Operation Àmọ̀tẹ́kùn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Operation Àmọ̀tẹ́kùn jẹ́ àgbáríjọ pọ̀ ẹ́ṣọ́, ọ̀tẹlẹ̀-múyẹ́ àti ọlọ́pàá gbogbo ìpínlẹ̀ Iléẹ̀ Yorùbá lápapọ̀ tí olú ilé iṣẹ́ wọn wà ní ìlú ÌbàdànÌpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí gbogbo àwọn Gómìnà Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà gbé kalẹ̀ láti ró ilẹ̀ Yorùbá lágbára ní abala ètò àbò. [1]

Kókó iṣẹ́ wọn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n gbé Amọ̀tẹ́kùn kalẹ̀ léte àti gbógun ti ìpànìyàn lọ́nà àtiọ́,[2] ìdígùn-jalè, ìjínigbé gbowó-ipá ìfi ohun ìní àti dúkìá ṣòfò tí ó ń ti ọwọ́ àwọn àtiọ̀húnrìnwá tínwọ́nbjẹ́ afura sí wípé wọ́n jẹ́ àwọn fúlàní dáran-daran. Kìí ṣe láti fi tako iṣẹ́ àwọn àjọ ọlọ́pàá tàbí àwọn ológun orí-ilẹ̀ ti ìjọba àpapọ̀, bí kò ṣe láti ṣe ìkúnlápá kí ètò àbò tó mẹ́hẹ ní pàá pàá jùlọ agbègbè àti àwọn ìlú apá ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà ó lè dúró ṣinṣin. [3]

Àwọn ìpínlẹ̀ tó ni Àmọ̀tẹ́kùn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Gbogbo àwọn ìpínlẹ̀ ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà tí wọ́n dá Àmọ́tẹ́kùn sílẹ̀ẹ̀ ni:

Gbàgbé àjọ ẹ̀ṣọ́ Àmọ̀tẹ́kùn kalẹ̀ fi bí ìfẹ́ àti ìdàgbàsókè òun àbò ilẹ̀ Yorùbá ṣe jẹ àwọn ọmọ Ódùduwà lógún sí.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Insecurity: Ondo to launch ‘Operation Amotekun’". The Eagle Online (in Èdè Bosnia). 2019-09-12. Retrieved 2020-01-11. 
  2. "Operation Amotekun Archives - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 2020-01-11. Retrieved 2020-01-11. 
  3. "OPERATION AMOTEKUN: S’West govs’ motion without movement". Vanguard News. 2019-11-08. Retrieved 2020-01-11. 
  4. "Military, Police Absent as South-west Govs Launch Operation Amotekun". THISDAYLIVE. 2020-01-10. Retrieved 2020-01-11. 

Àdàkọ:Ẹ̀ka