Ẹ̀bùn Nobel nínú Físíksì
Ẹ̀bùn Nobel nínú Físíksì The Nobel Prize in Physics | |
---|---|
Bíbún fún | Outstanding contributions in Physics |
Látọwọ́ | Royal Swedish Academy of Sciences |
Orílẹ̀-èdè | Sweden |
Bíbún láàkọ́kọ́ | 1901 |
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ | http://nobelprize.org |
Ẹ̀bùn Nobel nínú Físíksì (Àdàkọ:Lang-sv) je bibun ni ekan lodun latowo Akademy àwon Sayensi Oba Swidin. O je ikan ninu Ebun Nobel marun ti won je didasile latowo akoole ijogun Alfred Nobel ni 1895 o si unje bibun lati 1901; awon yioku ni Ebun Nobel ninu Kemistri, Ebun Nobel ninu Litireso, Ebun Nobel Alafia, ati Ebun Nobel fun Iwosan. Ebun Nobel ninu Fisiksi akoko je bibun fun Wilhelm Conrad Röntgen, ara Jemani, " fun idamo ise iwofa pataki to ti se nipa iwari àwọn ìranná (tabi ìranná-x tabi x-rays)." Ebun yi unje mimojuto latowo Nobel Foundation beesini won gba kakiri bi ebun oniyijulo ti onimosayensi kan le gba ninu fisiksi. Won unfihan ni Stockholm ni bi ajoyo ododun ni 10 Osu Kejila, to je ajodun iku Nobel. Físíksì
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |