Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 6 Oṣù Kejì
Ìrísí

- 1820 – Àwọn akórawọ̀lú ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà 86 àkọ́kọ́ tí Ẹgbẹ́ Ìsọdàmúsìn Amẹ́ríkà ṣonígbọ̀wọ́ bẹ̀rẹ̀ ìtẹ̀dó ní ibi tí Liberia wà lóòní.
- 1942 – Ogun Àgbáyé 2k: Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan gbógun ti Thailand.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1911 – Ronald Reagan, Ààrẹ 40k Àwọn Ìpínlẹ̀ Aparapọ̀ (al. 2004)
- 1945 – Bob Marley (fọ́tò), olórin ará Jamáíkà (al. 1981)
- 1950 – Natalie Cole, olórin ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1916 – Rubén Darío, olùkọ̀wé ará Nicaragua (ib. 1867)
- 1964 – Emilio Aguinaldo, Ọgágun àti Ààrẹ ará Filipínì (ib. 1869)
- 1993 – Arthur Ashe, agbá tẹnís ará Amẹ́ríkà (ib. 1943)
![]() | Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |