Jump to content

Wikipedia:Request an account

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Welcome to the request an account page
Àkékúrús:
WP:ACC
WP:RAC
WP:RQAC
WP:ACCT
WP:REQUESTACCOUNT

This page is for requesting a Wikipedia account be created for you in the event that you are unable to create one yourself using the signup page.


This is typically due to:

  • Having trouble completing the required CAPTCHA image verification step.
  • Choosing a username that is too similar to an existing username (an account creator can approve similar usernames if certain criteria are met).


Láti yàgò fún dídá orúkọ oníṣẹ́ àbadì lórí wikipedia nípa lílo ẹ̀rọ tàbí ìlànà àkọọ́lẹ̀, Wikipedia ma ń lo àwòrán ajẹ́rìí tí a ń pè ní (called a CAPTCHA) láti ri dájú pé ènìyàn gidi ni ẹni tí ó forúkọ sílẹ̀ kíí ṣe kọ̀mpútà.

Bí o bá yi gbìyànjú láti láti dá orúkọ oníṣẹ́ ṣùgbọ́n ti o ní ìpènijà pẹ̀lú àwòrán ajẹ́rìí CAPTCHA, ó ṣe é ṣe kí o ma lo browser tí kò bójú mu tí kò sì fara mọ́ àwọn àwòrán gidi, tàbí kí o ṣàmúlò orúkọ oníṣẹ́ tí ó fara pẹ́ orúkọ oníṣẹ́ ti wà lọ́wọ́ ẹnìkan tẹ́lẹ̀ rí. O lè you can bèrè fún orúkọ oníṣẹ́ tuntun.

Your username must represent you as an individual person
  • Usernames that only contain the names of companies, organizations, websites, musical groups or bands, teams, or creative groups are not allowed
  • Usernames that imply that your account is for shared use, or usernames that only describe a role, title, or position within an organization that can be represented or held by different people are not allowed

Your username must be truthful and appropriate

  • Usernames that are offensive, profane, violent, threatening, sexually explicit, libelous, or disruptive are not allowed
  • Usernames that are deliberately deceptive, confusing, long, similar to other accounts or users, or try to impersonate or falsely represent yourself as someone else are not allowed
  • Usernames that imply the intent to troll, vandalize, disrupt, harass, advertise, spam, or use Wikipedia for purposes that it is not created for are not allowed

Láti bèrè fún orúkọ oníṣẹ́ rẹ lo ìgbésẹ̀ 'Ìtọrọ fún orúkó oníṣẹ́', jọ̀wọ́ àwọn ìtọ́ni ìsàlẹ̀ yí síwájú si.

Ṣáájú kí o tó bẹ̀rẹ̀

[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Ṣàgbéyẹ̀wò Ìlànà ìforúkọ sílẹ̀ kí o sì gbọ yé, ọ̀pọ̀ ìforúkó sílẹ̀ fún krúkọ oníṣẹ́ ni ó lòdì sí ìlànà àti ìtọ́ni Wikipedia ni wọn kìí di mímú ṣẹ tàbí gbìgbà wọlé.
  • Rántí wìpéorúkọ oníṣẹ́ ẹyọ Wikipedia kan ṣoṣo lo lẹ́tọ̀ọ́ sí.[1] O gbọ́dọ̀ jẹ́wọ́ gbogbo àwọn orúkọ onoíṣẹ́ tí o bá ti ní tẹ́lẹ̀ nípa lílo àlàfo 'Àríwísí'. Èyí kéyí orúkọ oníṣẹ́ tí ẹ bá bèèrè fún tí ó bá ṣàfihàn fìdí-múlẹ̀ wípé ẹ ti ní orúkọ oníṣẹ́ tẹ́lẹ̀ lórí wikipedia ni a kò ní gbà wọlé. Orúkọ oníṣẹ́ tì a bá kẹ́fín dí wípé oníbèérè rẹ̀ fẹ́ lòó fún ohun àìtọ́ ibùlà (gẹ́gẹ́ bí ibi tí ó kè fo àwọn àkọsílẹ̀ rẹ̀ pamọ́ sí,sápamọ́s, tàbí sá fún ìdádúró tàbí ìjìyà, tàbí kí ó da ǹkan rú) niba kò ní gbà wọlé. Láfikún, bí wọ́n bá ṣàfisún àwọn ìgbìyàjú rẹ́, ó lè mú ìjìyà mìíràn dání.
  • A fẹ́ kí o mọ̀ wípé àyè yí kìíṣe ibi tí

a ti léṣèbéèrè fún pípa orúkọ oníṣẹ kan rẹ́ tàbí láti gba orúkọ oníṣẹ́ rẹ tẹ́lẹ̀ padà. Bí o bá ti gbàgbé ọ̀rọ̀ ìpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ rẹ tí o kò sì forúkọ e-mail kan kan forúkọ sílẹ̀, ájẹ́ pé ọ̀rọ̀ ìpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ rẹ kò níṣe é gbà padà nìyẹn. Ohun kan tí o lè ṣe ni wípé kí o forúkọ oníṣẹ́ mìíràn síslẹ̀, kí o sì bèrè fún ìfirọ́pò orúkọ oníṣẹ́ rétẹ́lẹ̀.

  • Forúkọ oníṣẹ́ sílẹ̀ pẹ̀lú àdírẹ́sì e-mail bí o bá _e eléyìí, yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ káti tètè gba ọ̀rọ̀ ìpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ rẹ padà nígbàkúùgbà tí o bá gbàgbé rẹ̀ nírọ̀rùn. if you do not have one.

Bí o bá ṣe tán láti bẹ̀rẹ̀

[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Wo inú àpò e-mail rẹ fún àwọn àyípadà tuntun tí ó níṣe peú ìforúkọ sílẹ̀ rẹ́.
    • Bí wọ́n bá ti buwọ́lu ìforúkọ sílẹ̀ rẹ tí wọ́n sì ti gbà ọ́ wọlé, wà á rí àtẹ̀jíṣẹ́ gbà nínú e-mail rẹ pẹ̀lú Àdàkọ:NonSpamEmail pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ rẹ tí o fi sílẹ̀ àti ọ̀rọ̀ ìpamọ́ rẹ.O lè Wọlé, níbi tí wọn yóọ́ ti pọ́n ní dandan fún ọ láti yí ọ̀rọ̀ ìpamọ́ rẹ padà.
    • Bí o bá ní ìpèpníjà nípa ìbéèrè rẹ wọn yóò fi àtẹ̀jíṣẹ́ ránṣésí ọ lórì e-mail rẹ tí yóò ṣàlàyé ohunbtì ó fàá tí orúkọ oníṣẹ́ rẹ́ kò fi lè di mímúṣẹ. Ẹ káàbọ̀ kí ìoele ìṣèbéèrè fún ìforúkọ dílẹ̀ tuntun nípa fífi orúkọ oníṣẹ̀ tí ẹlòmíràn kòì tíì lò rí.

Ṣé o kò rí àtẹ̀jíṣẹ́ orúkọ oníṣẹ́ rẹ lórí e meèlì rẹ?

[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọjọ́ tí okùforúkọ sílẹ̀ bá ti forúkọ sílẹ̀ ní a má ń gba orúkọ oníṣẹ́ wọlé. Ẹ̀wẹ̀, a kò lérò wípé ó yẹ kí ìgbésẹ̀ ìgbani wọlé yìí ó tó ọjọ méjì tàbí mẹ́ta, bí ìforúkọ̀ sílẹ̀ bá ṣe pọ̀ tó fún ìgbéyẹ̀wò. Kìí sábàà ṣẹlẹ̀ lọ́pọ̀ ìgbà kí olùforúkọ sílẹ̀ má tètè rí àtẹ̀jíṣẹ́ rẹ́, bóyá nípa(ìṣe ségesège ìtàkùn, tàbí kí ìforúkọ sílẹ̀ àwọn oníṣẹ́ ó pọ̀ jáǹtì-rẹrẹ). Nígbà míràn ẹ̀wẹ̀, fífàtẹ̀0jíṣẹ́ olùforúkọ sílẹ̀blè lò tó àìmọye ọ̀sẹ̀ kí a tó mú ìbéère wọn ṣẹ. Kìí ṣe wípé a kò ní mu ṣẹ, àmọ́ kí wọ́n mú sùúrù, ìbéèrè wọn yóò di mímúṣẹ dandan láìpẹ́.

Ṣáájú kí o tó forúkọ sílẹ̀ tàbí ṣèbéèrè nípa fíforúkọ rẹ sílẹ̀:

  • Wo àpò e-meelì ọlọ́pọ̀-èrò"spam" rẹ. Lọ́pọ̀ ìgbà, àwọn àtẹ̀jíṣẹ́ meelì má ń sábà àwọn ọlọ́pọ̀-èrò yí.
  • Ribdájú wípé o kò fi àpò e meelì rẹ́ wípé kí ó pa àtẹ̀jíṣẹ́ tintun rẹ́ tàbí kí ó ṣàtúnṣe sí wọ́n.Yẹ gbogbo àwọn àpò àti ìsọmọgbè wọn wò kí o sì ṣàwárí Àdàkọ:NonSpamEmail bóyá ó ti wọlé.
  • Ǹjẹ́ o forúkọ sílẹ̀ nípa lílo àdírẹ́sì Gmail? Àtẹ̀jíṣẹ́ rẹ ti lè wọlé, àmọ́ tí irinṣẹ́ tí ó má ǹ sẹ́ àwọn àtẹ̀jíṣẹ́ tuntun tí ó pín sí ọ̀nà márùún ó ti sẹ́e sí àyè kan (pàá pàá jùlọ ìpele "Social" tàbí "Promotions"). Yẹ àwọn ìpele wọ̀yí wò fún ìdáni lójú.
  • Gbìyànjú láti gba orúkọ oníṣẹ́ rẹ padà, ìyé ẹ̀yí tí o fi sílẹ̀. Bí a bá gba ìforúkọ sílẹ̀ rẹ wọlé, àmọ́ tí oò kàn rí èsì e meelì rè tí yóò sọ ọ̀rọ̀ ìpamọ́ rẹ fún ọlásán ni, o láǹfàní láti ṣàyípadà ọ̀rọ̀ ìfipamọ́ rẹ tí Wikiledia yóò fibránṣẹ́ síọ nìgbà tí o bá ti tẹ̀lé ìlànà bí o ṣe kè yí ọ̀rọ̀ ìpamọ́ rẹ padà.

Ǹjẹ́ o tibṣe tán láti bẹ̀rẹ̀?

  • Tí o bá fẹ́ ìrànlọ́wọ́ síwájú si lórí bí o ṣelè forúkọ sílẹ̀, jọ̀wọ́ lo Ìforúkọ sílẹ̀.
  • Bí o bá fẹ́ di Oníṣẹ́ tí ólẹ́tọ̀ọ́ forúkọ ẹlòmíràn sílẹ̀, ṣàmúlò ojú-ewé Atọ́nà.
  1. Minus the exceptions that allow for the legitimate creation and use of alternative accounts. See Wikipedia's sock puppetry policy for more information.