Hailliote Sumney
Hailliote Sumney | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Hailliote Sumney |
Orílẹ̀-èdè | Ghanaian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of California |
Iṣẹ́ | Actress, brand influencer, TV personality |
Hailliote Sumney tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí Hallie Sumney jẹ́ òṣèrékùnrin ilẹ̀ Ghana, aṣojú ilé-iṣẹ́ kan, gbajúmọ̀ ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán àti onínúure. Ó ti ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò fún àwọn gbajúgbajà ènìyàn bí i Boris Kodjoe, Michael Blackson, Becca, Stonebwoy àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Òun ni aṣojú lóbìnrin fún ilé-ìtàjà kan ní ìlú Londonpẹ̀lú Stonebwoy, tó jẹ́ aṣojú lọ́kùnrin fún ilé-ìtajà náà. Ní ọdún 2019, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí i olóòtú ayẹyẹ ìgbàmì-ẹ̀yẹ 4Syte TV's BET.[1][2][3][4]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Sumney sí ìlú Canada, sínú ìdílé Dr. Kodjoe Sumney àti Dr. Akosuah Sumney, àmọ́ wọ́n kó lọ sí United States nígbà tí ó pé ọmọdún méjì.[5] Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa nursing ní Summit career college, ní California ó sì tẹ̀síwájú láti lọ sí University of California, Riverside ní California, láti gboyè ẹ̀kọ́ mìíràn.[6][7]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó fi iṣẹ́ nọ́ọ̀sì sílè, níbi tí ó ti ń ṣiṣẹ́ ní Riverside Hospital ní United States láti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ fíìmù ṣíṣe ní ilẹ̀ Africa.[8] Ó ṣe ìfarahàn àkọ́kọ́ nínú fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Heels and Sneakers èyí tí Yvonne Nelson ṣàgbéjáde. Bẹ́ẹ̀ sì ni ó fi farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù àgbéléwò bí i Lagos Fake Life, èyí tí Mike Ezuruonye ṣàgbéjáde. Iṣẹ́ mìíràn tí ó farahàn nínú ni "To kill a ghost" àti Eden , bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n ti gbé àwọn fíìmù rẹ̀ mìíràn sí orí Netflix, Amazon Prime àti IROKOtv. Yàtọ̀ sí èyí, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olóòtú ètò 4Syte TV.
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Fíìmù | Ipa | Ọ̀rọ̀ |
---|---|---|---|
2016 | Heels and Sneakers (series) | produced by Yvonne Nelson, Efia Odo | |
A way back home | with Alex Ekubo, IK Ogbonna | ||
2017 | Kintampo | produced by Chris Attoh, also starring Adjetey Annan, Sika Osei and Deyemi Okanlawon | |
Desperate Survivors | produced by Samuel De Graft featuring Kalsonme Sinare and Benedicta Gafah | ||
2018 | Lagos Real Fake Life | Mirabel | Produced by Mike Ezeronye also starring Annie Idibia, Emmanuella (Mark Angel Comedy) |
Track of My Fears | produced by Ama K.Aberese and starring Rama Brew, Marie Humbert, and Blossom Chukwujekwu | ||
2018 | Shattered (short film) | produced by Haillie Sumney featuring Ian Wordi and directed by Chris Gyan | |
2019 | Twisted | starring Fela Makafui, James Gardener | |
2019 | 2 Days after Friday | produced by Venus Films, starring Jackie Appiah, Mofe Duncan, John Domelo | |
2019 | Smoke Screen | Maeve Grant | directed by Vickie Wills-Doku, starring Rama Brew, Blossom Chukwujekwu, Marie Humbert-Droz, David Dontoh |
2020 | Eden | directed by Harry Bentil, starring Solomon Fixon-Owoo, Kobby Acheampong, Godwin Namboh | |
A Woman's Scorn | directed by Maxwell Akwesi, starring James Gardener, Anthony Woode, Ekow Blankson and featuring Fela Makafui | ||
Trapped | directed by Eazzy Ologe starring IK Ogbonna | ||
Soft Work | Nonye | directed by Darasen Richards, starring Shaffy Bello, Frank Donga, Mofe Duncan, Alexx Ekubo, IK Ogbonna | |
2021 | Ghana Jollof | directed by Uzor Arukwe, Funnybone, Akah Nnani, Joselyn Dunmas | |
2022 | Co Habits | directed by Peter Sedufa, starring Fiifi Coleman, Caroline Sampson, Jeffery Nortey, Jackie Ankrah | |
2023 | To Kill a Ghost | Sharon | Directed by Mike Ezuruonye, starring Pat Akpabio, Lovelin Akpan, Treasure Bassey |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ghanaian TV personality to host 2019 BET Awards red carpet". www.myjoyonline.com. Retrieved 2019-10-25.
- ↑ Quartey, Daniel (2019-06-25). "5 photos of Ghanaian TV star said to have hosted 2019 BET Awards red carpet". Yen.com.gh - Ghana news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-25.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Haillie, host of 2019 BET Awards red carpet". www.graphic.com.gh. Retrieved 2019-10-25.
- ↑ Online, Peace FM. "Ghanaian TV Personality, Haillie Sumney Never Hosted The 2019 BET Awards Red Carpet – What Happened?". www.peacefmonline.com. Retrieved 2019-10-25.
- ↑ "HAILLIE SUMNEY BECOMES THE FIRST GHANAIAN TV PERSONALITY TO HOST BET RED CARPET.". BeachFM (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 21 June 2019. Retrieved 2019-10-25.
- ↑ Issahaku, Zeinat Erebong (2019-06-21). "Ghanaian TV personality, Hailliote Sumney, to host 2019 BET Awards red carpet". AmeyawDebrah.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-25.
- ↑ "Ghanaian TV personality to host 2019 BET Awards red carpet". www.ghanaweb.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-10-26. Retrieved 2019-10-26. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "African celebrities are prone to STDs and HIV – Actress, Haillie Sumney says". www.ghanaweb.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-25.