People's Democratic Party: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit
Ìlà 13: Ìlà 13:


'''People's Democratic Party|[[PDP]]'''
'''People's Democratic Party|[[PDP]]'''
jẹ́ [[ẹgbẹ́ òṣèlú]] alátakò ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. Wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1998. Àwọn ni ọmọ ẹgbẹ́ wọn ṣe ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà títí di ọdún 2015 kí ẹgbẹ́ òṣèlú [[All Progressives Congress]] tó gbàjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]] mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; [[Olúṣẹ̀gún Ọbásanjọ́]], [[Musa Yar'Adua]] àti [[Goodluck Jonathan]] ni ẹgbẹ́ yìí jẹ kí ẹgbẹ́ APC tó dà wọ́n lágbo nù lọ́dún 2015, tí Ààrẹ [[Muhammadu Buhari]] tí ẹgbẹ́ [[APC]] fi wọlé gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.
jẹ́ [[ẹgbẹ́ òṣèlú]] alátakò ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. Wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1998. Àwọn ni ọmọ ẹgbẹ́ wọn ṣe ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà títí di ọdún 2015 kí ẹgbẹ́ òṣèlú [[All Progressives Congress]] tó gbàjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]] mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; [[Olúṣẹ̀gún Ọbásanjọ́]], [[Umaru Musa Yar'Adua]] àti [[Goodluck Jonathan]] ni ẹgbẹ́ yìí jẹ kí ẹgbẹ́ APC tó dà wọ́n lágbo nù lọ́dún 2015, tí Ààrẹ [[Muhammadu Buhari]] tí ẹgbẹ́ [[APC]] fi wọlé gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.


{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}

Àtúnyẹ̀wò ní 17:18, 15 Oṣù Kejìlá 2019

People's Democratic Party
ChairmanUche Secondus
Akọ̀wé ÀgbàAbubakar Kawu Baraje
Ìdásílẹ̀1998 (1998)
IbùjúkòóWadata Plaza, Michael Okpara Way, Wuse, Abuja
Ọ̀rọ̀àbáModerate
Official coloursGreen, white, red
Ibiìtakùn
PDP, INEC
PDP, Yar' adua 2007
Ìṣèlú ilẹ̀ Nigeria

People's Democratic Party|PDP jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1998. Àwọn ni ọmọ ẹgbẹ́ wọn ṣe ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà títí di ọdún 2015 kí ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress tó gbàjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; Olúṣẹ̀gún Ọbásanjọ́, Umaru Musa Yar'Adua àti Goodluck Jonathan ni ẹgbẹ́ yìí jẹ kí ẹgbẹ́ APC tó dà wọ́n lágbo nù lọ́dún 2015, tí Ààrẹ Muhammadu Buhari tí ẹgbẹ́ APC fi wọlé gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.



Itokasi