Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 17 Oṣù Kẹ̀wá
Appearance
- 1806 – Ikúadánilóró pa asíwájú Ìjídìde àwọn ará Háítì, Ọbalúayé Jacques I ilẹ̀ Háítì nítorí ìjọba ìnira rẹ̀.
- 1912 – Bulgaria, Greece àti Serbia gbógun di Ottoman Empire, èyí dà wọ́n pọ̀ mọ́ Montenegro nínú Ogun àwọn ará Balkan Àkọ́kọ́.
- 1966 – Botswana àti Lesotho darapọ̀ mọ́ Àgbájọ àwọn Orílẹ̀-èdè.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1956 – Mae Jemison, American astronaut and physician
- 1968 – Ziggy Marley, Jamaican musician
- 1969 – Wyclef Jean, Haitian singer
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1806 – Jean-Jacques Dessalines, Haitian independence leader (b. 1758)
- 1849 – Frédéric Chopin, Polish musician and composer (b. 1810)
- 1887 – Gustav Kirchhoff, German physicist (b. 1824)