Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 9 Oṣù Kẹfà
Ìrísí
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1843 – Bertha von Suttner, olùkọ̀wé ará Austria (al. 1914)
- 1875 – Henry Hallett Dale, apoògùn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1968)
- 1961 – Michael J. Fox, òṣeré ará Kánádà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 68 – Nero, Ọbalúayé Rómù (ib. 37)
- 1870 – Charles Dickens, olùkòwé ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (ib. 1812)
- 1974 – Miguel Ángel Asturias, olùkọ̀wé ará Guatẹ́málà (ib. 1899)