Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 5 Oṣù Kejì
Ìrísí
- 1885 – Ọba Leopold 2k ilẹ̀ Bẹ́ljíọ̀m sọ Kóngò di ohun àdáni rẹ̀.
- 1958 – Gamel Abdel Nasser (fọ́tò) jẹ́ dídálórúkọ láti di ààrẹ àkọ́kọ́ Orílẹ̀òmìnira Árábù Aparapọ̀.
- 1962 – Ààrẹ Fránsì Charles De Gaulle gbà pé kí Algeria di alómìnira.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1914 – Alan Lloyd Hodgkin, ẹlẹ́bùn Nobel (al. 1998)
- 1915 – Robert Hofstadter, ẹlẹ́bùn Nobel (al. 1990)
- 1919 – Andreas Papandreou, olóṣèlú ọmọ Grííkì (al. 1996)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1790 – William Cullen, aṣekẹ́místrì ará Skọ́tlándì (ib. 1710)
- 1881 – Thomas Carlyle, olùkọ̀wé ará Skọ́tlándì (ib. 1795)
- 2005 – Gnassingbe Eyadema, Ààrẹ ilẹ̀ Tógò (ib. 1937)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |