Peanut soup
Ọbẹ̀ Peanut tàbí ọbẹ̀ ẹ̀pà jẹ́ ọbẹ̀ soup tí a ṣe láti ara ẹ̀pà peanuts, pẹ̀lú àwọn ohun èlò mìíràn. Ó jẹ́ ọ̀kan nínu àwọn oúnjẹ ilẹ̀ Africa ṣùgbọ́n tí wọ́n tún ń jẹ ẹ́ ní East Asia (Taiwan), the United States (ní Virginia nìkan) [1][2] àti àwọn agbègbè mìíràn káàkiri àgbáyé. Ó tún wọ́pọ̀ ní àwọn agbègbè kan, bí àríwá Argentina's ,[3][4] Bolivia[5] àti Peru,[6] níbi tí wọ́n ti lè jẹ́ nígbà mìíràn pẹ̀lú ẹran àti pásítà tàbí díndín. Ní Ghana wọ́n sábàá máa ń jẹ ẹ́ pẹ̀lú fufu, omo tuo àti banku ó sì máa ń ta gidi gan-an.[7] Ọbẹ̀ ẹ̀pà tún jẹ́ ọbẹ̀ ìbílẹ̀ ti àwọn ènìyàn Edo ní Nàìjíríà wọ́n sì sábàá máa ń jẹ ẹ́ pẹ̀lú iyán. [8][9][10] Díẹ̀ nínú àwọn èròjà pàtàkì tí a lò láti fi ṣe é ni ugu, ewé oziza, Piper guineense (hóró uziza) àti Vernonia amygdalina (ewúro).
A máa ń sè é láti ara ẹ̀pà èyí tí a gún kúnná,[11] tí wọ́n sábàá máa ń pè ní ẹbu ẹ̀pà. Nígbà tí a bá sè é, ẹ̀pà náà máa ń jẹ́ àwọ̀ píǹkì. Ọbẹ̀ ẹ̀pà máa ń di jíjẹ pẹ̀lú eba, fufu, banku, kenkey àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[12] Ó jẹ́ oúnjẹ tí ó jẹ́ pé àwọn ọmọ Nàìjíríà, ọmọ Ghana àti àwọn èèyàn mìíràn ní àwọn orílẹ̀-èdè Áfíríkà ń jẹ, gẹ́gẹ́ bí ní Sierra Leone.[13] Ní Ghana, wọ́n moọ̀ ọ́ sí nkatenkwan ní èdè Akan àti "Azidetsi" èdè Ewe.[14][15]
Àwọn àwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]-
Garnished ground nut or peanut soup
-
Peanut soup with fufu and fish
-
Latin American peanut soup
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Cathy (18 November 2012). "A Thanksgiving Recipe: Virginia Peanut Soup". National Peanut Board. Archived from the original on 20 December 2013. Retrieved 19 December 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Collins, Geneva (9 May 2007). "Where Settlers, Slaves and Natives Converged, a Way of Eating Was Born". The Washington Post. https://www.washingtonpost.com/wp-dyn/content/article/2007/05/08/AR2007050800381.html.
- ↑ ""Sopa de mani", el plato favorito de los norteños para festejar el Carnaval" ["Peanut Soup", the northerner's favorite dish to celebrate Carnival.]. www.quepasasalta.com.ar. Retrieved 2020-07-07.
- ↑ "Sopa de maní, la receta ideal para celebrar el jueves de ahijados" [Peanut Soup, the ideal recipe to celebrate Godchild Thursday]. www.todojujuy.com (in Èdè Sípáníìṣì). 14 February 2019. Retrieved 2020-07-07.
- ↑ "Sopa de Maní - Cochabamba Bolivia" [Peanut Soup - Cochabamba Bolivia]. Conoce Cochabamba Bolivia (in Èdè Sípáníìṣì). 2020-04-18. Retrieved 2020-07-07.
- ↑ "Sopa de Mani :: Gastronomía Perú" [Peanut Soup :: Gastronomy Peru]. Gastronomía Perú (in Èdè Sípáníìṣì). Archived from the original on 2020-11-04. Retrieved 2020-07-07.
- ↑ "Ghanaian groundnut soup – recipe". The Guardian. 24 April 2013. https://www.theguardian.com/world/2013/apr/24/ghana-groundnut-peanut-soup.
- ↑ "How to Cook Groundnut Soup". FoodieDame (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-13. Archived from the original on 2022-05-27. Retrieved 2022-05-12.
- ↑ "Groundnut Soup - Omisagwe". Sisi Jemimah (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-09-07. Retrieved 2022-05-12.
- ↑ "How to prepare Cassava Fufu: Akpu". All Nigerian Food Recipes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-01-13. Archived from the original on 2022-06-28. Retrieved 2022-05-12.
- ↑ Saffery, D. (2007). The Ghana Cookery Book. Jeppestown Press. p. 44. ISBN 978-0-9553936-6-2. https://books.google.com/books?id=tSVcQFoIsDIC&pg=PA44.
- ↑ "Recipe of Ultimate Ground nut/peanut soup | Best Recipes". getmenurecipes.web.app. Retrieved 2022-05-12.
- ↑ Anthropologist'S Cookbook. Taylor & Francis. 2012. p. 84. ISBN 978-1-136-16789-8. https://books.google.com/books?id=QxWwqqyz5KUC&pg=PA84.
- ↑ "Make groundnut soup the Edo way". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-04-16. Retrieved 2022-05-12.
- ↑ "Groundnut Soup (Omisagwe)". My Active Kitchen (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-04-08. Retrieved 2022-05-12.