Àtòjọ àwọn ọmọ ilé-ìgbìmọ̀ aṣojú-ṣòfin Nigeria ti ọdún 2023 sí 2027
Ìrísí
Wọ́n ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ilé-ìgbìmọ̀ àwọn aṣòfin kẹwàá lọ́jọ́ kẹtàlá oṣù kẹfà ọdún 2023. Àpapọ̀ gbogbo wọn jẹ́ 360. Lọ́jọ́ tí ṣe ìfilọ́lẹ̀ yìí, ẹgbẹ́-ọ̀ṣèlú All Progressive Congress ní ìjókòó ọmọ ẹgbẹ́ aṣojú-ṣòfin 162, Peoples Democratic Party ní 102, Labour Party ní 34, bẹ́ẹ̀ ni ẹgbẹ́-òṣèlú NNPP ní ìjókòó 18. APGA ní ìjókòó mẹ́rin; African Democratic Congress (ADC) àti Social Democratic Party ní ìjókòó méjì méjì; bẹ́ẹ̀ ni ẹgbẹ́ the YPP ní jíjókòó kan péré[1][2]. Lọ́jọ́ náà, ayé ìjókòó ẹni méjì ṣófo nítorí pé wọn kò tíì ṣètò ìdìbò wọn tán. Àjọ Independent National Electoral Commission, INEC sì kéde pé wọn yóò ṣètò láti ṣe àtúndì-ìbò ní àwọn ẹkùn-ìdìbò méjèèjì tí ayé wọn ṣì ṣófo
Ádárì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn olùdarí=
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orúkọ ipò | Ẹgbẹ́-òṣèlú | Onípò | Ipinlẹ̀ | Ẹkùn-ìdìbò | Láti | |
---|---|---|---|---|---|---|
Speaker of the House | APC | Tajudeen Abbas[3] | Kaduna | Zaria Federal Constituency | Kaduna I | 13 June 2023 |
Deputy Speaker of the House | APC | Benjamin Kalu[4] | Abia | Bende Federal Constituency | 2023 | 13 June 2023 |
Olùdarí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tó pọ̀ jùlọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orúkọ ipò | Ẹgbẹ́-òṣèlú | Ọmọ ẹgbẹ́ | Ìpínlẹ̀ | Ẹkùn ìdìbò | Láti |
---|---|---|---|---|---|
House Majority Leader | APC | Julius Ihonvbere [5] | Edo | Owan West | 4 July 2023 |
Deputy House Majority Leader | APC | Abdullahi Ibrahim Ali Halims[6] | Kogi | Ankpa, Omala and Olamaboro Federal Constituency | 4 July 2023 |
House Majority Whip | APC | Usman Bello kumo | Gombe | Akko Federal Constituency | 4 July 2023 |
Deputy House Majority Whip | APC | Adewunmi Onanuga[5] | Ogun | Remo Federal Constituency. | 4 July 2023 |
Olùdarí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tó kéré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orúkọ ipò | Ẹgbẹ́-òṣèlú | Ọmọ ẹgbẹ́ | Ìpínlẹ̀ | Ẹkùn ìdìbò | Láti |
---|---|---|---|---|---|
House Minority Leader | PDP | Kingsley Chinda[7] | Rivers | Obio/Akpor Federal Constituency | 4 July 2023 |
Deputy House Minority Leader | NNPP | Ali Madaki | Kano | Dala Federal Constituency | 4 July 2023 |
House Minority Whip | PDP | Ali Isa[8] | Gombe | Balanga/ Billiri constituency | 4 July 2023 |
Deputy House Minority Whip | LP | George Ozodinobi | Anambra | Dunukofia Njikoka Anaocha Federal Constituency | 4 July 2023 |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ YAKUB, ABDULRASHEED (2023-03-07). "INEC releases full list of elected lawmakers for Nigeria's 10th Assembly". Peoples Gazette (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-07-05.
- ↑ Shibayan, Dyepkazah (2023-03-07). "AT A GLANCE: Lawmakers elected into 10th national assembly". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-07-05.
- ↑ "Abbas emerges as 10th House of Reps Speaker". Vanguard Newspaper.
- ↑ Mojeed, Abdulkareem (2023-06-13). "Benjamin Kalu emerges Deputy Speaker House of Reps". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-07-05.
- ↑ 5.0 5.1 Majeed, Bakare (2023-07-04). "Ihonvbere, Chinda, others emerge as Reps principal officers". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-07-05.
- ↑ "10th House of Rep: Hon. Halims Of Ankpa Federal Constituency Emerge Deputy Majority Leader". Freshangle News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-07-04. Retrieved 2023-07-05.
- ↑ Nliam, Amaka (2023-06-16). "10th House of Reps: Chinda Emerges as Minority Leader". Voice of Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-07-05.
- ↑ Nliam, Amaka (2023-06-11). "10th Assembly: Gombe Rep Emerges PDP Consensus Candidate for Minority Whip". Voice of Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-07-05.