Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 8 Oṣù Kẹfà
Appearance
- 1949 – George Orwell gbé ìwé itàn àròkọ tó ún jẹ́ Nineteen Eighty-Four jáde.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1921 – Suharto, Ààrẹ ilẹ̀ Indonésíà (al. 2008)
- 1935 – Molade Okoya-Thomas, oníṣòwò àti ọlọ́rẹ ará Nàìjíríà (al. 2015)
- 1954 – Mudashiru Lawal, agbábọ́ọ́lù-ẹlẹ́sẹ̀ àrá Nàìjíríà (al. 1991)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 632 – Muhammad, òjísẹ́ ẹ̀sìn Ìmàle (ib. 570)
- 1998 – Sani Abacha, Ààrẹ ìjọba ológun ilẹ̀ Nàìjíríà (ib. 1943)
- 2009 – Omar Bongo, Ààrẹ ilẹ̀ Gàbọ̀nù (ib. 1935)