Jump to content

Wikipedia:Ìtọrọ àwọn àṣẹ àti irinṣẹ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àwọn Ìbéèrè àti Ìtọrọ àṣẹ[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

À ń bójúto níbí[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwùjọ àwọn olóòtú[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ (Óyá tọrọWo àwọn tí wọ́n tọrọ): Àsíá dídá àkọpamọ́ oníṣẹ́ ni a ma ń fún èyíkéyí oníṣẹ́ tí ó bá ń ṣiṣẹ nígbà gbogbo lórí request an account process|bèrè fún àṣẹ ìdá àkọpamọ́ oníṣẹ́. Níní àṣẹ yí ma ń fi òpin sí àì má lè dá orúkọ oníṣẹ́ púpọ̀ lásìkò kan náà láàrin wákàtí mẹ́rìnlélógún (24 hrs). Ó tún jẹ́ kí a lè dá orúkọ oníṣẹ́ mìíràn tí ó fara jọ orúkọ oníṣẹ́ tí ó ti wà tẹ́lẹ̀. Àṣẹ ìlè dá orúkọ oníṣẹ́ ni a lè fún oníṣẹ́ tí ó bá béèrè fun tí a sì lè gbàá kúrò lọ́wọ́ rẹ̀ láì ṣe ìfilọ̀ fún irúfẹ́ oníṣẹ́ bẹ́ẹ̀ nígbà tí kò bá lòó fún ìdá àkọpamọ́ oníṣẹ́ titun.
  • Irinṣẹ́ Ìdápadà (Óyá tọrọWo àwọn tí wọ́n tọrọ): Irinṣẹ́ ìdápadà ni ó ma ń fún oníṣẹ́ tí ó bá ni ní ànfàní láti yọ ìbàjẹ́ kan tí ẹnkẹ́ni bá hù láti ba àyọka tàbí ààtò àyọkà jẹ́, yálà oní tọ̀hún mọ̀ómọ̀ tàbí ó ṣe àṣìṣe tí ó lè ba nka jẹ́ lórí Wikipẹ́día kúrò kíá láì rosẹ̀ nípa lílo irinsẹ́ da padà. Oníṣẹ́ tí kò bá nímọ̀ nípa bí a ti ń gbé ìgbésẹ̀ láti gbógun ti ìwà bíba àyọka jẹ́, bóyá kò lóye nípa rẹ̀ ni tàbí kò mọ ìyàtọ̀ nípa àyọka tó dára àti èyí tí kò dára kò ní lẹ́tọ̀ọ́ sí àṣẹ yí. Kódà oníṣẹ́ tí wọ́n bá ń kẹ́fín sí wípé ó ń ba àwọn àyọka jẹ́ lọ́pọ̀ ìgbà tí wọ́n sì ń yiṣẹ́ rẹ̀ padà kò ní lẹ́tọ̀ọ́ sí àṣẹ yí rárá. Fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ alàyé nípa lílò, àsìkò wo ni a lè lòó àti tani ó lẹ́tọ̀ọ́ sí irinṣẹ́ da padà (rollback) Wikipedia:Rollback. Fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ alàyé ní ìgbẹ́sẹ̀ lílò irinṣẹ́ yí, ẹ gbabí wọlé.

Títọrọ ìyànda láti ṣàyọkúrò[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bí o ba wù ọ́ láti yọ èyíkéyí àṣẹ tàbí ìyànda ìṣàyọkúrò rẹ tí o ti ní tẹ́lẹ̀ kúrò yàtọ̀ sí àṣẹ bí (alákòóso tàbí olùdarí àgbà), o lè kàn sí àwọn alámùójútó

Pèpéle yí kò sí fún ìṣàgbéyẹ̀wò ẹ̀tọ́ oníṣẹ́ kọkan, bí o bá wá ṣàkíyèsí wípé oníṣẹ́ kan tọ́ sí kí ó ní èyíkéyìí nínú àwọn àṣẹ àti irinṣẹ́ wọ̀nyí, o lè tọ́ka rẹ̀ lórí ìtọ́ka pàjáwìrì.

Oníìbéèrè[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Láti bèrè ìyọ̀nda àṣẹ, tẹ" fi ìbéèrè mi ránṣẹ́" kí o sì fi ìdí tí ó fi fẹ́ gba ìyọ̀nda àṣẹ tí o ń béèrè fún.

Ẹnikẹ́ni nínú àwọn oníṣẹ́ Wikipẹ́día ló lè ṣe àríwísí sí ìbéèrè fún àṣẹ rẹ.

Alámòójútó[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn alámójútó nìkan ló ní àṣe láti fún àwọn olóòtú tí o bá pé òṣùwọn ní àṣẹ ìdá àkọpamọ́ àwọn Oníṣẹ́ titun (Account Creator) àti àṣẹ fún Ìdápadà (Rollback). Wọ́n lè fún irú ẹni bẹ́ẹ̀ fún ìgbà díẹ̀ tàbí fún ìgbà pípẹ́.

Current requests[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Irinṣẹ́ Ìdápadà (Rollback)[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wikipedia:PERM/Subpage

Oníṣe:Àpẹẹrẹ[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oníṣe:Deborahjay[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Hello User:Deborahjay, could you please provide a rationale for requesting this right. Thank you. T CellsTalk 17:27, 8 Oṣù Kẹrin 2020 (UTC)
Rationale: I'm an experienced WP editor (43K edits across 69 projects). Since joining this project in June 2018, I've made >1.9K edits to the Yoruba WP. I'm active daily, regularly checking Recent changes (Àwọn àtúnṣe tuntun), so identify vandalism within hours of occurrence. I have Rollback rights on the Simple English Wikipedia and learned to use the function there. I request the ability to perform Rollback here rather than simply Undo when there's a sequence of bad unacceptable edits. -- Deborahjay (ọ̀rọ̀) 22:11, 8 Oṣù Kẹrin 2020 (UTC)
 Done. T CellsTalk 10:03, 9 Oṣù Kẹrin 2020 (UTC)

Olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ (ACC)[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wikipedia:PERM/Subpage

Oníṣe:Àpẹẹrẹ[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]