágbára, tiwa-n-tiwa, dọ́gbadọ́gba, tí ó ní ìlọsíwájú, tí a kò pin àti àìbíkítà orílẹ̀-èdè aláṣẹ lábẹ́ Ọlọ́run."[2]
Ilé Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn isẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú:
- al policy on education.
- Collecting and collating data for purposes of educational planning and financing.
- Maintaining uniform standards of education throughout the country.
- Controlling the quality of education in the country through the supervisory role of the Inspectorate Services Department within the Ministry.
- Harmonizing educational policies and procedures of all the states of the federation through the instrumentality of the National Council on Education.
- Effecting co-operation in educational matters on an international scale.
Ara ilé iṣẹ́ àti àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Parastatal include:
- National Board for Technical Education (NBTE Archived 2022-07-19 at the Wayback Machine.), Kaduna.
- National Commission for Colleges of Education (NCCE), Abuja.
- Universal Basic Education Commission (UBEC), Abuja.
- National Commission for Nomadic Education (NCNE Archived 2021-06-24 at the Wayback Machine.), Abuja.
- National Commission for Adult Education Mass Literacy and Non-Formal Education (NMEC), Abuja.
- Nigerian Educational Research and Development Council (NERDC), Sheda, FCT.
- Joint Admissions and Matriculation Board (JAMB), Bwari, Abuja.
- West African Examination Council (WAEC), Lagos.
- National Examination Council (NECO), Minna, State.
- National Business and Technical Examinations Board (NABTEB Archived 2021-06-23 at the Wayback Machine.), Benin-city, Edo.
- National Institute for Educational Planning & Administration (NIEPA Archived 2021-06-24 at the Wayback Machine.), Ondo.
- National Teachers Institute (NTI), Kaduna.
- Nigerian Mathematical Centre (NMC), Sheda, FCT.
- Nigerian French Language Village (NFV)Badagry, Lagos.
- Nigerian Arabic Language Village (NALV) Ngala, Borno.
- National Institute for Nigerian Languages (NINLAN) Aba, Abia.
- Tertiary Education Trust Fund (TET FUND), Abuja.
- National Library of Nigeria (NLN), Abuja.
- Teachers’ Registration Council of Nigeria (TRCN Archived 2022-07-13 at the Wayback Machine.), Abuja.
- Computer Professionals Registration Council of Nigeria (CPN), Lagos.
- Federal Scholarship Board, Abuja.
- Librarians' Registration Council of Nigeria (LRCN Archived 2022-06-20 at the Wayback Machine.), Abuja
- ↑ "Jubilation at Education Ministry as Adamu takes over". Nigeria. Archived from the original on 2016-03-04. Retrieved 2015-11-14.
- ↑ "Home" (in en-US). FEDERAL MINISTRY OF EDUCATION. https://education.gov.ng/.