Jump to content

Kunle Afolayan: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ìlà 1: Ìlà 1:
'''{{PAGENAME}}''' (tí wọ́n bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1974) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Yorùbá, ní Ìgbómìnà láti [[ìpínlẹ̀ Kwara]] lórílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. Bàbá rẹ̀ ni gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò nígbà kan rí, ṣùgbọ́n tí ó ti di olóògbé,AmAdéyẹmí Josiah Afọláyan, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí [[Ade Love]]
'''{{PAGENAME}}''' (tí wọ́n bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1974) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Yorùbá, ní Ìgbómìnà láti [[ìpínlẹ̀ Kwara]] lórílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. Bàbá rẹ̀ ni gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò nígbà kan rí, ṣùgbọ́n tí ó ti di olóògbé,AmAdéyẹmí Josiah Afọláyan, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí [[Ade Love]]<ref name="Austine Media 2018">{{cite web | title=Kunle Afolayan Biography, History, Asset and Net Worth - Austine Media | website=Austine Media | date=2018-05-20 | url=https://austinemedia.com/kunle-afolayan-biography-and-net-worth/ | access-date=2019-12-09}}</ref> <ref name="Leadership Newspaper 2019">{{cite web | title=Kunle Afolayan | website=Leadership Newspaper | date=2019-04-07 | url=https://leadership.ng/2019/04/07/kunle-afolayan/ | access-date=2019-12-09}}</ref>


{{Infobox person
{{Infobox person

Àtúnyẹ̀wò ní 07:24, 9 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019

Kunle Afolayan (tí wọ́n bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1974) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Yorùbá, ní Ìgbómìnà láti ìpínlẹ̀ Kwara lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ ni gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò nígbà kan rí, ṣùgbọ́n tí ó ti di olóògbé,AmAdéyẹmí Josiah Afọláyan, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ade Love[1] [2]

Kunle Afolayan
Ọjọ́ìbí30 Oṣù Kẹ̀sán 1974 (1974-09-30) (ọmọ ọdún 50)[3]
Ebute Metta, Lagos, Lagos State, Nigeria
IbùgbéMagodo, Ikeja, Lagos State, Nigeria[4]
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actor, Director, Producer
Olólùfẹ́Tolu Afolayan
Àwọn ọmọ4
Parent(s)Adeyemi Josiah Afolayan (Ade Love - father)
Àwọn olùbátanMoji Afolayan (sister)
Gabriel Afolayan (brother)
Aremu Afolayan (brother)

Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀

Kúnlé jẹ́ ọmọ bíbí Ìgbómìnà pọ́ńbélé láti ìpínlẹ̀ Kwara gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú. Gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò àná ni bàbá rẹ̀ Ade Love. Kúnlé kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ìsúná ọ̀rọ̀-ajé. Ó ṣiṣẹ́ nílé ìfowópamọ́ fún ìgbà díẹ̀ kí ó tó dára pọ̀ mọ́ ìṣe sinimá àgbéléwò ṣíṣe lọ́dún 2015. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti ń kópa ní ìwọ̀nba kí ó tó di àkókò yìí. Kúnlé máa ń kópa nínú sinimá àgbéléwò lédè Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni sinimá-àgbéléwò tí ó ti kópa tó ṣòódó. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ sìn ni àmìn ẹ̀yẹ tí ó gbà gẹ́gẹ́ bí eléré tíátà.

Àwọn Ìtọ́kasí

  1. "Kunle Afolayan Biography, History, Asset and Net Worth - Austine Media". Austine Media. 2018-05-20. Retrieved 2019-12-09. 
  2. "Kunle Afolayan". Leadership Newspaper. 2019-04-07. Retrieved 2019-12-09. 
  3. "Its Kunle Afolayan’s birthday". The Nation. Archived from the original on 2014-10-07. Retrieved 24 October 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Kunle Afolayan Shows Off His New House In Magodo". Star Gist. Archived from the original on 2016-09-19. Retrieved 16 September 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)