Senegal
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Sẹ̀nẹ̀gàl)
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàl République du Sénégal | |
---|---|
Orin ìyìn: Pincez Tous vos Koras, Frappez les Balafons | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Dakar |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | French |
Lílò regional languages | Wolof, Soninke, Seereer-Siin, Fula, Maninka, Diola,[1] |
Orúkọ aráàlú | Senegalese |
Ìjọba | Semi-presidential republic |
Bassirou Diomaye Faye | |
Ousmane Sonko | |
Independence | |
• from France | 4 April 1960 |
Ìtóbi | |
• Total | 196,723 km2 (75,955 sq mi) (87th) |
• Omi (%) | 2.1 |
Alábùgbé | |
• 2023 estimate | 18,032,473[2] (61nd) |
• Ìdìmọ́ra | 92/km2 (238.3/sq mi) |
GDP (PPP) | 2008 estimate |
• Total | $21.773 billion[3] |
• Per capita | $1,739[3] |
GDP (nominal) | 2008 estimate |
• Total | $13.350 billion[3] |
• Per capita | $1,066[3] |
Gini (1995) | 41.3 medium |
HDI (2007) | ▲0.464 Error: Invalid HDI value · 166th |
Owóníná | CFA franc (XOF) |
Ibi àkókò | UTC |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 221 |
Internet TLD | .sn |
Sẹ̀nẹ̀gàl (Faransé: le Sénégal) tabi Orile-ede Olominira ile Senegal je orile-ede ni Iwoorun Afrika. Senegal ni Okun Atlantiki ni iwoorun, Mauritania ni ariwa, Mali ni ilaorun, ati Guinea ati Guinea-Bissau ni guusu. Sinu die lo ku ko yipo Gambia ka patapata si ariwa, ilaorun ati guusu, ibi to se ku nikan ni eti okun Atlanti Gambia[4] Ifesi ile Senegal fe to 197,000 km², be si ni o ni onibugbe bi 18 milionu.
Dakar ni oluilu re to wa lori Cap-Vert Peninsula ni eti Okun Atlantiki. Bi iye ida kan ninu meta awon ara Senegal ni won n gbe labe ila aini kakiriaye to je US$ 1.25 lojumo.[5]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ « La langue officielle de la République du Sénégal est le Français. Les langues nationales sont le Diola, le Malinké, le Pulaar, le Sérère, le Soninké, le Wolof et toute autre langue nationale qui sera codifiée. » − Extrait du site officiel du gouvernement sénégalais Archived 2006-07-25 at the Wayback Machine.
- ↑ Àdàkọ:Lien web.
- ↑ 3.0 3.1 3.2 3.3 "Senegal". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01.
- ↑ Gambia lies almost entirely within Senegal, surrounded by it on the north, east and south; from its western coast, Gambia's territory follows the Gambia River more than 300 kilometres (186 miles) inland.
- ↑ Human Development Indices, Table 3: Human and income poverty, p. 35. Retrieved on 1 June 2009