Yemi Ajibade
Omoba Yẹmí Ajíbádé | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Adéyẹmí Ọlánrewájú Goodman Ajíbádé 28 Oṣù Keje 1929 Ìlá Ọ̀ràngún, Ìpínlẹ̀ Ọ̀Ṣun, Nàìjíríà |
Aláìsí | 24 January 2013 London, UK | (ọmọ ọdún 83)
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Olùkọ̀tàn, òṣèré orí-ìtàgé àti olùdarí eré |
Notable work | Parcel Post Waiting for Hannibal |
Yẹmí Ajíbádé tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Keje ọdún 1929. [1][2] – 24 January 2013[3]), Ẹni tí wọ́n mọ̀ sí Yẹmí Ajíbádé, Yẹmí Goodman Ajíbádé tàbí Adéyẹmí Ajíbádé, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, adarí-eré, ati olùkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ń gbé ní orílẹ̀-èdè England láti ọdún 1950. Ó ti kó ipa ribiribi nínú eré orí-ìtàgé nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì pàá pàá jùlọ Canon of Black drama. Ó ti kọ orísiríṣi eré, ó sì ti darí ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré pẹ̀lú lórí ẹ̀rọamóhùnmáwòrá, orí rédíò àti sinimá.
Ìgbé ayé rẹ̀ àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀=
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Adéyẹmí Ọlánrewájú Goodman Ajíbádé ni wọ́n bí ní ìdílé Ọba ní ìlú Ìlá Ọ̀ràngún ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun [4]Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ti Girama ti ìlú Abẹ́òkúta tí ó sì tú kẹ́kọ̀ọ́ nílé ẹ̀kọ́ Kennington College of Law and Commerce ní ìlú London ní ọdún 1955. Ó tún kàwé ní ilé-ẹ̀kọ́ ti The Actors' Workshop ní ọdún 1960, ó sì tún kẹ́kọ́ ní London Film school ní ọdún 1966 àti London School of Gilm Technique ní ọdún. [1][5]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nígbà tí ó wà ní ìlú UK, Ajíbádé kópa nínú eré orí rédíò fún ilé -iṣè ìgbóhùn-sáfẹ́gẹ́ BBC African Service. [6] Wọ́n ṣàfihàn Ajíbádé gẹ́gẹ́ bí ẹni tí yóò gòkè agbà nínú eré ìtàgé lọ́jọ́ iwájú ní ilẹ̀ Adúláwọ̀[4] Òun ati olùkópa mìíràn bíi: Yulisa Amadu Maddy, Leslie Palmer, Eddie Tagoe, Karene Wallace, Basil Wanzira, and Elvania Zirimu, àti àwọn mìíràn tí wọ́n jọ ń kópa nínú eré ọlọ́kan-ò-jọ̀kan lóríbíi: ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ Lindsay Barrett Blackblast! ní ọdún 1973 fún isẹ́ pàtàkì ti BBC Two arts Full House ìtàn tí ó jẹ́ ti olùkọ̀tàn ará ikẹ̀ India.[7][8][9] Iṣẹ́ Ajíbádé ṣàfihan akitiyan rẹ̀ lórí iṣẹ́ rẹ̀ ń já fíkán pàá pàá jùlọ lórí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán, lára àwọn eré tí ó tún ń ṣe ni: Armchair Theatre "The Chocolate Tree" by Andrew Sinclair ní ọdún 1963,òun àti Earl Cameron pẹ̀lú Peter McEnery),[10] Danger Man ní ọdún (1965), Dixon of Dock Green ní ọdún (1968), Douglas Botting The Black Safari ní ọdún (1972), The Fosters ní ọdún (1976), Prisoners of Conscience ní ọdún (1981), àti Silent Witness ní ọdún(1996), and work on the stage – for instance, in "Plays Umbrella". Ó tún kópa nínú àwọn eré orí-ìtàgé sinimá mìíràn pẹ̀lú.[11][12][13][14] àti ní Lorraine Hansberry Les Blancs (Royal Exchange Theatre ní ọdún 2001.[15] Ó tún kópa gẹ́gẹ́ bí Terence Fisher nínú eré The Devil Rides Out ní ọdún 1968, gẹ́gẹ́ bí Monte Hellman nínú Shatter ní ọdún 1974 [16] gẹ́gẹ́ bí Hanif Kureshi nínú eré London Kills Me ní ọdún 1991 àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. [17] Ní ọdún 1966, Ajíbádé darí àwọn òṣèré bíi tirẹ̀ nínú àpérò World Festival of Black Arts ní ìlú Dakar, tí ó jẹ́ olú-ìlú fún orílẹ̀-èdè Senegal, láti dqrí eré ònkọ̀tàn Obi Egbuna tí ó pè ní Wind Versus Polygamy; ní 2nd World Black Arts Festival ní Ìpínlẹ̀ Èkó
Àwọn ìwé eré oníṣẹ́ tí ó ti kọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Award (unproduced)[18]
- Behind the Mountain – first produced: Unibadan Masques, 1977
- Fingers Only – first produced: The Factory, Battersea Arts, London (Black Theatre Co-operative, directed by Mustapha Matura), 1982. As Lagos, Yes Lagos, BBC Radio, 1971.
- A Long Way from Home – first produced: Tricycle Theatre, London (directed by Nicolas Kent), 1991
- Mokai – first produced: Unibadan Masques, 1979
- Parcel Post – first produced: Royal Court Theatre, London, 16 March 1976[18]
- Waiting for Hannibal – first produced: Drill Hall, London (Black Theatre Co-operative, directed by Ajibade with Burt Caesar), 1986
- Para Ginto (black version of Peer Gynt)[18] – Tricycle Theatre, 1995
Àwọn àṣàyàn ìwé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Fingers Only and A Man Names Mokai. Ibadan: Y-Book Drama series, 2001, 142 pp. ISBN 978-2659-88-6
- Parcel Post and Behind the Mountain. Ibadan: Y-Book Drama series, 2001, 147 pp. ISBN 978-2659-89-4
- Gwyneth Henderson and Cosmo Pieterse (eds), Nine African Plays for Radio (includes "Lagos, Yes Lagos" by Yemi Ajibade), Heinemann Educational Books, AWS, 127, 1973.
Àwọn eré sinimé tí ó ti kópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- 1962: The Sword in the Web (TV Series) - Jean
- 1963: Suspense (TV Series) - Joshua
- 1963: Armchair Theatre (TV Series) - Jacob Jones
- 1964: Festival (TV Series) - Aide to Lichee
- 1964: Espionage (TV Series) - Sergeant
- 1965: The Wednesday Play (TV Series) - Rebel soldier / Man in pub
- 1965: Danger Man (TV Series) - Barman
- 1966: The Witches - Mark (uncredited)
- 1967: Theatre 625 (TV Series) - Tsilla Mamadou
- 1967: Thirty-Minute Theatre (TV Series) - Observer
- 1968: 30 Is a Dangerous Age, Cynthia - New Lodger (uncredited)
- 1968: The Devil Rides Out - African (uncredited)
- 1968: Dixon of Dock Green (TV Series) - Roger Bunda
- 1969: The Power Game (TV Series) - Premier of Malta
- 1970: Carry On Up the Jungle
- 1972: The Black Safari (TV Movie)
- 1973: Full House (TV Series) - Black Blast! cast member
- 1974: Shatter - Ansabi M'Goya / Dabula M'Goya
- 1976: Shades of Greene (TV Series) - 1st Head boy
- 1976: The Fosters (TV Series) - Mr. Fuller
- 1981: Prisoners of Conscience (TV Series) - Walter Sisulu
- 1987: Truckers (TV Series) - Watchman
- 1989: Behaving Badly (TV Mini-Series) - Church Elder
- 1991: Smack and Thistle (TV Movie) - Pedro
- 1991: London Kills Me - Tramp
- 1993: Rwendo (Short)
- 1995: Skin (Short) - Neville
- 2002: Dirty Pretty Things - Mini Cab Driver (as Ade-Yemi Ajibade)
- 2004: Exorcist: The Beginning - Turkana Shaman
- 2007: Silent Witness (TV Series) - Samson Moyo
- 2007: Flawless - Guinean Negotiatior (final film role)
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Africa Who's Who, London: Africa Journal Ltd, for Africa Books, 1981, p. 82.
- ↑ Later sources give his birth year as 1933.
- ↑ Yemi Ajibade Archived 5 November 2018 at the Wayback Machine. at Aveleyman.
- ↑ 4.0 4.1 "The African Scene", Negro Digest, October 1963, p. 32.
- ↑ Josanne Leonard, interview with Horace Ové, 5 October 2007[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́], Caribbean 360.
- ↑ Fiona Ledger, "History of African Performance", BBC World Service, African Performance 2007.
- ↑ Cast and credits, Full House (03/02/73), BFI.
- ↑ Full House 03/02/73, BFI.
- ↑ "Full House", Radio Times, Issue 2569, 1 February 1973, p. 15.
- ↑ Leonard White, Armchair Theatre: The Lost Years, Kelly Publications, 2003, p. 103.
- ↑ "Plays Umbrella", Riverside Studios, August 1980. Peter Gill, "Scrape Off the Black", 15 March 2012.
- ↑ Cast list in Nicholas Wright, Five Plays, Nick Hern Books, 2000, p. 81.
- ↑ Cast list in Nicholas Wright, The Custom of the Country, RSC Playtexts, London: Methuen, 1983, p. 26.
- ↑ Cast list in Nicholas Wright, Five Plays, London: Nick Hern Books, 2000, p. 149.
- ↑ Les Blancs, UK Theatre Web.
- ↑ Brad Stevens, Monte Hellman: His Life and Films, Jefferson, North Carolina: McFarland & Company, 2003, p. 96.
- ↑ Credits – London Kills Me"[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́], in Kenneth C. Kaleta, Hanif Kureishi: Postcolonial Storyteller, University of Texas Press, 1998, p. 275.
- ↑ 18.0 18.1 18.2 "Yemi Ajibade at Dollee.com". Archived from the original on 24 December 2017. Retrieved 18 October 2020.
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Yemi Ajibade Archived 24 December 2017 at the Wayback Machine. at Dollee.com
- WorldCat.
- Records of the Black Theatre Co-operative – Nitro Theatre Company, The National Archives.
- "Yemi Ajibade"[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́], Black Plays Archive, National Theatre.
- Yemi Ajibade actor credits, Filmography at Cineplex.
- Pages with script errors
- Webarchive template wayback links
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from September 2023
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- Articles with dead external links from December 2023
- Male actors from Osun State
- Nigerian dramatists and playwrights
- Black British male actors
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1929
- Àwọn ọjọ́aláìsí ní 2013
- Yoruba male actors
- Yoruba dramatists and playwrights
- 20th-century Nigerian male actors
- Nigerian royalty
- Yoruba royalty
- Alumni of the London Film School
- University of Ibadan people
- British male dramatists and playwrights
- 20th-century British dramatists and playwrights
- Nigerian theatre directors
- Nigerian emigrants to the United Kingdom
- Black British writers
- 20th-century British male writers
- Nigerian princes