Solomon Ọlámilékan Adéọlá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Solomon Ọlámilékan Adéọlá
Sínétọ̀ fún Apá Ìwọ̀ oòrùn Ìpínlẹ̀ Èkó
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
June 6, 2011
Serving with Olúrẹ̀mí Tinúbú and Gbenga Bareehu Ashafa
AsíwájúGàníyù Ọláńrewájú Solomon
Vice-Chairman of the
Senate Committee on Communications
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
September 17, 2015
AsíwájúGilbert Nnaji
Honourable of the House of Representatives
In office
2011–2015
AsíwájúEmmanuel Oyeyemi Adedeji
Arọ́pòOluwafemi Adebanjo
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Solomon Ọlámilékan Adéọlá

Oṣù Kẹjọ 10, 1969 (1969-08-10) (ọmọ ọdún 54)
Lagos, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress
(Àwọn) olólùfẹ́Tèmítọ́pẹ́ Adéọlá
Alma materRufus Giwa Polytechnic
ProfessionAccountant
Politician
Websiteyayiadeola.com

Solomon Ọlámilékan Adéọlá tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Yáyì ni wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹwàá ọdún 1969 (August 10, 1969),[1] jẹ́ Onímọ̀ Ìṣirò àti Aṣòfin-àgbà nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó ń ṣojú apá ìwọ̀ oòrùn Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó ti fìgbà kan jẹ́ ọmọ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣojú-ṣòfin Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà kí ó tó di Sínétọ̀. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Association of Accounting Technicians (AAT).[2][3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named bio
  2. Lagos West: Adeola Aka Yayi Make History Winning Senate Seat. Thenigerianvoice.com (2015-03-31). Retrieved on 2016-07-30.
  3. Yayi wins Lagos West senate seat – The Nation Nigeria. Thenationonlineng.net (2015-03-31). Retrieved on 2016-07-30.