Jump to content

Rosaline Meurer

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Rosaline Meurer
Ọjọ́ìbíRosaline Ufuoma Meurer
15 Oṣú Kejì Ọdún 1992
Ọmọ orílẹ̀-èdèGámbíà
Nàìjíríà
Iṣẹ́òṣèré àti afẹwàṣiṣẹ́

Rosaline Ufuoma Meurer (tí a bí ní 15 Oṣú Kejì Ọdún 1992), jẹ́ òṣèrébìnrin àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ-èdè Gámbíà àti Nàìjíríà.[1][2] Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ kan tí ó kó ní ọdún 2014 gẹ́gẹ́ bi Kaylah nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Oasis; àti fún ipa tí ó kó nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Merry Men: The Real Yoruba Demons ti ọdún 2018 gẹ́gẹ́ bi Kẹ́mi Alẹ́ṣinlọ́yẹ́.[3][4]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Meurer dag̀bà ní orílẹ̀-èdè Gámbíà níbití ó ti ní ètò-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀. Ó ti ní oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ ìṣàkóso òwò, ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ bí a ti ṣé n ya àwòrán.[5]

Iṣẹ́ ìṣe rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Meurer bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi afẹwàṣiṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè Gámbíà, ṣááju kí ó tó wá sí Nàìjíríà ní ọdún 2009. Desmond Elliot ló gbàá nímọ̀ràn láti máa ṣiṣé eré ìtàgé ní Nàìjíríà.[6] Ó dé sí ìlú Èkó níbi tí ó ti kọ́kọ́ ṣe eré kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Spellbound ní ọdún 2009 kí ó tó tún kópa nínu eré In the Cupboard ní ọdún 2011.[7][8]

Ní ọdún 2012, ó tún kó ipa kékeré kan nínu eré Weekend Getaway.[9] Lẹ́hìn kíkópa nínu fíìmù ti 2012 náà, ó dá iṣé eré ṣíṣe rẹ̀ dúró fún ìgbà díẹ̀ láti le ráyẹ̀ tún tẹ̀síwájú nínu ẹ̀kọ́ rẹ̀. Ní ọdún 2014, ó padà sídi iṣẹ́ fíìmù rẹ̀ nígbà tí ó kópa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Oasis.[10][11] Ní ọdún tí ó tẹ̀le, ó kópa nínu àwọn eré tí àkọ́lé wọn ń ṣe Damaged Petal, Red Card àti Open Marriage.[12]

Ní ọdún 2017, ó kó ipa olú-ẹ̀dá-ìtàn nínu eré Our Dirty Little Secret.[13] Ní ọdún kan náà, ó tún kópa nínu àwọn eré bíi Philip, Polycarp, The Incredible Father àti Pebbles of Love.[14] Ó ṣe agbéréjáde fún ìgbà àkọ́kọ́ rẹ̀ pẹ̀lú eré tí àkólé rẹ̀ jẹ́ The Therapist's Therapy.[15] Ní ọdún 2018, ó kópa olú-ẹ̀dá-ìtàn gẹ́gẹ́ bi Valerie nínu fíìmù kan tí Eniola Badmus ṣe táa pe àkọ́lé rẹ̀ ní Karma, bẹ́ẹ̀ ló tún kópa gẹ́gẹ́ bi Kẹ́mi Alẹ́ṣinlọ́yẹ́ nínu eré Ayo Makun kan tí a pe àkọ́lé rẹ̀ ní Merry Men: The Real Yoruba Demons.[16][17][18]

Ní ọjọ Kẹẹ̀dọ́gbọ́n Oṣù Kaàrún Ọdun 2017, Meurer ṣe àtúnṣe sí èrọ omi tí ó wà láàrin ọjà ní ìlú Udu, Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà.[19][20] Ó tún ti fi owó fún aláboyún kan ní ilé-ìwòsàn 3-H Clinic and Maternity tó wà ní ìlú Warri, Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà.[21][22]

Àkójọ àwọn eré rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn sinimá àgbéléwò rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Àkọ́lé Ipa
2009 Spellbound
2011 In the Cupboard
2012 Weekend Getaway
2015 Damaged Petal Nneka
2015 Red Card Kachi
2015 Open Marriage Becky
2016 My Sister And I
2017 Pebbles of Love Vanessa
2017 Our Dirty Little Secret Anita
2017 The Incredible Father Susan
2018 Merry Men: The Real Yoruba Demons Kemi Alesinloye
2018 Karma Valerie
2019 Accidental Affair Jenny
2020 Circle of Sinners Betty
TBA Table of Mendagger

Àwọn eré tẹlifíṣọ̀nù rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Àkọ́lé Ipa Àwọn àkọsílẹ̀
Ọdun 2014 Oasis Kaylah Lead role
2017 Philip and Polycarp Monica Main role

Àwọn ìyẹ́sí rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Ayẹyẹ Ẹ̀ka Èsì ìtọ́kasí
2017 City People Movie Awards Most Promising Actress of the Year (English) Wọ́n Yàán [23]
La Mode Green Special Recognition Award Gbàá [24]
2016 Nigeria Goodwill Ambassador Awards Next Rated Actress Gbaa [25]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Tonto Dikeh’s ex, Churchill declares love for Rosy Meurer". P.M. News. 15 February 2020. Retrieved 15 May 2020. 
  2. Ogbeche, Danielle (19 January 2017). "Lady accused of having sex with Tonto Dikeh’s husband blasts critics". Daily Post Nigeria. https://dailypost.ng/2017/01/19/lady-accused-sex-tonto-dikehs-husband-blasts-critics-video. Retrieved 15 May 2020. 
  3. Abraham, Anthony Ada; Nwagu, Linda (4 March 2018). "Nigeria: Top 10 Young Actresses to Look Out for in 2018". AllAfrica.com. Archived from the original on 5 March 2018. https://web.archive.org/web/20180305083717/https://allafrica.com/stories/201803050057.html. Retrieved 15 May 2020. 
  4. "‘Merry Men’ Back On Another Mission". This Day Newspaper. 14 December 2019. Retrieved 15 May 2020. 
  5. "Rosaline Meurer bags ‘indigenous Woman award’". Vanguard Newspaper. 12 July 2019. Retrieved 15 May 2020. 
  6. "I got more jobs, money after Tonto Dikeh’s marriage crisis allegations – Rosaline Meurer". The Punch Newspaper. 8 April 2018. Retrieved 15 May 2020. 
  7. "Spellbound". Modern Ghana. 23 March 2011. Retrieved 15 May 2020. 
  8. "Skeletons in their closet - ‘In the cupboard’ film review". Daily Post Nigeria. 14 September 2012. https://dailypost.ng/2012/09/14/skeletons-closet-in-cupboard-film-review. Retrieved 15 May 2020. 
  9. "Film review: ‘Weekend Getaway’ gathers all the stars, but has no idea what to do with them". YNaija. 5 May 2013. https://ynaija.com/film-review-weekend-getaway-gathers-all-the-stars-but-has-no-idea-what-to-do-with-them. Retrieved 15 May 2020. 
  10. "'At 26 I have achieved what some of you can never achieve'- Rosy Meurer tells age doubters". Lailas News. 7 July 2018. Archived from the original on 13 April 2021. Retrieved 15 May 2020. 
  11. Onuorah, Vivian (19 February 2017). "“I Didn't Break TONTO DIKEH’s Marriage, Ask Her”--ROSALINE MEURER". City People Magazine. Retrieved 15 May 2020. 
  12. Boulor, Ahmed (19 January 2017). "Lady accused of dating Tonto Dikeh’s husband cries out (Video)". Ripples Nigeria. https://www.ripplesnigeria.com/lady-accused-dating-tonto-dikehs-husband-cries-video. Retrieved 15 May 2020. 
  13. "Society doesn’t allow Nigerian women to be romantic – Daniel Lloyd". Vanguard Newspaper. 24 September 2017. Retrieved 15 May 2020. 
  14. "#BNMovieFeature: WATCH IK Ogbonna, Daniel Lloyd, Rosaline Meurer, Stan Nze in "Pebbles of Love"". BellaNaija. 11 August 2019. https://www.bellanaija.com/2019/08/bnmoviefeature-watch-ik-ogbonna-daniel-lloyd-rosaline-meurer-stan-nze-in-pebbles-of-love. Retrieved 15 May 2020. 
  15. Nathaniel, Nathan (16 September 2017). "Actress Rosaline Meurer Joins League Of Movie Producers". The Nigerian Voice. Retrieved 15 May 2020. 
  16. McCahill, Mike (7 December 2018). "Merry Men: The Real Yoruba Demons review – cheerful comedy, lost in translation, Film". The Guardian. https://www.theguardian.com/film/2018/dec/07/merry-men-the-real-yoruba-demons-review. Retrieved 15 May 2020. 
  17. Efe, Obiomah (30 September 2018). "‘Merry Men: The Real Yoruba Demons’ is amoral". flickchat. https://flickchat.tv/merry-men-the-real-yoruba-demons-is-amoral. Retrieved 15 May 2020. 
  18. Onuorah, Vivian (19 February 2017). "“I Didn't Break TONTO DIKEH’s Marriage, Ask Her”--ROSALINE MEURER". City People Magazine. Retrieved 15 May 2020. 
  19. "Actress Rosaline Meurer Commissions Water Project". This Day Newspaper. 16 July 2017. Retrieved 15 May 2020. 
  20. Nathaniel, Nathan (10 July 2017). "Actress, Rosaline Meurer Gives Life To Udu Community As She Commissions New Water Project". The Nigerian Voice. Retrieved 15 May 2020. 
  21. Onuoha, Chris (28 May 2017). "Nollywood actress Rosaline Meurer donates cash to pregnant women". Vanguard Newspaper. Retrieved 15 May 2020. 
  22. Adebayo, Tireni (28 May 2017). "Nollywood actress Rosaline Meurer donates cash to pregnant women". Kemi Filani News. Retrieved 15 May 2020. 
  23. Omaku, Josephine (12 September 2017). "City People Movie Awards: and the Nominees are…". Ghafla!. Retrieved 15 May 2020. 
  24. Nathaniel, Nathan (10 July 2017). "Rosaline Meurer Bags Special Award for ambassadorial support for mother and child". The Nigerian Voice. Retrieved 15 May 2020. 
  25. "Nigeria: Kudos!!! Pretty Nollywood Star, Roseline Meurer Nominated for Nigeria Goodwill Ambassador Awards 2016". AllAfrica.com. 16 November 2016. Archived from the original on 18 November 2016. https://web.archive.org/web/20161118124349/http://allafrica.com/stories/201611170058.html. Retrieved 15 May 2020.