Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 20 Oṣù Kọkànlá
Appearance
- 1695 – Zumbi, the last of the leaders of Quilombo dos Palmares in early Brazil, was executed.
- 1994 – Ìjọba Angola àti àwọn akógun UNITA tọwọ́bọ̀wé sí Prótókólù Lusaka ní Zambia, láti fòpin sí ogun abẹ́lẹ́ lẹ́yìn ọdún 19.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1889 – Edwin Hubble, American astronomer (al. 1953)
- 1923 - Nadine Gordimer, South African writer, Nobel laureate
- 1957 - Goodluck Jonathan, olóṣèlú àti Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1695 – Zumbi, ara Brasil (b. 1655)
- 1910 - Leo Tolstoy, olùkọ̀wé ará Rọ́síà (ib. 1828)
- 1975 – Francisco Franco, Olórí Orílẹ̀-èdè Spéìn (1936–1975) (ib. 1892)