Solomon Ọlámilékan Adéọlá
Ìrísí
Solomon Ọlámilékan Adéọlá | |
---|---|
Sínétọ̀ fún Apá Ìwọ̀ oòrùn Ìpínlẹ̀ Èkó | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga June 6, 2011 Serving with Olúrẹ̀mí Tinúbú and Gbenga Bareehu Ashafa | |
Asíwájú | Gàníyù Ọláńrewájú Solomon |
Vice-Chairman of the Senate Committee on Communications | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga September 17, 2015 | |
Asíwájú | Gilbert Nnaji |
Honourable of the House of Representatives | |
In office 2011–2015 | |
Asíwájú | Emmanuel Oyeyemi Adedeji |
Arọ́pò | Oluwafemi Adebanjo |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Solomon Ọlámilékan Adéọlá 10 Oṣù Kẹjọ 1969 Lagos, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Tèmítọ́pẹ́ Adéọlá |
Alma mater | Rufus Giwa Polytechnic |
Profession | Accountant Politician |
Website | yayiadeola.com |
Solomon Ọlámilékan Adéọlá tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Yáyì ni wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹwàá ọdún 1969 (August 10, 1969),[1] jẹ́ Onímọ̀ Ìṣirò àti Aṣòfin-àgbà nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó ń ṣojú apá ìwọ̀ oòrùn Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó ti fìgbà kan jẹ́ ọmọ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣojú-ṣòfin Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà kí ó tó di Sínétọ̀. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Association of Accounting Technicians (AAT).[2][3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedbio
- ↑ Lagos West: Adeola Aka Yayi Make History Winning Senate Seat. Thenigerianvoice.com (2015-03-31). Retrieved on 2016-07-30.
- ↑ Yayi wins Lagos West senate seat – The Nation Nigeria. Thenationonlineng.net (2015-03-31). Retrieved on 2016-07-30.