Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Agbalagba (2): Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
Yemi festus (ọ̀rọ̀ | àfikún) |
Àlẹ̀mọ́: Reverted |
||
Ìlà 5: | Ìlà 5: | ||
</div> |
</div> |
||
---- |
---- |
||
{{Àdàkọ:Afd top}} |
|||
====Ọ̀rọ̀ ìforúkọsílẹ̀==== |
====Ọ̀rọ̀ ìforúkọsílẹ̀==== |
||
<!-- sọ̀rọ̀ ṣóki nípa ìdí tí o fi fẹ́ fa oníṣẹ́ yìí sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí alábójútó--> |
<!-- sọ̀rọ̀ ṣóki nípa ìdí tí o fi fẹ́ fa oníṣẹ́ yìí sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí alábójútó--> |
||
Ẹ kú déédé àsìkò yí o! Orúkọ oníṣẹ́ mi ni [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] . Mo jẹ́ aláfikún sí Wikipedia èdè Yorùbá láti ǹkan bí ọdún mẹ́sàn án sẹ́yìn. Bákan náà ni mo sì jẹ́ Ààrẹ fún ẹgbẹ̀ Yorùbá Wikimedians User Group tí a ń ṣe agbátẹrù fùn Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àìmọye ènìyàn nípa Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ń tọrọ láti di alábòójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá nítorí mo ṣàkíyèsí wípé a nílò alábòójútó si lòrì Wikipedia Yorùbá. |
Ẹ kú déédé àsìkò yí o! Orúkọ oníṣẹ́ mi ni [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] . Mo jẹ́ aláfikún sí Wikipedia èdè Yorùbá láti ǹkan bí ọdún mẹ́sàn án sẹ́yìn. Bákan náà ni mo sì jẹ́ Ààrẹ fún ẹgbẹ̀ Yorùbá Wikimedians User Group tí a ń ṣe agbátẹrù fùn Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àìmọye ènìyàn nípa Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ń tọrọ láti di alábòójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá nítorí mo ṣàkíyèsí wípé a nílò alábòójútó si lòrì Wikipedia Yorùbá. |
||
Ẹ lè dìbò fúnminpẹ̀lú kí ẹ tẹ ''Mo faramọ'' nísàlẹ̀, kí ẹ sì kọ èrò yín síbẹ̀ pẹ̀lú. Ẹ ṣeun púpọ̀ fún ìbuwọ́lù yín. [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba|ọ̀rọ̀]]) 13:23, 9 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC) |
Ẹ lè dìbò fúnminpẹ̀lú kí ẹ tẹ ''Mo faramọ'' nísàlẹ̀, kí ẹ sì kọ èrò yín síbẹ̀ pẹ̀lú. Ẹ ṣeun púpọ̀ fún ìbuwọ́lù yín. [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba|ọ̀rọ̀]]) 13:23, 9 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC) |
||
{{Àdàkọ:Afd bottom}} |
|||
====Ìjíròrò==== |
====Ìjíròrò==== |
Àtúnyẹ̀wò ní 12:14, 18 Oṣù Ọ̀wàrà 2024
Àwọn ìfi orúkosílẹ̀ fún alámòjútó tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ
Àkókò tí a wà lọ́wọ́lọ́wọ́ ni
- Ijíròrò tó tẹ̀le yìí jẹ́ àkójọ ìjíròrò pẹ̀lú ìbéèrè fún ìparẹ́ àpilẹ̀kọ tó wà lókè. Ẹ jọwọ, ẹ má ṣe ṣe àtúnṣe sí i. Ẹ máa fi àwọn èrò tuntun yín sí ojú ìjíròrò tó yẹ (bíi ojú-ewe ìjíròrò àpilẹ̀kọ tàbí nígbà àyẹ̀wò ìparẹ́). Ẹ má ṣe fi àtúnṣe kankan sí ojú ewe yìí mọ́.
Ọ̀rọ̀ ìforúkọsílẹ̀
Ẹ kú déédé àsìkò yí o! Orúkọ oníṣẹ́ mi ni Agbalagba . Mo jẹ́ aláfikún sí Wikipedia èdè Yorùbá láti ǹkan bí ọdún mẹ́sàn án sẹ́yìn. Bákan náà ni mo sì jẹ́ Ààrẹ fún ẹgbẹ̀ Yorùbá Wikimedians User Group tí a ń ṣe agbátẹrù fùn Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àìmọye ènìyàn nípa Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ń tọrọ láti di alábòójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá nítorí mo ṣàkíyèsí wípé a nílò alábòójútó si lòrì Wikipedia Yorùbá. Ẹ lè dìbò fúnminpẹ̀lú kí ẹ tẹ Mo faramọ nísàlẹ̀, kí ẹ sì kọ èrò yín síbẹ̀ pẹ̀lú. Ẹ ṣeun púpọ̀ fún ìbuwọ́lù yín. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 13:23, 9 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
- Ijíròrò lókè yìí ni a fipamọ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bi àkójọ àwọn òfin àròkò náà. Ẹ jọwọ, ẹ má ṣe ṣe àtúnṣe sí i. Ẹ máa fi àwọn èrò tuntun yín sí ojú ìjíròrò tó yẹ (bíi ojú-ewe ìjíròrò àpilẹ̀kọ tàbí nígbà àyẹ̀wò ìparẹ́). Ẹ má ṣe fi àtúnṣe kankan sí ojú ewe yìí mọ́. Ẹ má ṣe fi àtúnṣe kankan sí ojú ewe yìí mọ́.
Ìjíròrò
- Àwọn ìjápọ̀ fún oníṣẹ́ Àpẹrẹ: Agbalagba (talk.contribs.deleted.logs.block log.lu.rfar.rfc.rfcu.ssp.spi)
- A lè rí àwọn àtúnṣe tí oníṣẹ́ Àpẹrẹ ti sọ̀rọ̀níṣókí ní ibí.
Jọ̀wọ́ sọ̀rọ̀ tútù tó dára, pẹ̀lụ́ ìrẹ̀lẹ̀. Tí o kò bá mọ oníṣẹ́ tí ó fẹ́ di alábójútó yìí dáradára, Jọ̀wọ́ ṣe àyẹ̀wo àfikún rẹ̀ dáradára kí o tó dási.
Ìkọ àfìkọṣábẹ́=====Faramọ́ (support)=====
- Mo faramọ́ kí Ọ̀GBẸ́NI Mikaeel tí orúkọ oníṣẹ́ ẹ wọ́n jẹ́ Àgbàlagbà di alámòójútó látàrí iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ń ṣeApalopadidun1 (ọ̀rọ̀)
- Mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel, pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ Àgbàlagbà, di alámòjútó. Enitanade (ọ̀rọ̀) 18:57, 10 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
- Inú mi dùn púpọ̀ pẹ̀lú ẹ̀mí ìdarí tí Ọ̀gbẹ́ni Mikael, nítorí náà, mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel, pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ Àgbàlagbà, di alámòjútó. Oníṣe:SolutionTomi
- Mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel, pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ Àgbàlagbà, di alámòjútó lórí ìkànni Yorùbá Wikipedia yìí.Ọmọladéabídèmí99 (ọ̀rọ̀) 08:45, 11 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
- Mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel, pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ Àgbàlagbà, di alámòjútó lórí ìkànnì Wikipedia Yorùbá nítorí iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n mọ̀ ṣe, tí wọ́n sì máa ń ṣe lórí Wikipedia Yorùbá.--Àìná - TheSymbyat (ọ̀rọ̀) 09:04, 11 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
- Inú mi dùn púpọ̀ pẹ̀lú ẹ̀mí ìdarí tí Ọ̀gbẹ́ni Mikael, nítorí náà, mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel, pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ Àgbàlagbà, di alámòjútó Oníṣe: Olaide07
- Mo faramọ́ kí oníṣe Agbalagba jẹ́ alámójútó lórí Wikipedia Yoruba, wọ́n ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ Àfikún sí Wikipedia Yoruba láàrín ọdún tí ó kọjá sí ìsinsìnyí. Marvelousola01 (ọ̀rọ̀) 10:05, 11 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
- Mo faramọ́ kí oníṣe Agbalagba jẹ́ alámójútó lórí Wikipedia Yoruba, wọ́n ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ Àfikún sí Wikipedia Yoruba láàrín ọdún tí ó kọjá sí ìsinsìnyí. Billy bindun (ọ̀rọ̀) 11:33, 11 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
- Mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel, pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ Àgbàlagbà, di alámòjútó lórí ìkànnì Yorùbá Wikipedia yìí.Oluwatoyin Ayomide (ọ̀rọ̀)
- Mo faramọ lọpọlọpọ Macdanpets (ọ̀rọ̀) Macdanpets 21:52, 11 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
- Inú mi dùn láti faramọ́ Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel tí orúkọ oníṣẹ́ rẹ̀ jẹ́ Àgbàlagbà láti jẹ alámòjútó lórí ìkànnì Yorùbá Wikipedia.Ruth-4life (ọ̀rọ̀) 12:20, 11 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
- mo faramọ kí oníṣé àgbàlagbà jé̩ alámójútó Wikipedia.omo iya eleja (ọrọ)
- Mo faramọ́ kí oníṣẹ́ Àgbàlagbà ó di Alábòójútó àgbà fún Wikipedia èdè Yorùbá látàrí ipa takun takun wọn tí wọ́n ti ń kó lórí ìdàgbàsókè Wikipedia èdè Yorùbá pàá pàá jùlọ ìṣàkóso àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Yorùbá Wikimedians lápapọ.Bibiire1 (ọ̀rọ̀) 17:41, 16 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
- Mo faramo kí oníse Agbalagba ó di alábòójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá.Yemi festus (ọ̀rọ̀) 17:53, 16 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
lòdìsí (oppose)
Ìdásí gbogboògbò (general comment)
tí àwọn ìforúkosílẹ̀ kó bá dé ojú ìwọ̀n.