Jump to content

Wikipedia:Account creator

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Information page Àdàkọ:Nutshell

Olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ fún àwùjọ àwọn oníṣẹ́ Wikipẹ́día (accountcreator user group) ni ó tún ní ẹ̀tọ́ sí irinṣẹ́ yí láti dá àkọpamọ́ àwọn oníṣẹ́ tuntun tí wọ́n bá nífẹ̀ẹ́ sí dídá orúkọ oníṣẹ́.

Àwọn ohun tí olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ lè ṣe[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn àkọpamọ́ tí a dá lábẹ́ user group nípasẹ̀ olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ yóò lè lo àwọn irinṣẹ́ tí ó wà lábẹ́ ìdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ láti ṣe:

  • Ní ànfàní láti dá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ tí ó ju mẹ́fà lọ[1] láàrin wákàtí ẹ́rìnlélógún ó ní ànfàní láti lo irinṣẹ́ pàtàkì yí láti fi Special:dá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ tàbí kí ó lo irinṣẹ́ mìíràn bi (the noratelimit flag).
  • Ó Ní ànfàní láti ṣe "àyídá-yidà" kí ó sì dá orúkọ oníṣẹ́ kan tí fara jọ orúkọ oníṣẹ́ tí ó ti wà tẹ́lẹ̀ nípa lílo ìṣẹ́dá orúkọ oníṣẹ́ afara-jọra (the override-antispoof flag).
  • Ó ní ànfàní láti ṣàyípadà kí ó sì dá orúkọ oníṣẹ́ tí wọ́n ti pagidí tí ó sì ti wọ "ìwé ẹ̀kọ̀" (blacklist) nípa lílo àká ìwé ẹ̀kọ̀ (the tboverride-account flag).
  1. àdínkù lè bá ànfàní yí bí olùdá àkọpamọ́ náà bá ń ṣi agbára rẹ̀ lò.

Láti di olùdá àkọpamọ́ oníṣẹ́[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Láti ní àṣẹ àsíá ìjẹ́ olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́, o gbúdọ̀ jẹ́ ẹni tí ṣiṣẹ́ déédé tó sì ní ìrírí tó gbòòrò wo ìlànà àti ìtọ́ni (ACC), tí wọn yóò sì ṣàfihan rẹ̀ lórí pátákó ajúwe Wikimedia Foundation. Oníṣẹ́ tí ó bá fìfẹ́ hàn sí àsíá àṣẹ yí ti gbúdọ̀ gbìyànjú láti dá àkọpa.ọ́ orúkọ oníṣẹ́ tí ó ti tó mẹ́fà ṣáájú kí ó bèrè fún ìyọnda àṣẹ ìlò irinṣẹ́ ìdá àkọpamó orúkọ oníṣẹ́ pẹ̀lú ìtàkùn yí Wikipedia:Requests for permissions/Olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́.

Àwọn kókó pàtàkì mìíràn[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àṣẹ àsíá ìdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ ni a ma ń fún àwọn oníṣẹ́ Wikipẹ́día tó bá peregedé tí wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ olóòrè-kóòrè lórí pẹ́lú nìkan ni wọ́n ní ànfàní láti lo àwọn irinṣẹ́ pàtàkì tí ó wà lábẹ́ àṣẹ ìdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ ní ìlànà tiwọn. Ẹ̀wẹ̀, Yorùbá Wikipẹ́día ti ní àwọn àtòjọ àwọn oníṣẹ́ 1 wọ̀nyí tí wọn ti gba àṣẹ tí wọ́n sì gbé àsíá ìdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ lábẹ́ orúkọ wọn gbogbo.