Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 10 Oṣù Kẹfà
Ìrísí
- 1980 – African National Congress ní orílẹ̀-èdè Gúúsù Áfríkà ṣe ìkéde ìpè láti bẹ̀rẹ̀ rògbòdìyàn látọwọ́ olórí wọn Nelson Mandela tó wà lẹ́wọ̀n nígbànáà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1895 – Hattie McDaniel (fọ́tò), òṣeré ará Amẹ́ríkà (al. 1952)
- 1915 – Saul Bellow, olùkòwé ará Amẹ́ríkà (al. 2005)
- 1949 – John Sentamu, bísọ́bù-àgbà ìlú York ọmọ ilẹ̀ Ùgándà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 323 BC – Alẹksándà Ẹni Nínlá, ọba àwọn ará Makẹdóníà (ib. 356 SK)
- 1940 – Marcus Garvey, alákitiyan ará Jamáíkà (b. 1887)
- 2004 – Ray Charles, akorin ará Amẹ́ríkà