Temilade Openiyi
Temilade Ọpeniyi ni wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 1995. Orúkọ tí àwọn ènìyàn mọ̀ ọ́ sí jùlọ ni Tems.[1] Ó jẹ́ akọrin ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà, oǹkọ̀wé orin àti o ǹṣe àwo orin.
Tems | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Temilade Openiyi[2] 11 Oṣù Kẹfà 1995 Lagos, Nigeria |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2018 - present |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments | Vocals |
Labels | Leading Vibe LTD |
Associated acts | |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé e rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Temilade Ọpeniyi ni wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 1995 ní Ipinle Eko, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìyá rẹ jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà nígbà tí bàbá rẹ jẹ́ ọmọ ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì. Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n bí Tems ni àwọn ẹbí rẹ lọ sí orílẹ̀-èdè gẹ̀ẹ́sì. Nígbà tí Tems pé ọmọ ọdún márùn ún ni ìyá àti bàbá rẹ pínyà. Ó padà sí l̀lúpéjú kí ó tó di wípé ó wá lọ sí Lẹkki lẹ́yìn naa Àjáh.[3] Nígbà tí Tems wà ní ilé-ẹ̀kọ́ ni olùkọ́ rẹ tí ó ńkọ ní ẹ̀kọ́ orin ti kọ́kọ́ ṣe àkíyèsi rẹ. Tems kọ́ nípa dùrù títẹ̀, ó sì tún kọ́ orin kíkọ pẹ̀lú gìtá ẹ̀gbọ́n rẹ.[4]
Iṣẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2018 ó ṣe ìgbàsílẹ̀ àkójọpọ̀ orin tirẹ̀ tí ó pè ní Mr Rebel.[5] Ní oṣù kẹjọ ọdún 2019, Tems ṣe àgbéjáde àwo orin kan, Gbiyanju Me.[6] Eléyì í di ìlúmọ̀ọ́ká tí ó fi jẹ́ wípé àwọn ènìyàn tí wọ́n ń wò ó lori ẹ̀rọ ayélujára ti YouTube lọ́wọ́lọ́wọ́ báyì í ju miliọnu 5.6 lọ. Ní ọdún 2020, DJ Edu yàn án gẹ́gẹ́ bí i ọ̀kan nínú “àwọn òṣèré mẹ́wàá tí òun yí ò wò” ní ọdún na.[7] Ní ọdún kanna yí ni akọrin ọmọ ilẹ̀ Améríkà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Khalid gbà á láti darapọ̀ mọ́ òun àti Davido ẹlẹgbẹ́ rẹ tí í ṣe ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà lórí Afrobeats remix ti Mọ Iye Rẹ̀.[8] Iṣẹ́ rẹ tí ó pè ní "single Damages from her For Broken Ears EP di ìlú mọ̀ ọ́ ká òmíràn lẹ́yìn "single Try Me" tí ó ṣe. Orin yi ni ó wà ní ipele kẹfà lórí ìgbékalẹ̀ tuntun ti "Turn Table Top 50" (ìwé àpẹrẹ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan) àti wípé àwọn tí wọ́n ǹ wó ó lórí ẹ̀rọ ayélujára ti YouTube tó miliọnu 2.7. Ní ọdún 2020, ìfọwọ́sowọ́pọ̀ rẹ pẹ̀lú Wizkid lórí orin wọn, Essence jẹ́ kí ó wà ní ìpele ìkínní lórí BBC 1Xtra Airplay Chart[9] láti bí í ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù kínní ọdún 2021.[10]
Ní oṣù Kejìlá ọdún 2020, Tems àti òṣèré ẹlẹgbẹ́ rẹ tí ó tún jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Omah Lay ni wọ́n mú ní orílẹ̀-èdè Uganda, ní àkókò tí wọ́n lọ síbẹ̀ fún iṣẹ́ orin kíkọ, fún ẹ̀sùn pé wọn kò tẹ̀lé àwọn òfin tí ó rọ̀ mọ́ ààbò lórí àrùn COVID-19. Lẹ́hìn na ni wọ́n tú wọn sílẹ̀ tí wọ́n sì fagilé gbogbo ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn wọ́n.[11]
Àwòrán ìwòye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn kékèèké
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọlé | Àwọn àwo-orin |
---|---|---|
2018 | "Mr Rebel"[12] | Non-album single |
2019 | "Looku Looku"[13] | |
"Try Me" | ||
2020 | "These Days"[14] | |
"Damages" | For Broken Ears |
EPs
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkọlé | Àwọn àlàyé àwo-orin | Ìwé-ẹ̀rí |
---|---|---|
For Broken Ears |
|
Àwọn ẹ̀bùn àti àwọn yíyàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Ìṣẹ̀lẹ̀ | Ẹ̀bùn | Olùgba ẹ̀bùn | Èsì | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2019 | The Headies | Best Vocal Performance (Female) | "Mr Rebel" | Wọ́n pèé | [15] |
Best Alternative Song | Wọ́n pèé | ||||
2020 | The Headies | Next Rated | "Omah Lay" | Wọ́n pèé | [16] |
The Future Awards Africa | Prize for Music | Wọ́n pèé | [17] | ||
2021 | BET Awards | Best New International Act | Wọ́n pèé | [18][19] | |
MTV Africa Music Award | Best Breakthrough Act | Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ | [20] | ||
Net Honours | Most Played Alternative Song | "Damages" | Gbàá | [21] | |
All Africa Music Awards | Best Female Artist in Western Africa | Herself | Wọ́n pèé | [22][23][24] | |
Best African Collaboration | "Essence"
(Wizkid featuring Tems) |
Gbàá | |||
Song of the Year | Gbàá | ||||
Best Artist, Duo or Group in African RnB & Soul | Wọ́n pèé | ||||
"Damages" | Wọ́n pèé | ||||
Breakout Artist of the Year | Herself | Wọ́n pèé | |||
African Entertainment Awards USA | Best Female Artist | Gbàá | [25] | ||
Artist of the Year | Wọ́n pèé | ||||
Best Female Artist – Central/West Africa | Wọ́n pèé | ||||
Best Collaboration | "Essence"
(Wizkid featuring Tems) |
Gbàá | |||
Best Video | Gbàá | ||||
Song of the Year | Gbàá | ||||
MTV Europe Music Awards | Best African Act | Herself | Wọ́n pèé | [26] | |
Soul Train Music Awards | Best Collaboration | "Essence"
(Wizkid featuring Tems) |
Gbàá | [27] | |
Video of the Year | Wọ́n pèé | ||||
Song of the Year | Wọ́n pèé | ||||
The Ashford & Simpson Songwriter's Award | Wọ́n pèé | ||||
Best New Artist | Herself | Wọ́n pèé | |||
Afro X Digitals Awards | Pop Song of the Year (Female) | "Damages" | Àdàkọ:Win | [28] | |
The Beatz Awards | Songwriter of the Year | Herself for "Damages" | Wọ́n pèé | ||
2022 | Grammy Awards | Best Global Music Performance | "Essence"
(Wizkid featuring Tems) |
Wọ́n pèé | [29][30] |
NAACP Image Awards | Outstanding New Artist | Herself | Wọ́n pèé | [31] | |
Outstanding Music Video/Visual Album | "Essence"
(Wizkid featuring Tems) |
Gbàá | |||
Outstanding International Song | Gbàá | ||||
Nickelodeon Kids Choice Award | Favorite Global Music Star | Herself | Wọ́n pèé | [32] | |
The Headies | Best Vocal Performance (Female) | Herself for "Essence" | Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ | [33] | |
Best Collaboration | "Essence"
(Wizkid featuring Tems) |
Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ | |||
Best R&B Album | w:If Orange Was a Place | Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ | |||
Best Female Artiste | Herself | Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ | |||
BET Awards | Best New Artist | Wọ́n pèé | [34][35][36] | ||
Best International Act | Gbàá | ||||
Best Collaboration | "Essence"
(Wizkid featuring Tems) |
Gbàá |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Tariemi, Oreoritse (May 9, 2022). "Tems Becomes First Nigerian Artist To Debut No. 1 On Billboard Hot 100". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on May 16, 2022. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ "Singer Tems". Daily Trust. April 2, 2022. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ Laketu, Adedayo (2020-03-09). "The sweet, arresting harmonies of Nigeria’s Tems". The FADER. Retrieved 2021-04-16.
- ↑ Okare, Fisayo (2018-10-23). "Native Exclusive: How Tems Triumphs after "Mr Rebel"". The Native. Retrieved 2021-04-16.
- ↑ Okare, Fisayo (2018-10-23). "Native Exclusive: How Tems Triumphs after "Mr Rebel"". The Native. Retrieved 2021-04-16.
- ↑ Obi, Ify (2020-02-06). "Interview: Tems Is On a Mission to Take Over". OkayAfrica. Retrieved 2021-04-16.
- ↑ "Rema". OkayAfrica. 2020-02-06. Retrieved 2021-04-16.
- ↑ Samanga, Rufaro (2020-04-23). "Khalid Recruits Davido and Tems on New Single 'Know Your Worth (Remix)'". OkayAfrica. Retrieved 2021-04-16.
- ↑ "BBC 1Xtra Airplay Chart". The UK Radio Airplay Chart. Archived from the original on 2021-01-20. Retrieved 2021-04-16.
- ↑ "The Essence of Wizkid and Tems". Mp3Chord. 2021-04-10. Archived from the original on 2021-04-10. Retrieved 2021-04-16.
- ↑ "BebeCool: Tems accuse Uganda musician of making police arrest her and Omah Lay". BBC News Pidgin. 2020-12-19. Retrieved 2021-04-16.
- ↑ "Burna Boy, Davido, Teni, others get nominated for 2019 Headies [FULL LIST]". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-12.
- ↑ "Lady Donli 'Corner' feat. VanJess & The Cavemen". OkayAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-12. Retrieved 2020-02-12.
- ↑ "Tems - These Days". Notjustok (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-05-19. Archived from the original on 2020-06-14. Retrieved 2020-05-21.
- ↑ "Headies 2019: Here are all the winners at the 13th edition of music award". Pulse Nigeria. 20 October 2019. Retrieved 26 October 2019.
- ↑ "Live Update: All The Winners At The Headies 2020". The Guardian. 2021-02-21. Retrieved 2021-02-25.
- ↑ Obi-Young, Otosirieze (9 November 2020). "The Future Awards Africa 2020 Announces 145 Nominees in 20 Categories". Folio. Retrieved 16 June 2021.
- ↑ "2021 BET Awards: Full list of winners and nominees". CBS News. Retrieved 29 June 2021.
- ↑ Unamaka, Sampson (8 June 2021). "Nigerian singer Tems clinches 2021 BET Awards nomination". The Nation (Nigeria). Retrieved 9 June 2021.
- ↑ "See the Full List of 2021 #MTVMAMA Nominees including Tems, Omah Lay and Rema!". BellaNaija. 9 December 2020. Retrieved 16 June 2021.
- ↑ Mofijesusewa, Samuel (20 June 2021). "NET Honours 2021: "Damages" by Tems Named Most Played Alternative Song". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 21 July 2021.
- ↑ "All Africa Music Awards 2021: All the nominees". Music in Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 23 September 2021. Retrieved 27 September 2021.
- ↑ Obey, Yinka (25 November 2021). "AFRIMA 2021: Wizkid, Iba One win big, Manjeru makes history, full list of winner". Legit.ng – Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-11-26.
- ↑ "2021 AFRIMA Awards – See Full Winners List". tooXclusive (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 22 November 2021. Retrieved 2021-11-26.
- ↑ "Wizkid wins five awards at 2021 AEAUSA". The Nation Newspaper. 28 December 2021. Retrieved 28 December 2021.
- ↑ "Wizkid Wins Best African Act At MTV EMA 2021". The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 15 November 2021. Archived from the original on 2021-11-23. Retrieved 2021-11-23.
- ↑ "H.E.R. Is Top Nominee at 2021 Soul Train Awards; Maxwell & Ashanti to Receive Special Awards: Exclusive". Billboard. Retrieved 2 November 2021.
- ↑ "Afrodigital Award winners". AfroxDigital.com.
- ↑ "Wizkid, Burnaboy, oda Nigerian artists wey dey 2022 Grammy nomination". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/media-59394925.
- ↑ "2022 Grammy Awards: Wizkid, Femi Kuti, Burna Boy, Tems nominated". Vanguard News. 3 April 2022. Retrieved 4 April 2022.
- ↑ Spivey, Kemberlie (19 January 2022). "2022 NAACP Image Awards Nominations: The Full List". Forbes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-01-20.
- ↑ "Kids' Choice Awards Nominees: See Who's Up for Favorite Actor, Actress and Movie | Entertainment Tonight". www.etonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-07.
- ↑ "2022 Headies Full List Nominees". Vanguard News. 24 May 2022. Retrieved 25 May 2022.
- ↑ "BET Awards 2022 Nominees Announced". BET (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2 June 2022.
- ↑ "Tems wins Best International Act at BET Awards 2022". Vanguard News. June 27, 2022. Retrieved June 27, 2022.
- ↑ "BET Awards: Tems wins 2022 Best International Act". Punch Newspapers. June 27, 2022. Retrieved June 27, 2022.