Jump to content

Olatoye Tempitope Sugar

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Olatoye Temitope Sugar
Member of the House of Representatives of Nigeria for Lagelu/Akinyele
In office
9 June 2015 – 9 March 2019
AsíwájúMuritala Kayode Adewale
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1973
Aláìsí9 March 2019(2019-03-09) (ọmọ ọdún 45–46)[1]
Ibadan, Oyo State, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAction Democratic Party
Alma mater
Occupation
  • Businessman
  • politician
Websitehttp://olatoyetemitopesugar.com

Olatoye Temitope Sugar (1973 – 9 March 2019) je ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asoju-sofin àpapọ̀ o ti onsójú àgbègbè Lagelu / Akinyẹle ati alágaa,ìgbìmọ̀ Ilelórí Ìdàgbàsókè Ilu ati Eto Ekunfún orílè-èdè Nàìjíríà [2] Bakan naa lo tun je oludije fun ipo Senato fun Oyo central llábé ẹgbẹ òṣèlú Action Democratic Party nínú idibo ọdún 2019. [3] [4]

Igbesi aye ibẹrẹ ati ikẹkọ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Suga wa lati ọgbà Efungade-Onigbodogi, Alafara Oje ni ìjọba ìbílẹ̀ Ibadan North East ni Ìpínlè Oyo nígbà ti awon abúlé bàbà re ni Onigbodogi ati Alape méjéèjì nijoba ibile Lagelu ni ipinle Oyo. Temitope odo ni eko alakọbẹrẹ re ni St Michael Primary School, Yemetu ati IMG Primary School, Beyerunka, Alafara Oje méjèèjì ni Ibadan . Lẹ́yìn naa lo lo si ileewe girama Ikolaba, St Luke’s College, Molete ati Alugbo Comprehensive High School, Egbeda, gbogbo won n'ilu Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Oyo fun eko gírámà. [5] Lẹhinna o lọ si Federal College of Education Abeokuta, Ipinle Ogun, nibiti o ti gbà iwe-ẹri ti orilẹ-ede rẹ. Lẹyin naa lo tun lo si yunifasiti ti Ibadan níbi ti o ti gbà oye, bẹẹ lo tun gba oye. [6]