Afghanístàn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Afuganísítáànù)
Jump to navigation Jump to search
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn
Islamic Republic of Afghanistan
 • د افغانستان اسلامي جمهوریت (Pashto)
 • Da Afġānistān Islāmī Jumhoryat
 • جمهوری اسلامی افغانستان (Dari)
 • Jomhūrī-ye Eslāmī-ye Afġānestān
Àsìá
Mottoلا إله إلا الله، محمد رسول الله
"Lā ʾilāha ʾillā llāh, Muhammadun rasūlu llāh"
"There is no God but Allah; Muhammad is the messenger of Allah. (Shahada)
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèMillī Surūd
ملي سرود
("National Anthem")

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Kabul
Official languages Dari 27 million (77%) (L1 + L2), Pashto 16.8 million (48%)[2]
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn 
Orúkọ aráàlú Ará Afghanístàn
Ìjọba Unitary presidential Islamic republic
 -  President Ashraf Ghani
 -  1st Vice President Amrullah Saleh
 -  2nd Vice President Sarwar Danish
Aṣòfin National Assembly
 -  Ilé Aṣòfin Àgbà House of Elders
 -  Ilé Aṣòfin Kéreré House of the People
Formation
 -  Hotak Empire 21 April 1709 
 -  Durrani Empire October 1747 
 -  Emirate 1823 
 -  Recognized 19 August 1919 
 -  Kingdom 9 June 1926 
 -  Republic 17 July 1973 
 -  Current constitution 26 January 2004 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 652,230[8] km2 (40th)
251,830 sq mi 
 -  Omi (%) negligible
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2019 32,225,560[9] (43rd)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 46/km2 (174th)
119/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2018
 -  Iye lápapọ̀ $72.911 billion[10] (96th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $2,024[10] (169th)
GIO (onípípè) Ìdíye 2018
 -  Àpapọ̀ iye $21.657 billion[10] (111st)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $601[10] (177th)
Gini (2008) 27.8 (1st)
HDI (2018) 0.496 (170th)
Owóníná Afghani (Afs) (AFN)
Àkókò ilẹ̀àmùrè D† (UTC+4:30 Solar Calendar)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .af افغانستان.
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +93

Afghanístàn ( /æfˈɡænstæn,_æfˈɡɑːnstɑːn/; Pashto/Dari: افغانستان, Pashto: Afġānistān [avɣɒnisˈtɒn, ab-],[lower-alpha 1] Dari: Afġānestān Àdàkọ:IPA-fa), àlòṣiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn, ni is a orílẹ̀-èdè onílẹ̀bodèGúúsù àti Àrin Ásíà. Afghanístàn ní bodè mọ́ Pakistan ní ìlà-òrùn àti ní gúúsù;[lower-alpha 2] mọ́ Iran ní ìwọ̀-òrùn; mọ́ Turkmenistan, Uzbekistan, àti Tajikistan ní àríwá; àti mọ́ Ṣáínà ní àríwá-ìlàòrùn. Gbogbo ilẹ̀ ibẹ̀ fẹ̀ tó 652,000 square kilometers (252,000 sq mi), orílẹ̀-èdè olókè ní tó ní ilẹ̀ pẹpẹ ní apá àríwá àti gúúsù-ilàòrùn. Kabul ni olúìlú àti ilú tótóbijùlọ níbẹ̀. Iye aráàlú ibẹ̀ fẹ́ ẹ̀ pọ̀ tó 32 mílíọ́nù, tí wọ́n jẹ́ ẹ̀yà àwọn Pashtun, Tajik, Hazara àti Uzbek.

Nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwọn ènìyàn tí wọ́n sọ pé ó wà ní ìlú yìí lé díẹ̀ ní mílíònù mọ́kànlélógún (21,017.000). Èdè tí wọ́n ń sọ ní ìlú yìí tó àádọ́ta ṣùgbọ́n ìlàjì nínú àwọn tí ó wà ní ìlú náà ni ó ń sọ páṣítọ̀ (Pashto) tí òun àti Dárì jọ jẹ èdè ìjọba (official language). Dárì (Dari) yìí nì orúkọ tí wọ́n ń pe Persian (Pásíà) ní Afuganísítàànù. Dárí yìí ṣe pàtàkì gan-an ni gẹ́gẹ́ bí èdè tí ìjọba ń lò (lingua franca). Fún ti òwò tí ó jẹ mọ gbogbo àgbáyé, èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ń gbilẹ̀ sí i. Àwọn èdè mìíràn tí wọ́n ń sọ ní ìlú yìí ni Tadzhik, Uzbek, Turkmen, baluchi, Brachic àti pashayi


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named AO
 2. "South Asia :: Afghanistan – the World Factbook – Central Intelligence Agency". 
 3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named LoC-pdf
 4. Dictionary.com. The American Heritage Dictionary of the English Language, Fourth Edition. Houghton Mifflin Company, 2004. Reference.com (Retrieved 13 November 2007).
 5. Dictionary.com. WordNet 3.0. Princeton University. Reference.com (Retrieved 13 November 2007). Archived 28 March 2014 at the Wayback Machine.
 6. "Constitution of Afghanistan". 2004. Archived from the original on 20 September 2016. Retrieved 16 February 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 7. Afghan | meaning in the Cambridge English Dictionary. the Cambridge English Dictionary. ISBN 9781107660151. https://dictionary.cambridge.org/dictionary/english/afghan. 
 8. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Factbook
 9. "Afghan Population Estimates 1398" (PDF). Central Statistics Organization. 2019. Archived from the original (PDF) on 4 June 2019. Retrieved 4 July 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 10. 10.0 10.1 10.2 10.3 "Afghanistan". International Monetary Fund. Retrieved 14 November 2018. 


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "Note", but no corresponding <references group="Note"/> tag was found
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/> tag was found