Oníṣe:Drhay8/drafts

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
The Smart Money Woman
Fáìlì:The Smart Money Woman poster.jpg
Written byJola Ayeye
Directed byBunmi Ajakaiye
StarringOsas Ighodaro
Kemi Lala Akindoju
Timini Egbuson
Toni Tones
Country of originNigeria
Original language(s)English
No. of seasons1
No. of episodes7
Production
Executive producer(s)Arese Ugwu
Producer(s)Kemi Lala Akindoju
Production location(s)Lagos, Lagos State, Nigeria
Release
First shown inNigeria
Original releasepresent

The Smart Money Woman Jẹ fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà oloṣeṣe ti o da lórí aramada 2016 ti orukọ n je Arese Ugwu.[1] Afihan akoko rẹ̀ jàde lórí AfricanMagic Showcase ní oṣù kẹsan ní ọdún 2020.[1] A ṣè àwọn fíìmù náà lati ṣe iṣe iyasọtọ ati mu ohun ti o wa nínú iwe aramada náà wa si oju aye.[2] Akoko Afihan ise yi, jàde ní ori AfricanMagic gege bi ise oni'pele mẹtala.[1][3] Onkọwe Arese Ugwu àti Kemi Lala Akindoju lo gbe jàde. O ya Osas Ighodaro, Timini Egbuson, Ini Dima-Okojie, Kemi Lala Akindoju àti ọpọlọpọ àwọn miiran.[1][4]


Ètò Eré[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

The Smart Money Woman jẹ́ ìtàn àwọn obìnrin marun àti bí wọ́n se n ṣé iṣakoso inawo àti dukia, ìtàn aramada náà dale lórí eto inawo àwọn obìnrin ati bí o nse nipa ribiribi lori ojo iwaju inawo won..[5] ìtàn aramada náà tun sọrọ nípa àwọn ọrẹ, iwa nípa afarawe, àti bí àwọn ipa awujọ se n ṣé akoso inawo lawo li 'jo iwaju.[6]

Àwọn Akópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 "Arese Ugwu's 'Smart Money Woman' series is coming to Netflix". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-07-28. Retrieved 2021-10-06. 
  2. "'The Smart Money Woman' official trailer". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-13. Retrieved 2021-10-06. 
  3. Odusola, Aby (2020-08-13). "The Smart Money Woman Series Is Coming To Our Screens In September!". The Culture Custodian (Est. 2014) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-07. 
  4. "The Smart Money Woman | Netflix". www.netflix.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-06. 
  5. Tv, Bn (2021-02-03). "The Cast of Arese Ugwu’s “The Smart Money Woman” Answer Questions on their Roles, Relationships & Finances". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-06. 
  6. BellaNaija.com (2021-07-30). "Arese Ugwu’s “The Smart Money Woman” is Coming to Netflix". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-06.