Sagamu
Ìrísí
Sagamu Orisagamu | |||
---|---|---|---|
LGA | |||
Agbègbè Araromi | |||
Coordinates: 6°50′N 3°39′E / 6.833°N 3.650°ECoordinates: 6°50′N 3°39′E / 6.833°N 3.650°E | |||
Country | Nigeria | ||
State | Ogun State | ||
LGA(s) | Sagamu | ||
Government | |||
• Local Government Chairman | Odulate Olashile (APC) | ||
Area | |||
• Total | 614 km2 (237 sq mi) | ||
Population (2006 census) | |||
• Total | 253,412 | ||
Time zone | UTC+1 (WAT) | ||
3-digit postal code prefix | 121[1] | ||
ISO 3166 code | NG.OG.SH | ||
National language | Yorùbá | ||
|
Sagamu tàbí Ishagamu jẹ́ ìlú àti olú-ìlú ìjọba ìbílẹ̀ kan tí ó wà ní apá Gúúsù Ìwọ̀-oòrùn Ìpìnlẹ̀ Ògùn lẹ́gbẹ̀ẹ́ Odò Ibu.[2] Sagamu sì jẹ́ àkójọpọ̀ ìlú mẹ́tàlá ní ìpínlẹ̀ Ògùn lọ́nà odò Ibu àti odò Ewuru, láàrin ipinle Eko àti Ibadan. Wọ́n sì dasílẹ̀ láàrin sẹ́ńtúrì kọkàndínlógún nípa sẹ̀ ọmọ-ẹgbẹ́ Yorùbá,[3]ní apá Guusu Ìwọ̀-oòrun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Àwọn ìlú mẹ́tàlá tí ó wà nínú rẹ̀ ni: Makun, Ofin Sonyindo, Epe, Ibido, Igbepa, Ado, Oko, Ipoji, Batoro, Ijoku, Latawa ati Ijagba.[4][5] Ó sì jẹ́ olú-ìlú Rẹ́mo, ẹni tí ó jẹ́ apàṣẹ ìlú Remo ni a mọ̀ sí Oba Akarigbo. Ìlú Ofin sì ni ààfin Ọba Akarigbo wà.
Àwọn èèyàn tó lààmìlaaka láti ìlú Sagamu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Adebayo Ogunlesi, oníṣòwò
- Anthony Joshua, eléré ìdárayá
- Gbenga Daniel, olóṣèlú
- Babatunde Adewale Ajayi, Ọba ìlú Sagamu
Àwọn àtòjọ àwòrán ìlú Sagamu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]-
Aafin Akarigo palace
-
Akarigbo Palace
-
Methodist church Nigeria
-
Methodist church
-
Sagamu central mosque
-
St. John church
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2012-11-26. Retrieved 2009-10-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Basil Ugorji (2012). From Cultural Justice to Inter-Ethnic Mediation: A Reflection on the Possibility of Ethno-Religious Mediation in Africa. Basil Ugorji. pp. 95–. ISBN 978-1-4327-8835-3. http://books.google.com/books?id=FQjQe-nCkzIC&pg=PA95.
- ↑ "Shagamu | Nigeria". Encyclopedia Britannica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-15.
- ↑ "Shagamu time now. Local current time and time zone in Shagamu / Ogun / Nigeria - Current-Time.World". current-time.world (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2024-07-06. Retrieved 2020-05-25.
- ↑ "Remo Town in Ogun Nigeria Guide". www.nigeriagalleria.com. Retrieved 2020-05-25.