Agustín Pedro Justo
Agustín Pedro Justo | |
---|---|
President of Argentina | |
In office 20 February 1932 – 19 February 1938 | |
Vice President | Julio Argentino Pascual Roca |
Asíwájú | José Félix Uriburu |
Arọ́pò | Roberto M. Ortiz |
Minister of War | |
In office 12 October 1922 – 12 October 1928 | |
Ààrẹ | Marcelo Torcuato de Alvear |
Asíwájú | Julio Moreno |
Arọ́pò | Luis Dellepiane |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Concepción del Uruguay, Entre Ríos | 26 Oṣù Kejì 1876
Aláìsí | 11 January 1943 Buenos Aires, Argentina | (ọmọ ọdún 66)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Argentine |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | UCR-A |
Other political affiliations | Concordancia |
Profession | Military |
Signature | |
Military service | |
Branch/service | Argentine Army |
Years of service | 1892–1931 |
Rank | Major General |
Agustín Pedro Justo Rolón tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1976 jẹ́ Ààrẹ apàṣẹwàá orílẹ̀-èdè Argentina tẹ́lẹ̀ láàrin ọdún 1932 sí 1938, ó sì tún jẹ́ olóṣèlú pẹ́lú ni.[1] Justo kòpa nínú ìdìtẹ̀-gbàjọba ti ọdún 1930, lẹ́yìn èyí ni ó di Ààrẹ pẹ́lú ìdìbò èrú. Ó jẹ Ààrẹ láàrín ọdún 1930 sí ọdún 1943. Òun ni ó da country's central bank sílẹ̀ tí ó sì da gbígba owó-orí sílẹ̀ pẹ̀lú.[2]
Ó yan olórí ìjọba Marcelo Torcuato de Alvear, pẹ̀lú ìrírí rẹ̀ lábẹ́ ìjọba alágbádá, ati ipa rẹ̀, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bíi 1931 campaign. Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kọkànlá ọdún 1931, pẹ́lú Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú (Partido Demócrata Nacional), Radical Civic Union (Unión Cívica Radical) (UCR), àti Socialist Independent Party (Partido Socialista Independiente). Wọ́n fi ẹ̀sùn ìṣèrú ìbò tí wọ́n fún lórúkọ patriotic fraud kàn án láàrín ọdún 1931 àti 1943. Lásìkò yí, àwọn olóṣèlú alátakò bíi Yrigoyen tí ó wá láti ẹgbẹ́ ìṣèlú Radical Civil Union. gbénáwojú ìṣèjọba rẹ̀.[3] Iṣẹ́ takuntakun tí Mínísítà fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèrè rẹ̀ Carlos Saavedra Lamas, ni ó jẹ́ àṣeyọrí pàtàkì fún ìṣèjọba rẹ̀, amọ̀ wọ́n fi ẹ̀sùn àjẹbánu rẹpẹtẹ kan ìṣèjọba rẹ̀ pẹ̀lú bí ó ṣe jọ̀wọ́ ètò ọrọ̀ Ajé orílẹ̀-èdè sọ́wọ́ àwọn British pàá pàá jùlọ ní ìgbà kejì rẹ̀ ọ̀gbẹ́ni Julio A. Roca Jr. ṣe tọwọ́ bọ̀wé àdéhùn Roca-Runciman Treaty.
Nípa rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1976 ní ìlú Concepción del Uruguay, ní ẹkùn Entre Ríos Province. Bàbá rẹ̀ Agustín,ti fìgbà kan rí jẹ́ Gómìnà fún ẹkùn Corrientes Province, kò pẹ́ púpọ̀ tí ó sì fi di ìgbà kejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè náà. Ó kópa nínú ìṣèlú orílẹ̀-èdè rẹ̀ títí ó fi bí ọmọ rẹ̀ Justo tí òun àti ẹbí rẹ̀ tó kó lọ sí Buenos Aires. Iya rẹ̀ Otilia Rolón, ní ó wá láti inú ẹbí Corrientes. Nígbà tí Justo wà ní ọmọ ọdún mọ́kànlá, ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Colegio Militar de la Nación (National Military College). Ó sì dra pọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ tókù nínú Revolución del Parque, níbi tí wọ́n ti gba àwọn ohun ija fún àwọn ajìjangbara, wọ́n mú wọn amọ́ wọ́n da wọn sílẹ̀ẹ̀ láìpẹ́. Ó jáde nílé ẹ̀kọ́ yí pẹ̀lú ipò ensign.[4]
Awon itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Agustín P. Justo, Luciano de Privitellio, 1997, ISBN 9789505572397
- ↑ La moneda y su historia, Rioja, Leonci, ISBN 9789870271017[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Hipólito Yrigoyen, Instituto Yrigoyeneano, 1978
- ↑ Historia argentina: 1830-1992, Torcuato S. Di Tella, 1993, ISBN 9789501662467
- Pages with script errors
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from October 2023
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- Presidents of Argentina
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1876
- Àwọn ọjọ́aláìsí ní 1943
- People from Uruguay Department
- Argentine people of Italian descent
- Argentine generals
- People of the Infamous Decade
- University of Buenos Aires alumni
- Colegio Militar de la Nación alumni
- Burials at La Recoleta Cemetery
- 20th-century Argentine politicians
- Patrician families of Buenos Aires
- Àwọn ará Argẹntínà