Zubby Michael
Zubby Micheal | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Azubuike Michael Egwu Anambra State |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Mass Communication, Nnamdi Azikiwe University |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Nnamdi Azikiwe University |
Iṣẹ́ | Actor movie producer. |
Gbajúmọ̀ fún | His role in Three Windows. |
Azubuike Michael Egwu tí a mọ̀ gẹ́gẹ́ bíi Zubby Michael jẹ́ òṣèré Nàìjíríà àti olùgbé eré jáde .[1][2] Ó jẹ́ mímọ̀ fún ipa tí ó kó nínú Three Windows, Royal Storm àti Professional Lady. Ìfarahàn rẹ̀ àkọ́kọ́ jẹ́ nínú eré tí a pe àkọlé rẹ̀ ní Missing Rib ṣùgbọ́n ó jẹ́ mímọ̀ nínú eré The Three Windows níbi tí ó ti kó ipa tó síwájú.[3]
Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Zubby jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Anambra State. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga Nnamdi Azikiwe University níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ mass communication.[4]
Ó bẹ̀rẹ̀ eré ìtàgé ní Yola, Ipinle Adamawa ní ìgbà èwe rẹ̀.[5] Eré àkọ́kọ́ tí ó ti farahàn jẹ́ nínú eré tí a pe àkọlé rẹ̀ ní Missing Rib ṣùgbọ́n ó gbajúmọ̀ fún ipa tó síwájú tí ó kó nínú The Three Windows. Zubby síì ti farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré míràn.[6][7]
Iṣẹ́ Òṣèlú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní 25 November 2019 a yan Zubby sínú ipò òṣèlú gẹ́gẹ́ bí agbani ní ìmọ̀ràn pàtàkì lórí ayélujára fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra State Gómìnà Willie Obiano.[8][9] Wọ́n fún-un ní ìwé èrí ìdánimọ̀ fún akitiyan rẹ̀ lórí ètò ìróni l'àgbára fún àwọn ọ̀dọ́ ti City Radio 89.7 FM ní ìpínlè Anambra.
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ àti èyí tí wọ́n yàn án fún
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àmì-ẹ̀yẹ fún iṣẹ́ òṣèré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Àbájáde |
---|---|---|---|
2019 | City People Movie Awards | Best Actor of the Year (Igbo)[10] | Wọ́n pèé |
City People Movie Awards | Best Actor of the Year (English)[11] | Wọ́n pèé | |
Nigeria Achievers Awards | Best Lead Actor of the Year (English)[12] | Wọ́n pèé | |
South South Achievers Awards (SSA)[13] | Male Actor of the Year | Wọ́n pèé | |
2018 | South East Entertainment Award | Movie icon of the year | Gbàá |
City People Movie Awards[14] | Best Actor Of The Year (English) | Wọ́n pèé | |
2015 | Nigerian Entertainment Award[15] | Actor of the Year (Indigenous Films) | Wọ́n pèé |
City People Movie Awards[16] | Best Supporting Actor of the Year (English) | Wọ́n pèé | |
2014 | City People Movie Awards[17] | Best New Actor of the Year (English) | Wọ́n pèé |
2011 | Best Of Nollywood Awards (BON)[18] | Most Promising Act (male) | Wọ́n pèé |
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ mìíràn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Àbájáde |
---|---|---|---|
2020 | South-East Beauty Pageant Organisation | Best Celebrity Politician of the Year | Won |
2019 | City People Movie Awards | Best Igbo Film of the Year (Eze ndi Ala)[10] | Nominated |
2018 | The Nigerian MSMEs & Achievers Awards | Nollywood Personality of the Year | Won |
Fún àwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Orúkọ ìwé-ìròyìn |
---|---|
2019 | A New Touch of Africa (spring/summer 2019 edition)[19] |
Àwọn ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Ibi ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò |
---|---|
2021 | KingsPrimeTV [20] |
2019 | BBC news Igbo[21] |
A New Touch of Africa[22] |
Àṣààyàn àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Orúkọ | Ojúṣe | Àwọn akópa | |
---|---|---|---|---|
2021 | Bloody Doings | Ugonna | Starring Jerry Amilo | |
2020 | Omoghetto:The Saga | Azaman | ||
Identical Twins | ||||
Bad Omen | ||||
Burial Battle | ||||
Audio Money | ||||
Egg of love | ||||
2019 | The Return of Dangote | |||
Our Father's Property | Ebuka | |||
Dying of Thirst | Uzor | |||
Blood Feud | Reuben | |||
Children obey your parents | Azubuike | |||
Hunchback Princess | Ugo | |||
Seed of Greatness | Agumba | |||
A Thousand War | Obidi | |||
G4 The Money Men | Obinwanne | |||
Flashback | Chris | Starring Rachael Okonkwo | ||
Seed of Deception | Chima | |||
Enemy of Progress | Uzondu | |||
Shameless Sisters | Starring Lizzy Gold | |||
Yahoo King | King Ezego | |||
Boy Makes Money | Uzodimma | |||
Son of No Man | Nnanna | |||
The Return of Eze Ndi Ala | Eze | Starring Ken Erics, Rachael Okonkwo | ||
Afraid to Fall | James | |||
Pains of the Orphan | Prince Chimaobi | |||
2018 | Throne of Terror | |||
Sound of Calamity | Prince Irudike | |||
Lack of Money | Joshua | |||
Hunted Bride | Prince Ahamefula | Starring Eve Esin | ||
Omenka | Prince Obieze Nnoruka | Starring Queen Nwokoye | ||
Yahoo Shrine | Jide | |||
Bastard Money | Lazarus | |||
Made in South | Edozie | |||
Anayo China | Anayo | |||
Wasted Authority | Collins | Starring Ngozi Ezeonu | ||
Youngest Wife | Festus | |||
The one man squad | Victor | |||
Mama | Starring Liz Benson | |||
2017 | Eze Ndi Ala in America | Eze | Starring Ken Erics, Rachael Okonkwo | |
The King of Vulture (Eze K'udene) | ||||
Mr Arrogant | Arinze | |||
The Return | Igwe Ufuma | Starring Chacha Eke | ||
War for love | Dennis | Starring Rachael Okonkwo | ||
Ozoemena Ozubulu | Ozoemena | |||
Adaure, My love | Izunna | Starring Rachael Okonkwo | ||
Sword of Justice | Prince Ogugua | Starring Ken Erics, Ngozi Ezeonu | ||
2016 | Family Matters (Akara Ayasago) | Tony | Starring Ebere Okaro | |
2015 | 1st Hit | Gallardo | Starring Nonso Diobi and Mayor Ofoegbu | |
The Promise | Izu | Starring Chacha Eke | ||
Abba | Chibueze | Starring Queen Nwokoye | ||
Okada 50 | Okada 50 | Starring Ebere Okaro | ||
Compound fools | Ossai | Starring Kenneth Okonkwo, Yul Edochie Queen Nwokoye and Funke Akindele | ||
My love, my mother's wish | Ikechukwu | Starring Rachael Okonkwo | ||
Settle Me | Agozie | Starring Ken Erics, Ngozi Ezeonu | ||
The Struggle | Alfred | Starring Kelvin Books Ikeduba |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "I nye Odumeje otito Chukwu, Chukwu eweere gị iwe – Zubby Michael" (in en-GB). 22 November 2019. https://www.bbc.com/igbo/afirika-50515749.
- ↑ "Zubby Michael: Check out photos of actor's newly completed mansion". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 26 September 2018. Retrieved 12 December 2019.
- ↑ "Tuface taught me humility – Zubby Michael, actor". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 17 February 2017. Retrieved 12 December 2019.
- ↑ "Nollywood Actor, Zubby Michzel, in Love With P Square's Little Sister Mary". Nigerian Voice. Retrieved 12 December 2019.
- ↑ "10 Nollywood Actors Who Started Out Well But Haven't Really Kicked On". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 January 2018. Retrieved 5 May 2019.
- ↑ "Tuface taught me humility – Zubby Michael, actor". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 17 February 2017. Retrieved 5 May 2019.
- ↑ "12 Rising And Promising Nollywood Actors". Archived from the original on 1 April 2019. Retrieved 5 May 2019.
- ↑ Alabi, Temitope (25 November 2019). "Obiano Appoints Actor Zubbby Michael As Special Adviser On Media". Information Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 12 December 2019.
- ↑ Nseyen, Nsikak (26 November 2019). "Nollywood actor, Zubby Micheal gets political appointment". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 12 December 2019.
- ↑ 10.0 10.1 Salami, Oluwadamilare (2019-10-04). "Nomination List for 2019 City People Movie Awards (Igbo)". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-29.
- ↑ Salami, Oluwadamilare (2019-10-04). "Nomination List for 2019 City People Movie Awards (English)". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-29.
- ↑ "Nigeria Achievers Awards/NWAA on Instagram: "Nomination Alert!! Dear highly esteemed nominee, this is to formally bring to your notice your nomination in this year's Nigeria Achievers…"". Instagram (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-29.
- ↑ "Nominnees 2019 – South South Achievers Awards" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 5 May 2019.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Reporter (8 September 2018). "Nominees For 2018 City People Movie Awards [Full List]". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 5 May 2019.
- ↑ "Music stars bag nominations for NEA Awards". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 12 June 2015. Archived from the original on 1 May 2019. Retrieved 5 May 2019.
- ↑ "Check Out The Full Nominee List Of City People Awards – Gistmania". www.gistmania.com. 7 December 2015. Retrieved 5 May 2019.
- ↑ Blog, Judith Audu (9 June 2014). "Judith Audu's Blog: City People Entertainment Awards 2014, Complete Movie Categories Nominees List...". Judith Audu's Blog. Retrieved 5 May 2019.
- ↑ Eribake, Akintayo (27 May 2011). "Ini Edo, Yemi Blaq to host BON awards". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 5 May 2019.
- ↑ "A New Touch of Africa". A New Touch of Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-29.
- ↑ "Zubby Michael "I Am Scared of Women" (Prime Talks on Kinsprimetv) - YouTube". www.youtube.com. Retrieved 2021-02-11.
- ↑ Gịnị na-afịọ nke Zubby Michael (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), retrieved 2019-12-29
- ↑ ANTOA Exclusive Interview with Actor Zubby Michael (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), retrieved 2019-12-29
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from September 2023
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- Living people
- Date of birth missing (living people)
- Nigerian male film actors
- Nigerian film producers
- Actors from Anambra State
- Nigerian actor-politicians
- Igbo male actors
- Nnamdi Azikiwe University alumni
- Nigerian politicians
- Year of birth missing (living people)