Jump to content

Chief Daddy 2: Going for Broke (Fíìmù Nàìjíríà)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Chief Daddy 2: Going for Broke jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó jáde ní ọdún 2022. Ó jẹ́ ìtẹ̀síwájú fíìmù Chief Daddy. Bode Asiyanbi, Hiedi Uys, Salah Sabiti, Mo Abudu, ni ó ṣe àkọsílẹ̀ fíìmù náà, Ebonylife Tv ló sì ṣe àgbéjáde rẹ̀, tí Niyi Akinmolayanèyí tó jẹ́ olùdarí àgbà tó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ sì darí.[1][2] Lára àwọn akópa fíìmù náà ni ògbóǹtarìgì àwọn òṣèré bí i: Shaffy Bello, Funke Akindele-Bello, Joke Silva, Rahama Sadau, Mawuli Gavor, Beverly Naya, Falz àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ [3][4][5] Àmọ́ ṣáá, ìgbà tí fíìmù náà jáde, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ní àríwísí sí fíìmù náà, pé ìgbìyànjú wọn nínú fíìmù yẹn ò tó nǹkan tí wọ́n ń retí.[6][7][8] Nítorí náà, olùdarí àgbà ti EbonyLife, ìyẹn MO Abudu, tọrọ àforíjì lọ́wọ́ àwọn òǹwo-fíìmù náà, ó sì ṣe àfikún pé wọ́n máà ṣàtúnṣe.[9]

Shaffy Bello, Funke Akindele-Bello, Joke Silva, Kate Henshaw-Nuttal, Rahama Sadau, Mawuli Gavor, Beverly Naya, Falz, Linda Ejiofor Beverly Osu, Broda Shaggi, Uzor Arukwe, Zainab Balogun, Dakore Egbuson-Akanga, Rachel Oniga ati Nedu Wazobia[10] [11]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Adeniyi, Taiwo (2022-01-15). "MOVIE REVIEW: It is a wrap on Chief Daddy 2". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-01-17. Retrieved 2022-07-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Mo Abudu Appeases Viewers Following Chief Daddy 2 Criticism". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-14. Archived from the original on 2022-05-03. Retrieved 2022-07-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Watch Chief Daddy 2 - Going for Broke | Netflix". www.netflix.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-06-20. Retrieved 2022-07-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :03
  5. "Negative reactions trail ‘Chief Daddy’ sequel - P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-01-03. Retrieved 2022-07-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "Criticism trails EbonyLife's Chief Daddy 2". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-03. Archived from the original on 2022-07-17. Retrieved 2022-07-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Mo Abudu responds to negative feedback on latest film "Chief Daddy 2"". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-14. Archived from the original on 2022-02-15. Retrieved 2022-07-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. Kaduna, George (2022-04-13). "Actual reasons 'Chief Daddy 2' flopped - Director". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-07-05. Retrieved 2022-07-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. Augoye, Jayne (2022-01-14). "Mo Abudu finally responds to critics of 'Chief Daddy 2'". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-07-17. Retrieved 2022-07-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  10. Empty citation (help) 
  11. Empty citation (help)