Jump to content

Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Agbalagba (2): Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
Àlẹ̀mọ́: Reverted
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Manual revert Reverted
Ìlà 5: Ìlà 5:
</div>
</div>
----
----
{{Àdàkọ:Afd top}}
'''<big>Oyege'''</big>. [[User:T Cells]] 12:31, 18 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
----
====Ọ̀rọ̀ ìforúkọsílẹ̀====
<!-- sọ̀rọ̀ ṣóki nípa ìdí tí o fi fẹ́ fa oníṣẹ́ yìí sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí alábójútó-->
Ẹ kú déédé àsìkò yí o! Orúkọ oníṣẹ́ mi ni [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] . Mo jẹ́ aláfikún sí Wikipedia èdè Yorùbá láti ǹkan bí ọdún mẹ́sàn án sẹ́yìn. Bákan náà ni mo sì jẹ́ Ààrẹ fún ẹgbẹ̀ Yorùbá Wikimedians User Group tí a ń ṣe agbátẹrù fùn Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àìmọye ènìyàn nípa Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ń tọrọ láti di alábòójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá nítorí mo ṣàkíyèsí wípé a nílò alábòójútó si lòrì Wikipedia Yorùbá.
Ẹ lè dìbò fúnminpẹ̀lú kí ẹ tẹ ''Mo faramọ'' nísàlẹ̀, kí ẹ sì kọ èrò yín síbẹ̀ pẹ̀lú. Ẹ ṣeun púpọ̀ fún ìbuwọ́lù yín. [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba|ọ̀rọ̀]]) 13:23, 9 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)

Ìlà 68: Ìlà 60:

Ready now? Take a deep breath and go!

END INSTRUCTIONS -->
END INSTRUCTIONS -->
{{Àdàkọ:Afd bottom}}

---- <!-- Please leave this horizontal rule -->
---- <!-- Please leave this horizontal rule -->
[[Ẹ̀ka:Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó]]
[[Ẹ̀ka:Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó]]

Àtúnyẹ̀wò ní 12:38, 18 Oṣù Ọ̀wàrà 2024

Àkékúrús:
WP:RFA
WP:RFX
WP:Àpẹrẹ

Àwọn ìfi orúkosílẹ̀ fún alámòjútó tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ

Àkókò tí a wà lọ́wọ́lọ́wọ́ ni

Ọjọ́bọ̀ 26 Oṣù Kejìlá 2024

Ọ̀rọ̀ ìforúkọsílẹ̀

Ẹ kú déédé àsìkò yí o! Orúkọ oníṣẹ́ mi ni Agbalagba . Mo jẹ́ aláfikún sí Wikipedia èdè Yorùbá láti ǹkan bí ọdún mẹ́sàn án sẹ́yìn. Bákan náà ni mo sì jẹ́ Ààrẹ fún ẹgbẹ̀ Yorùbá Wikimedians User Group tí a ń ṣe agbátẹrù fùn Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àìmọye ènìyàn nípa Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ń tọrọ láti di alábòójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá nítorí mo ṣàkíyèsí wípé a nílò alábòójútó si lòrì Wikipedia Yorùbá. Ẹ lè dìbò fúnminpẹ̀lú kí ẹ tẹ Mo faramọ nísàlẹ̀, kí ẹ sì kọ èrò yín síbẹ̀ pẹ̀lú. Ẹ ṣeun púpọ̀ fún ìbuwọ́lù yín. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 13:23, 9 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]

Ìjíròrò

Jọ̀wọ́ sọ̀rọ̀ tútù tó dára, pẹ̀lụ́ ìrẹ̀lẹ̀. Tí o kò bá mọ oníṣẹ́ tí ó fẹ́ di alábójútó yìí dáradára, Jọ̀wọ́ ṣe àyẹ̀wo àfikún rẹ̀ dáradára kí o tó dási.

Ìkọ àfìkọṣábẹ́=====Faramọ́ (support)=====

  1. Mo faramọ́ kí Ọ̀GBẸ́NI Mikaeel tí orúkọ oníṣẹ́ ẹ wọ́n jẹ́ Àgbàlagbà di alámòójútó látàrí iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ń ṣeApalopadidun1 (ọ̀rọ̀)
  2. Mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel, pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ Àgbàlagbà, di alámòjútó. Enitanade (ọ̀rọ̀) 18:57, 10 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
  3. Inú mi dùn púpọ̀ pẹ̀lú ẹ̀mí ìdarí tí Ọ̀gbẹ́ni Mikael, nítorí náà, mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel, pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ Àgbàlagbà, di alámòjútó. Oníṣe:SolutionTomi
  4. Mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel, pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ Àgbàlagbà, di alámòjútó lórí ìkànni Yorùbá Wikipedia yìí.Ọmọladéabídèmí99 (ọ̀rọ̀) 08:45, 11 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
  5. Mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel, pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ Àgbàlagbà, di alámòjútó lórí ìkànnì Wikipedia Yorùbá nítorí iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n mọ̀ ṣe, tí wọ́n sì máa ń ṣe lórí Wikipedia Yorùbá.--Àìná - TheSymbyat (ọ̀rọ̀) 09:04, 11 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
  6. Inú mi dùn púpọ̀ pẹ̀lú ẹ̀mí ìdarí tí Ọ̀gbẹ́ni Mikael, nítorí náà, mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel, pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ Àgbàlagbà, di alámòjútó Oníṣe: Olaide07
  7. Mo faramọ́ kí oníṣe Agbalagba jẹ́ alámójútó lórí Wikipedia Yoruba, wọ́n ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ Àfikún sí Wikipedia Yoruba láàrín ọdún tí ó kọjá sí ìsinsìnyí. Marvelousola01 (ọ̀rọ̀) 10:05, 11 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
  8. Mo faramọ́ kí oníṣe Agbalagba jẹ́ alámójútó lórí Wikipedia Yoruba, wọ́n ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ Àfikún sí Wikipedia Yoruba láàrín ọdún tí ó kọjá sí ìsinsìnyí. Billy bindun (ọ̀rọ̀) 11:33, 11 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
  9. Mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel, pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ Àgbàlagbà, di alámòjútó lórí ìkànnì Yorùbá Wikipedia yìí.Oluwatoyin Ayomide (ọ̀rọ̀)
  10. Mo faramọ lọpọlọpọ Macdanpets (ọ̀rọ̀) Macdanpets 21:52, 11 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
  11. Inú mi dùn láti faramọ́ Ọ̀gbẹ́ni Mikaeel tí orúkọ oníṣẹ́ rẹ̀ jẹ́ Àgbàlagbà láti jẹ alámòjútó lórí ìkànnì Yorùbá Wikipedia.Ruth-4life (ọ̀rọ̀) 12:20, 11 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
  12. mo faramọ kí oníṣé àgbàlagbà jé̩ alámójútó Wikipedia.omo iya eleja (ọrọ)
  13. Mo faramọ́ kí oníṣẹ́ Àgbàlagbà ó di Alábòójútó àgbà fún Wikipedia èdè Yorùbá látàrí ipa takun takun wọn tí wọ́n ti ń kó lórí ìdàgbàsókè Wikipedia èdè Yorùbá pàá pàá jùlọ ìṣàkóso àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Yorùbá Wikimedians lápapọ.Bibiire1 (ọ̀rọ̀) 17:41, 16 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
  14. Mo faramo kí oníse Agbalagba ó di alábòójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá.Yemi festus (ọ̀rọ̀) 17:53, 16 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
lòdìsí (oppose)
Ìdásí gbogboògbò (general comment)

Pa cache ojú ewé rẹ́ tí àwọn ìforúkosílẹ̀ kó bá dé ojú ìwọ̀n.