The virgin
Olùkọ̀wé | Bayo Adebowale |
---|---|
Country | Nigeria |
Language | English |
Series | Egret romance & thrillers |
Genre | Novel |
Publisher | Bounty press and Paperback Publishers, Ibadan |
Publication date | 1985 |
Media type | Print (Hardback & Paperback) |
Pages | 116 pp |
ISBN | Àdàkọ:ISBNT |
OCLC | 633633330 |
The Virgin jẹ́ íwé tì o tájù ńì ọ̀dùń 1985 tì Báyọ̀ Adebowale je ákọ̀wè ná.Bayo Adebowale.[1][2] Íwé tì wọ̀ń ṣè átẹ̀jádè rẹ̀ ńì ọ̀dùń 1985,sọ̀ ńìpá wàálá tì óbìńrìń káń dójùkọ̀ ńì ìlú rẹ̀ ńìpá kì ómù íkáń lárà áwọ̀ń ókùńrìń mẹ́tá káń tìwọ̀ń dà èńù ífẹ̀ sì ,tí wọ̀ń mọ̀ pè ótìjábàlé tábì kí áwọ̀ń tù áṣírì ẹ́ ńí álè ìgbèyáwò rẹ́.[3][4] Scholar Wendy Griswold ṣe afihan iwe yi gẹ́gẹ̀ bí "ìgbèsì aye abule". "Íwé yì tùńṣè áfìháń áṣá átì íṣè ìgbèsì áyé áwọ̀ń órìlé-èdé Ńáìjìrìá tì ó sí dábì ákọ̀wè káń tí óńjẹ̀ Chinua Achebe.[1]
Ágbékálẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Obìńrìń káń tì ó wá látì ílẹ́ Yoruba ńì ábùlè káń, tì òsí tí fẹ́ ọ́dẹ̀ káń látì ábùlè íbomíráń . Bẹ́ńá ńí árákùńrìkáń tì óńbọ̀ látì ígbòrò dá èńù ífékọ̀ bẹ́ńá ńì ótùń fí ọ́wọ̀ rá gbògbó árá ẹ́. Árábìńrìń yì durò tìtì dì ọ́jọ̀ álẹ̀ ígbè ìyáwò rẹ́.
Background
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Adebowale jẹ́ ẹ́gbẹ̀ "third generation" tì àwọ̀ń àkọ̀wè órile-ede Ńáìjìrìá tí wọ̀ń má ṣè áfìháń áwọ̀ń nkan igbalode tì óyátọ̀si awon akowe aye atijọ̀.[5] Pùpọ̀ ńìńù áwọ̀ń íṣẹ̀ Adebowale ,óma sonipa awọ̀ń árá abùlè. .[1] The Virgin jẹ́ nkan lara awon iṣẹ́ naa. Adebowale Ni igbagbo pe awọ̀ń akowe orile-ede Naijiria kìwọ̀ń màṣè afihan Awa ati íṣé órìlè edé Ńáìjìrìá.[1]
Átùńṣè íwé ńáà si ere óńìṣè
Tunde Kelani tùń íwé yì ṣè tì ósì sọ̀dì ere óńíṣè tí ó sí dárì ére 95-minute film version, tì o ai pè ákọ̀lé rẹ́ ńì tit The Narrow Path,Ti òjade Ni ọ̀jọ́ ke ji la óṣù kárùń ọ̀dùń 2012. Èré ṣè áfìháń Sola Asedeko, Ayo Badmus átìKhabirat Kafidipe . Beautiful Nubia.[6] jẹ́ enì tí ókọ̀ órìń ńáà. Mumin Wale Kelani átì Frank Efe Patrick Ni wọ̀ń ṣè átùńṣè rẹ́., ti Abiola Atanda[7] jẹ́ ẹ́ńì tì óf7ùń wọ̀ń ńí ẹ́ṣọ̀ átì àṣọ̀. Ere je otìtọ̀ si iwe naa laye yọ́ ikan kan kuro ńìbẹ́ bayi ẹ́jẹ̀ pe afihan àṣá Ati ise wa ninu ere naa.[8]
Awọ̀ń itọ̀kásì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 Griswold, Wendy (19 June 2000). Bearing Witness: Readers, Writers, and the Novel in Nigeria - Wendy Griswold - Google Books. ISBN 0691058296. https://books.google.com/books?id=kf7_x8yz430C&q=The+virgin,+Bayo+Adebowale+novel&pg=PA124. Retrieved 2015-04-04.
- ↑ "Pragmatic Features of Nigerian English : A Case Study of Selected Poems of Bayo Adebowale" (PDF). Unilorin.edu.ng. Archived from the original (PDF) on 2015-04-10. Retrieved 2015-04-04.
- ↑ "When pages flip to inhabit screens - Weekly Trust". Dailytrust.com.ng. 2014-06-28. Retrieved 2015-04-04.
- ↑ Ehling, Holger G.; Mutius, Claus-Peter Holste-von (2001). No Condition Is Permanent: Nigerian Writing and the Struggle for Democracy - Holger Ehling, Claus-Peter Holste-von Mutius - Google Books. ISBN 9042014865. https://books.google.com/books?id=31mP-0eAhxYC&q=The+Virgin+by+Bayo+adebowale&pg=PA189. Retrieved 2015-04-04.
- ↑ Dalley, Hamish (Winter 2013). "The Idea of "Third Generation Nigerian Literature": Conceptualizing Historical Change and Territorial Affiliation in the Contemporary Nigerian Novel". Research in African Literatures 44 (4): 15–34. doi:10.2979/reseafrilite.44.4.15.
- ↑ "Chemistry graduate behind winning sound tracks". Punchng.com. 2013-06-12. Archived from the original on 2015-04-10. Retrieved 2015-04-04.
- ↑ "The Narrow Path (2006)". Internet Movie Database. Retrieved 4 April 2015.
- ↑ Kerr, David; Banham, Martin; Gibbs, James; Plastow, Jane; Osofisan, Femi (2011). Media and Performance - Google Books. ISBN 9781847010384. https://books.google.com/books?id=dFzMC-nHqi4C&q=The+Virgin+by+Bayo+adebowale&pg=PA30. Retrieved 2015-04-04.