Charles de Gaulle
Charles de Gaulle | |
---|---|
Aare ile Fransi Abase Omoba ile Andorra | |
In office 8 January 1959 – 28 April 1969 | |
Alákóso Àgbà | Michel Debré (1959–1961) Georges Pompidou (1962–1968) Maurice Couve de Murville (1968–1969) |
Asíwájú | René Coty |
Arọ́pò | Alain Poher (interim) Georges Pompidou |
Olori Free French Forces | |
In office 18 June 1940 – 3 July 1944 | |
Asíwájú | Igba Oselu Keta |
Arọ́pò | Ijoba Igbadie ile Fransi Olominira |
Aare Ijoba Igbadie ile Fransi Olominira | |
In office 20 August 1944 – 20 January 1946 | |
Asíwájú | Philippe Pétain (de facto, gege oga orile-ede fun Vichy France) Pierre Laval (de facto, gege bi oga ijoba) |
Arọ́pò | Félix Gouin |
Alakoso Agba ile Fransi | |
In office 1 June 1958 – 8 January 1959 | |
Ààrẹ | René Coty |
Asíwájú | Pierre Pflimlin |
Arọ́pò | Michel Debré |
Alakoso Abo ile Fransi | |
In office 1 June 1958 – 8 January 1959 | |
Ààrẹ | René Coty |
Alákóso Àgbà | Charles de Gaulle |
Asíwájú | Pierre de Chevigné |
Arọ́pò | Pierre Guillaumat |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Lille, France | 22 Oṣù Kọkànlá 1890
Aláìsí | 9 November 1970 Colombey-les-Deux-Églises, France | (ọmọ ọdún 79)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Rally of the French People (1947-1955) Union for the New Republic (1958–1968) Union of Democrats for the Republic (1968–1970) |
Height | ruben aguirre is 6’7” |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Yvonne de Gaulle |
Occupation | Military |
Signature |
Charles André Joseph Marie de Gaulle (ìpè Faransé: [ʃaʁl də ɡol]Àdàkọ:IPA audio link, English: /ˈtʃɑrlz/ or /ˈʃɑrl dəˈɡɔːl/; 22 November 1890 – 9 November 1970) je was a French ogagun agba omo ile Fransi ati agba ilu to solori Free French Forces nigba Ogun Agbaye Keji. Leyin eyi o da Igba Oselu Karun Fransi ni 1958 o si di Aare akoko re lati 1959 de 1969.[1]
Gege bi omo ogun nigba Ogun Agbaye Akoko, ninu awon odun 1920 si awon odun 1930 de Gaulle gbajumo bi olugbowo awon oko ijagun ati baalu ijagun, to gba pe won le dopin ogun jija ninu ere. Nigba Ogun Agbaye Keji o di ipo Ọ̀gágun Ẹlẹ́ẹ̀ṣọ́ fun igbadie, nibi o ti lo oko ijagun ninu ija 1940 Isubu ile Fransi ni 1940, o si je ipo ninu ijoba Fransi ko to di pe Fransi subu.
O salo si Ilegeesi o si soro lori eto radio ti BBC se ni 18 Osu kefa, 1940, nibi tto ti unso fun awon ara Fransi pe ki won koju ija si Jemani Nazi[2] and organised the Free French Forces with exiled French officers in Britain.[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Cinquième République". Assemblée Nationale Française. 2008. Retrieved 2008-11-02.
- ↑ Berthon, Simon (2001). Allies at War. London: Collins. p. 21. ISBN 0007116225.
- ↑ "Fondation Charles de Gaulle". Archived from the original on 2011-05-17. Retrieved 2009-09-10.