Jumoke Verissimo
Jumoke Verissimo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kejìlá 1979 Lagos, Lagos Island, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | University of Alberta (PhD)University of Ibadan (MA), Lagos State University (BA) |
Iṣẹ́ | Poet. Novelist. Academic. |
Gbajúmọ̀ fún | Writing A Small Silence, I am memory |
Jumoke Verissimo (tí wọ́n bí ní 26 December 1979 ní Èkó) jẹ́ òǹkọ̀wé ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akéwì, òǹkọ̀wé ìtàn àròsọ, òǹkọ̀wé ìtàn ọmọdé àti alárìíwísí.
Ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Jumoke sí Èkó . Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè master's ní African studies (performance) láti University of Ibadan àti bachelor's degree nínú ẹ̀kọ́ English literature láti Lagos State University. Ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi olóòtú, olóòtú àgbà, copywriter àti akọ̀ròyìn fún àwọn ìwé-ìròyìn bíi The Guardian àti NEXT. Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, Jumoke ń gbé ní Canada pẹ̀lú ọmọbìnrin rẹ̀, ó sì ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi aṣèránwọ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní Toronto Metropolitan University .[1]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Peoples Daily[2] ṣe àpèjúwe iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi "èyí tó dúró fún ẹ̀dùn ọkàn àti ìmọ̀lára, tó sí jẹ́ àkéjáde ẹkún àwùjọ." The Punch náà ṣe àpèjúwe rẹ̀ bíi, "ọ̀kan lára àwọn tó máa yí ojú ìwò lítíréṣọ̀ Nàìjíríà padà", lẹ́yìn ìwé rẹ̀ àkọ́kọ́, èyí tí àwọn ènìyàn gbà tọwọ́ tẹsẹ̀ káàkiri orílẹ̀-èdè. Wọ́n ṣàfihàn iṣẹ́ rẹ̀ ní Migrations (Afro-Italian), Wole Soyinka ed., Voldposten 2010 (Norway), Livre d'or de Struga (Poetes du monde, sous le patronage de l'UNESCO) àti àwọn àkọsílẹ̀ loríṣiríṣi. Díẹ̀ lára àwọn ewì rẹ̀ ni wọ́n ti tú sí èdè Italian, Norwegian, French, Japanese, Chinese, àti Macedonian.[citation needed] Ìwé ìtàn àròsọ Veissimo ti ọdún 2019, A Small Silence (Cassava Republic) ni wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bíi èyí tó jáwé olúborí ti ẹ̀bùn Aidoo-Snyder fún iṣẹ́ tó dára jù lọ.[3]
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- 2009: Carlos Idzia Ahmad Prize, First Prize for a first book of Poetry.[4]Àdàkọ:Unreliable source?
- 2009: Anthony Agbo Prize for Poetry, Second Prize for a first book of Poetry[4]
- 2012: Recipient, Chinua Achebe Centre Fellowship, 2012[citation needed]
- 2020: Ondaatje Prize, shortlisted for A Small Silence[5]
- 2020: Winner of the Aidoo-Snyder Book Prize for best original creative work.[6]
Ìtàn àròsọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- A Small Silence Cassava Republic, London, 2019 ISBN No: 9781911115793
Ewì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- I Am Memory DADA Books, Lagos, 2008 ISBN No: 978-978-088-065-1
- The Birth of Illusion FULLPOINT, Nigeria, 2015 ISBN No: 978-978-946-697-9
Iṣẹ́ àtúnṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Co-editor,Sọ̀rọ̀sóke: An #Endsars Anthology (Noirledge, Nigeria, 2022 ISBN No: 9789785874693
Ìwé àwọn ọmọdé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Grandma and the Moon's Hidden Secret, 2022 Cassava Republic, London, 2019 ISBN No: 9781913175351
- Àdùkẹ́, Ìyá Àgbà Àti Àṣírí Òṣùpá (Yoruba), 2022 Cassava Republic, London, 2019 ISBN No: 9781913175382
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Jumoke Verissimo on ResearchGate". ResearchGate. Retrieved 17 April 2019.
- ↑ "Interview on People's Daily Newspaper, Nigeria". Archived from the original on 8 July 2013. Retrieved 7 July 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ News, BrittlePaper (25 November 2020). "Jumoke Verissimo Wins the Aidoo-Snyder Prize for Best Creative Work". BrittlePaper. https://brittlepaper.com/2020/11/jumoke-verissimo-wins-the-aidoo-snyder-prize-for-best-creative-work/. Retrieved 2 May 2021.
- ↑ 4.0 4.1 "Obiwu: AWF 2009 LITERARY CONTEST SHORT LIST". Archived from the original on 20 July 2019. Retrieved 2 November 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Shortlist for £10,000 Ondaatje Prize announced". Books+Publishing (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-21. Retrieved 2020-05-07.
- ↑ "Aidoo-Snyder Book Prize". 2020-10-21. Retrieved 2021-05-02.