Oníṣe:Demmy/Sandbox/tests
Demmy@yo Wikipedia
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]I request an extension/permanence to my temporary sysop access. It lapse tomorrow.
- Language Code: yo
- List of local sysops: w:yo:Special:Listadmins
- List of local bureaucrats: w:yo:Special:Listusers/bureaucrat
- Local Request Link: w:yo:Wikipedia:Requests_for_adminship/demmy_2
- Local User Page: w:yo:User:Demmy
- Preferred duration and reason: Another month or preferably longer/permanent. The other 2 permanent admins are inactive for all intent and purpose. So is the community.
Thank you. Demmy 09:24, 8 March 2008 (UTC)
- Mo ti ṣeé, extended for three more months. Expires on June 9, 2008. --FiLiP ¤ 10:40, 9 March 2008 (UTC)
Olobiripo
alágbẹ̀dẹ=blacksmith
àgbẹ̀dẹ = metal
idẹ = iron
sweat = aagun
water vapor = aagun omi
adú = carbon, carbon dioxide = adu oloksigen meji
atmospheric pressure = fífún efuufuroboto
atmosphere = efuufuroboto =ojuefuufu
exosphere = oderoboto
ionosphere = ioniroboto
thermosphere = olooruroboto
mesosphere = aarinroboto
stratosphere =
troposphere =
Ìrò = theory
graph = ìlà àjúwe
equator = abudogba
làákaye = intelligence, onilaakaye = intelligent
amúnáwa = electricity, electric current - iwo imunawa, electric motor = moto imunawa
asa = hawk
eye ìdì = eagle
frequency = onigbagbogbo
ìse = formal
ìtẹ̀ka = fingerprint
àìrísese = unemployment
fiction = ìtan kàyéfì
hydro-electric = atanna-afomise
hybrid: n; (A mule is a hybrid because its parents are a house and a donkey.) àdàmòdì Àdàmòdì nì ìbákasíe torí pé esin àti ràkunmi ni wón bí í.
tabili irinse = toolbar
ìgòayíribiti = cylinder
owóníná = currency
ìgbònwó = cubic
ìjòngbòn; wàhàlà; rúkèrúdò = crisis
àsèsèyo osù = crescent
Àwìn = credit
edé = crayfish
bàbà = copper
Ẹgbẹ́ aláàánú = charity
Ọrúndún = century
ìràwò onírù = comet
ìdí abájò = clue
wàràkàsí = cheese
Se àmì sí gbogbo àtúnse gẹ́gẹ́ bi kékeré lát'ìbẹ̀rẹ̀. Show preview on first edit S'àfihàn àgbéwò fún àtúnse àkọ́kọ́
Disable page caching D'ènà fífi ojúewé pamọ́
Add pages I create to my watchlist S'àfikún ojúewé tí mo dá mọ́ ìmójútó mi
Add pages I edit to my watchlist S'àfikún ojúewé tí mo s'àtúnse mọ́ ìmójútó mi
Add pages I delete to my watchlist S'àfikún ojúewé tí mo parẹ́ mọ́ ìmójútó mi
Add pages I move to my watchlist S'àfikún ojúewé tí mo kó kúrò mọ́ ìmójútó mi
Ọjọ́àìkú
Ọjọ́ajé
Ọjọ́ìsẹ́gun
Ọjọ́rú
Ọjọ́bọ̀
Ọjọ́ẹtì
Ọjọ́àbámẹ́ta
Nípa Wá rí
Àsìse
E-mail me when a page I'm watching is changed Fi e-mail ránsẹ́ sími tí ojúewé tí mò ún mójútó bá yípadà
E-mail me when my user talk page is changed Fi e-mail ránsẹ́ sími tí ojúewé ẹnitínse mi bá yípadà
E-mail me also for minor edits of pages Fi e-mail ránsẹ́ sími bákannà fún àtúnse kékékèé sí ojúewé
Show the number of watching users S'àfihàn iye àwọn ẹnitínse tí wọn ún mójútó Ìfọ̀rọ̀wérọ̀
wọ́pọ̀ = common ìwọ́pọ̀ = common dìjọ, ìdìjọ = condense, condensation ooru = steam igbona = heat, igbegbonu gbona = hot
nomba déédé = constant (math)
àkóónú, àkósínú = content
bóòlu alápèrè = basketball
pupa fúéfúé = blonde
Ẹfọ̀n = buffalo
Ìdè = button
onídẹ = brass, idẹ
pọn = brew, distill, (pọn ọtí)
compression, n. ìfúnpò
concave, adj. jìn kòtò (He brought some concave mirrors.) Ó mú àwọn dígí tí jìn kòtò wá
ìpéjọ congress
conjecture, n ìròtẹ́lẹ̀, ìsọtẹ́lè
conical, adj. bí adodo, bí òǹgo
àrọ = funnel ====cone, conical
consecutive, adj. lẹ́sẹlẹ́sẹ, lẹ́sẹẹsẹ, ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé
consecutively, adv. léraléra
Ẹlẹgbẹ́ = contemporary (Fágùnwà was contemporary with Ọdúnjọ.) Ẹlẹgbẹ́ ni fágùnwà àti Ọdúnjo
adverb (n); ọ̀rọ̀ àpọ́nlé ===She sang a song beautifully today. (Ó kọrin dáradára ló nìí
adjective (n)ọ̀rọ̀ Àpèjúwe: She sang a beautiful song. (Ó kọ orin aládùn).
òfurufú = sky
Beam: v. ‘ràn’ The sun beamed through the cloud; Oòrùn ràn gba inú kùrukùru kọjá
yìnyín = ice wàrà oníyìnyín = ice cream
idiom: n; (“I’ve got cold feet”doesn’t only means that my feet fell cold, it means that I am frightened- it is an idiom.) àkànlò èdè “Ese mí dì lútù”kò túmò sí èsè mi n tutu nìkan, ó túmò sí pè èrù bà mí- àkànlò èdè ní.
immigrant = àtìpò
ibàa pónjú = yellow fever
infant = omo owó
pronoun, n. ọ̀rọ̀-arọ́pò-orúko
prose, n. ọ̀rọ̀ geere
purple, adj. ẹlẹ́sẹ̀ àlùkò, àwọ̀ àlùkò. (That is a purple flower.) Àdòdó aláwọ̀ àlùkò nìyẹn.
address - ipoibugbe
jomijòkè = amphibian
ìjo aguda = anglican church
Apéjopò = assambly
Associate Professor = Ojogbon ẹlẹgbẹ́
agbalúgbú = wave
Baptist=onítẹ̀bọmi
èso àjàrà = grape
- ... Kalulu (àwòran), ọmọdékùnrin Africa tó kú ní 1877, jẹ́ yíyàláwòrán ní Madame Tussauds, à ti pé ó kó pa nínú ìsìnkú Dk. Livingstone ní Lọ́ndọ̀n?
- ... Árámáìkì jẹ́ èdè ayéijọ́un tó ní ìbátan gbágbágbá mọ́ èdè Hébérù?
- ... Marie Curie gba Ẹ̀bùn Nobel ní ẹ̀mẹjì; ní 1903 ó gba Ẹ̀bùn Nobel nínú Físíksì àti ní 1911 ó gba Ẹ̀bùn Nobel nínú Kẹ́místrì?
- ... Brazzaville ni olúìlú àti ìlú atóbijùlọ ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò?